1 Chronicles

1 Chronicles 13

Biblica® Open Yoruba Contemporary Bible · tap any highlighted word for context

1 Chronicles 13 — Scripture text (Biblica® Open Yoruba Contemporary Bible)

Dafidi sì gbèrò pẹ̀lú olúkúlùkù àwọn ìjòyè rẹ̀, àwọn aláṣẹ ẹgbẹẹgbẹ̀rún àti àwọn aláṣẹ ọgọ́rùn-ún Dafidi sì wí fún gbogbo àwọn ìjọ ẹli pé, tí ó bá dára lójú yín àti tí ó bá ṣe jẹ́ àṣẹ Olúwa Ọlọ́run wa, jẹ́ kí a ránṣẹ́ sí ọ̀nà jíjìn àti gbígbòòrò sí àwọn arákùnrin wa tókù ní gbogbo àwọn agbègbè ìlú ẹli àti pẹ̀lú àwọn àlùfáà àti àwọn ará àwọn tí ó wà pẹ̀lú wọn nínú ìlú wọn àti pápá oko tútù, láti wá kó ara wọn jọ pọ̀ sọ́dọ̀ wa. Ẹ jẹ́ kí a gbé àpótí ẹ̀rí Olúwa padà sọ́dọ̀ wa, nítorí wí pé àwa kò ṣe ìwádìí nípa rẹ̀ ní àsìkò ìjọba . Gbogbo ìjọ náà sì gbà láti ṣe èyí nítorí ó dàbí wí pé ó tọ lójú gbogbo àwọn ènìyàn. Nígbà náà ni pe gbogbo àwọn ọmọ ẹli jọ, láti ọ̀dọ̀ Ṣihori ní lọ sí ní ọ̀nà à bá wọ , láti gbé àpótí ẹ̀rí Ọlọ́run padà láti -. Dafidi àti gbogbo àwọn ọmọ ẹli pẹ̀lú rẹ̀ lọ sí ti (-) láti gbé àpótí ẹ̀rí Ọlọ́run Olúwa tí a fi orúkọ rẹ̀ pè, tí ó jókòó láàrín kérúbù gòkè wá. Wọ́n sì gbé àpótí ẹ̀rí Ọlọ́run láti ilé lórí kẹ̀kẹ́ tuntun, Ussa àti ń ṣọ́ ọ. Dafidi àti gbogbo àwọn ọmọ ẹli ni wọ́n ṣe àjọyọ̀ pẹ̀lú gbogbo agbára wọn níwájú Ọlọ́run, pẹ̀lú orin àti pẹ̀lú dùùrù, ohun èlò orin olókùn, tambori, kimbali pẹ̀lú ìpè. Nígbà tí wọ́n dé sí ilẹ̀ ìpakà , Ussa sì na ọwọ́ rẹ̀ síta láti di àpótí ẹ̀rí Olúwa mú, nítorí màlúù kọsẹ̀. Ìbínú Olúwa, sì ru sí , ó sì lù ú bolẹ̀ nítorí o ti fi ọwọ́ rẹ̀ lórí àpótí ẹ̀rí. Bẹ́ẹ̀ ni ó sì kú síbẹ̀ níwájú Ọlọ́run. Nígbà náà sì bínú nítorí ìbínú Olúwa ké jáde lórí , àti títí di òní, wọ́n sì ń pe ibẹ̀ ní -. Dafidi sì bẹ̀rù Ọlọ́run ní ọjọ́ náà, ó sì béèrè pé, báwo ni èmi náà ó ṣe gbé àpótí ẹ̀rí Ọlọ́run sí ọ̀dọ̀ mi? Kò gbé àpótí ẹ̀rí náà wá sí ọ̀dọ̀ ará rẹ̀ ní ìlú ti dípò èyí, ó sì gbé e yà sí ilé - ará . Àpótí ẹ̀rí Olúwa sì wà lọ́dọ̀ àwọn ará ilé - ní ilé rẹ̀ fún oṣù mẹ́ta, Olúwa sì bùkún agbo ilé àti gbogbo ohun tí ó ní.

Every verse in 1 Chronicles 13

Chapter navigation

Biblica® ní oore ọ̀fẹ́ láti lo Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní™ / Biblica® Open Yoruba Contemporary Bible™ Copyright © 2009, 2017 by Biblica, Inc. “Biblica” is a trademark registered in the United States Patent and Trademark Office by Biblica, Inc. Used with permission. Licensed under CC BY-SA 4.0.

0:000:00