2 Kings

2 Kings 8

Biblica® Open Yoruba Contemporary Bible · tap any highlighted word for context

2 Kings 8 — Scripture text (Biblica® Open Yoruba Contemporary Bible)

Nísinsin yìí, ṣa wí fún obìnrin náà tí ọmọ rẹ̀ ọkùnrin jí padà sáyé pé, “Jáde lọ pẹ̀lú ìdílé rẹ kí o sì lọ dúró fún ìgbà díẹ̀ ní ibikíbi tí o bá le dúró sí, nítorí Olúwa ti pàṣẹ ìyàn ní ìlú tí yóò lò tó ọdún méje.” Obìnrin náà tẹ̀síwájú gẹ́gẹ́ bí ọ̀rọ̀ ènìyàn Ọlọ́run ti sọ. Òun àti ìdílé rẹ̀ sí lọ, wọ́n sì ṣe àtìpó ní ilẹ̀ àwọn ará fún ọdún méje. Ní ẹ̀yìn ọdún méje ó sì padà wá láti ilẹ̀ àwọn ará ó sì lọ sí ọ̀dọ̀ ọba láti lọ bẹ̀ ẹ́ fún ilé àti ilẹ̀ rẹ̀. Ọba sì ń sọ̀rọ̀ sí , ìránṣẹ́ ènìyàn Ọlọ́run pé, “Sọ fún mi nípa gbogbo ohun ńlá tí ṣa ti ṣe.” Bí ti ń sọ bí tí ṣa ṣe jí òkú di alààyè, obìnrin náà tí ọmọ rẹ̀ ọkùnrin tí ṣa ti dá padà sí ayé wá láti bẹ ọba fún ilé àti ilẹ̀ rẹ̀. Gehasi sì wí pé, “Obìnrin náà nìyìí olúwa mi ọba, ọmọkùnrin rẹ náà nìyí tí ṣa ti jí dìde sí ayé.” Ọba béèrè lọ́wọ́ obìnrin náà nípa rẹ̀, ó sì sọ fún un. Ó sì yan ìjòyè kan fún ún fún ọ̀rọ̀ rẹ̀ ó sì wí fún un pé, “Ẹ fún un padà gbogbo ohun tí ó bá jẹ́ tirẹ̀, àti pẹ̀lú gbogbo èrè ilé rẹ̀ fún ún láti ọjọ́ tí ó ti kúrò ní ìlú títí di àsìkò yìí.” ṣa lọ sí , Beni- ọba ń ṣe àìsàn. Nígbà tí wọ́n sọ fún ọba pé, “Ènìyàn Ọlọ́run ti wá láti gbogbo ọ̀nà òkè síbí,” ọba sì wí fún pé, “Mú ọrẹ lọ́wọ́ rẹ, sì lọ pàdé ènìyàn Ọlọ́run. Kí o sì béèrè Olúwa láti ọ̀dọ̀ rẹ̀, béèrè lọ́wọ́ rẹ̀ pé ṣé èmi yóò sàn nínú àìsàn yìí?” Hasaeli lọ láti pàdé ṣa, ó mú lọ pẹ̀lú rẹ̀ ẹ̀bùn gẹ́gẹ́ bí ogójì ẹrù ìbákasẹ tí gbogbo ìní tí ó dára jù fún wíwò ti , ó sì wọlé lọ ó sì dúró níwájú rẹ̀, ó sì wí pé, “Ọmọ rẹ - ọba rán mi láti béèrè pé, ‘Ṣé èmi yóò sàn nínú àìsàn mi yìí?’ ” ṣa da á lóhùn pé, “Lọ kí o lọ sọ fún un pé, ‘Ìwo ìbá sàn nítòótọ́’; ṣùgbọ́n Olúwa ti fihàn mí pé nítòótọ́ òun yóò kùú.” Ó sì ranjú mọ́ ọn pẹ̀lú àtẹjúmọ́ gidigidi títí tí ojú fi ti . Nígbà náà ènìyàn Ọlọ́run bẹ̀rẹ̀ sí ní sọkún. “Kí ni ó dé tí olúwa mi fi ń sọkún?” béèrè. “Nítorí pé èmi mọ ibi tí ìwọ yóò ṣe sí ẹli,” ó sì dáhùn pé, “Ìwọ yóò fi iná si odi agbára wọn, ìwọ yóò, pa àwọn ọ̀dọ́ ọmọkùnrin wọn pẹ̀lú idà, ìwọ yóò kọlù àwọn ọmọ wẹ́wẹ́ wọn, ìwọ ó sì fọ́ wọn túútúú, ìwọ o sì la inú àwọn aboyún wọn.” Hasaeli sì wí pé. “Báwo ni ìránṣẹ́ rẹ, ajá lásán làsàn