1 Chronicles

1 Chronicles 19

Biblica® Open Yoruba Contemporary Bible · tap any highlighted word for context

1 Chronicles 19 — Scripture text (Biblica® Open Yoruba Contemporary Bible)

Ní àkókò yí, Nahaṣi ọba àwọn ará sì kú, ọmọ rẹ̀ sì rọ́pò rẹ̀ gẹ́gẹ́ bí ọba. Dafidi rò wí pé èmi yóò fi inú rere hàn sí ọmọ ṣi, nítorí baba a rẹ̀ fi inú rere hàn sí mi. Bẹ́ẹ̀ ni, Dafidi rán àwọn aṣojú lọ láti lọ fi ìbá kẹ́dùn rẹ̀ hàn sí ní ti baba a rẹ̀. Nígbà tí àwọn ọkùnrin wá sí ọ̀dọ̀ ní ilẹ̀ àwọn ará láti fi ìbá kẹ́dùn rẹ̀ hàn sí i. Àwọn ọkùnrin ọlọ́lá ti sọ fún pé, “Ṣé ìwọ rò pé ń bu ọlá fún baba rẹ nípa rírán àwọn olùtùnú sí ọ? Ṣé àwọn ọkùnrin rẹ̀ wá sí ọ̀dọ̀ rẹ láti rìn wò àti láti bì í ṣubú, àti láti ṣe ayọ́lẹ̀wò ilẹ̀ náà.” Bẹ́ẹ̀ ni fi ipá mú àwọn ọkùnrin , fá irun wọn, wọ́n gé ẹ̀wù wọn kúrò ní àárín ìdí rẹ̀, ó sì rán wọn lọ. Nígbà tí ẹnìkan wá, tí ó sì sọ fún nípa àwọn ọkùnrin rẹ̀, ó rán àwọn ìránṣẹ́ láti lọ bá wọn, nítorí wọ́n ti di rírẹ̀ sílẹ̀ gidigidi. Ọba wí pe, “Dúró ní títí tí irùngbọ̀n yín yóò fi hù, nígbà náà ẹ padà wá”. Nígbà tí àwọn ará sì ri pé wọ́n ti di ẹ̀ṣẹ̀ ní ihò imú , Hanuni àti àwọn ará rán ẹgbẹ̀rún (1,000) tálẹ́ǹtì fàdákà láti gba iṣẹ́ àwọn kẹ̀kẹ́ àti àwọn agun-kẹ̀kẹ́ láti -, Siria àti . Wọ́n gba iṣẹ́ ẹgbẹ̀rin méjìlélọ́gbọ̀n (32,000) kẹ̀kẹ́ àti agun-kẹ̀kẹ́ àti ọba pẹ̀lú àwọn ọ̀wọ́ ọmọ-ogun rẹ̀ tí ó wá pàgọ́ ní ẹ̀bá , nígbà tí àwọn ará kójọpọ̀ láti ìlú wọn, tí wọ́n sì jáde lọ fún ogun. Ní gbígbọ́ eléyìí, Dafidi rán jáde pẹ̀lú gbogbo àwọn ọmọ-ogun ọkùnrin tí ó le jà. Àwọn ọmọ sì jáde wá, wọ́n sì tẹ́ ogun ní ẹnu odi ìlú ńlá wọn, nígbà tí àwọn ọba tí ó wá, fún rara wọn wà ni orílẹ̀-èdè tí ó ṣí sílẹ̀. Joabu ri wí pé àwọn ìlà ogun wà níwájú àti ẹ̀yìn òun, bẹ́ẹ̀ ni o mu àwọn ọmọ-ogun tí ó dára ní ẹli, o sì tẹ́ ogun wọn sí àwọn ará . Ó fi ìyókù àwọn ọkùnrin náà sí abẹ́ àkóso ṣ arákùnrin rẹ̀, a sì tẹ́ wọn kí wọn dojúkọ àwọn ará . Joabu wí pé tí àwọn ará bá le jù fún mi, nígbà náà, ìwọ ni kí o gbà mí; ṣùgbọ́n tí àwọn ará bá le jù fún ọ, nígbà náà èmi yóò gbà ọ́. Jẹ́ alágbára kí ẹ sì jẹ́ kí a jà pẹ̀lú ìgboyà fún àwọn ènìyàn wa àti àwọn ìlú ńlá ti Ọlọ́run wa. Olúwa yóò ṣe ohun tí ó dára ní ojú rẹ̀. Nígbà náà àti àwọn ọmọ-ogun pẹ̀lú rẹ̀ lọ síwájú láti lọ jà pẹ̀lú àwọn ará . Wọ́n sì sálọ kúrò níwájú rẹ̀. Nígbà ti àwọn ará ri pé àwọn ará ń sálọ, àwọn náà sálọ kúrò níwájú arákùnrin rẹ̀ ṣ. Wọ́n sì wọ inú ìlú ńlá lọ. Bẹ́ẹ̀ ni padà lọ sí ẹmu. Lẹ́yìn ìgbà tí àwọn ará rí wí pé àwọn ẹli ti lé wọn, wọ́n rán ìránṣẹ́. A sì mú àwọn ará rékọjá odò wá, pẹ̀lú Ṣofaki alákòóso ọmọ-ogun , tí ó ń darí wọn. Nígbà tí a sọ fún nípa èyí, ó pe gbogbo ẹli jọ wọ́n sì rékọjá ; Ó lọ síwájú wọn, ó sì fa ìlà ogun dojúkọ wọ́n. Dafidi fa ìlà rẹ̀ láti bá àwọn ará jagun wọ́n sì dojú ìjà kọ ọ́. Ṣùgbọ́n àwọn ará sálọ kúrò níwájú ẹli, Dafidi sì pa ẹ̀ẹ́dẹ́gbàárin (7,000) agun-kẹ̀kẹ́ wọn àti ọ̀kẹ́ méjì (40,000) ọmọ-ogun ẹlẹ́ṣẹ̀. Ó pa Ṣofaki alákòóso ọmọ-ogun wọn pẹ̀lú. Nígbà tí àwọn ẹrú rí i wí pé ẹli ti borí wọn, wọ́n ṣe àlàáfíà pẹ̀lú , wọ́n sì ń sìn ní abẹ́ ẹ rẹ̀. Bẹ́ẹ̀ ni, àwọn ará kò ní ìfẹ́ sí ríran àwọn ará lọ́wọ́ mọ́.

Every verse in 1 Chronicles 19

Chapter navigation

Biblica® ní oore ọ̀fẹ́ láti lo Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní™ / Biblica® Open Yoruba Contemporary Bible™ Copyright © 2009, 2017 by Biblica, Inc. “Biblica” is a trademark registered in the United States Patent and Trademark Office by Biblica, Inc. Used with permission. Licensed under CC BY-SA 4.0.

0:000:00