yóò ṣe ṣe irú nǹkan ńlá bẹ́ẹ̀?” “Olúwa ti fihàn mí pé ìwọ ni yóò jẹ ọba ,” ṣa dá a lóhùn. Nígbà náà fi ṣa sílẹ̀ ó sì padà sí ọ̀dọ̀ ọ̀gá rẹ̀. Nígbà tí - béèrè, “Kí ni ohun tí ṣa sọ fún ọ?” dá a lóhùn, “Ó sọ fún mi wí pé ìwọ yóò sàn nítòótọ́.” Ṣùgbọ́n ní ọjọ́ kejì ó mú aṣọ tí ó nípọn, ó sì kì í bọ inú omi ó sì tẹ̀ ẹ́ sí ojú ọba, bẹ́ẹ̀ ni ó sì kú. Nígbà náà sì rọ́pò rẹ̀ gẹ́gẹ́ bí ọba. Ní ọdún karùn-ún ti ọmọ ọba ẹli, nígbà tí ṣafati jẹ́ ọba , Jehoramu ọmọ ṣafati bẹ̀rẹ̀ ìjọba rẹ̀ gẹ́gẹ́ bí ọba . Ó jẹ́ ẹni ọdún méjìlélọ́gbọ̀n nígbà tí ó di ọba. Ó sì jẹ ọba ní ẹmu fún ọdún mẹ́jọ. Ó sì rìn ní ọ̀nà ọba ẹli, gẹ́gẹ́ bí ilé ti lọ, nítorí ó fẹ́ ọmọbìnrin ó sì ṣe ohun búburú níwájú Olúwa. Bí ó tilẹ̀ jẹ́ pé, nítorí ti ìránṣẹ́ rẹ̀ . Olúwa kò fẹ́ pa run, ó ti ṣèlérí láti ṣètọ́jú ìmọ́lẹ̀ fún àti àwọn ilé rẹ̀ títí láéláé. Ní àkókò , Edomu ṣọ̀tẹ̀ sí , wọ́n sì gbé ọba tiwọn kalẹ̀. Bẹ́ẹ̀ ni lọ sí pẹ̀lú gbogbo kẹ̀kẹ́ rẹ̀. Àwọn ará sì yí i ká àti kẹ̀kẹ́ àwọn olórí wọn, ṣùgbọ́n ó dìde dúró ní òru; àwọn ogun rẹ̀ síbẹ̀síbẹ̀, sá padà lọ ilé. Títí ó fi di òní, Edomu wà nínú ọ̀tẹ̀ lórí , Libina ṣọ̀tẹ̀ ní àkókò kan náà. Gẹ́gẹ́ bí fún iṣẹ́ mìíràn ti ìjọba , àti gbogbo ohun tí ó ṣe, ṣé a kò ha kọ wọ́n sínú ìwé ọ̀rọ̀ ọjọ́ àwọn ọba ? Jehoramu sì sùn pẹ̀lú àwọn baba rẹ̀ a sì sin ín pẹ̀lú wọn ní ìlú , Ahasiah ọmọ rẹ̀ sì jẹ ọba ní ipò rẹ̀. Ní ọdún méjìlá ọmọkùnrin ọba ẹli, Ahasiah ọmọkùnrin ọba bẹ̀rẹ̀ ìjọba rẹ̀. Ahasiah jẹ́ ẹni ọdún méjìlélógún nígbà tí ó di ọba. Ó sì jẹ ọba ní ọdún kan ní ẹmu. Orúkọ ìyá rẹ̀ a sì máa jẹ́ , ọmọbìnrin ọba ẹli. Nígbà tí ó rin ọ̀nà ilé ó sì ṣe búburú níwájú Olúwa, gẹ́gẹ́ bí ilé ti ṣe, nítorí ó tan nípa ìgbéyàwó sí ìdílé . Ahasiah sì lọ pẹ̀lú ọmọ lọ sí ogun lórí ọba ní . Àwọn ará ṣẹ́ lẹ́sẹ̀. Bẹ́ẹ̀ ni ọba padà sí láti wo ọgbẹ́ rẹ̀ sàn tí ará ti jẹ ní yà lórí rẹ̀ ní ní ojú ogun rẹ̀ pẹ̀lú ọba . Nígbà náà ọmọ ọba sọ̀kalẹ̀ lọ sí láti lọ wo ọmọ nítorí tí ó fi ara pa.

Every verse in 2 Kings 8

Chapter navigation

Biblica® ní oore ọ̀fẹ́ láti lo Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní™ / Biblica® Open Yoruba Contemporary Bible™ Copyright © 2009, 2017 by Biblica, Inc. “Biblica” is a trademark registered in the United States Patent and Trademark Office by Biblica, Inc. Used with permission. Licensed under CC BY-SA 4.0.

0:000:00