Acts

Acts 18

Biblica® Open Yoruba Contemporary Bible · tap any highlighted word for context

Acts 18 — Scripture text (Biblica® Open Yoruba Contemporary Bible)

Lẹ́yìn nǹkan wọ̀nyí, Paulu jáde kúrò ni lọ sí Kọrinti. Ó sì rí Júù kan tí a ń pè ní , tí a bí ni Pọntu, tí ó ti dé ní lọ́ọ́lọ́ọ́, pẹ̀lú aya rẹ̀; nítorí tí pàṣẹ pé, kí gbogbo àwọn Júù jáde kúrò ní . Ó sì tọ̀ wọ́n lọ láti rí wọn. Nítorí tí òun náà jẹ́ íṣẹ̀-ọwọ́ kan náà, ó bá wọn jókòó, ó sì ń ṣiṣẹ́: nítorí àgọ́ pípa ni iṣẹ́ ọwọ́ wọn. Ó sì ń fi ọ̀rọ̀ wé ọ̀rọ̀ pẹ̀lú wọn nínú ọgu lọ́jọjọ́ ìsinmi, ó sì ń yí àwọn Júù àti àwọn lọ́kàn padà. Nígbà tí àti sì tí wá, ọ̀rọ̀ náà ká lára, ó ń fihàn fún àwọn Júù pé, Jesu ni náà. Nígbà tí wọ́n sì sàtakò rẹ̀, tí wọ́n sì sọ̀rọ̀-òdì, ó gbọ́n aṣọ rẹ̀, ó sì wí fún wọn pé, “Ẹ̀jẹ̀ yin ń bẹ lórí ara yin; ọrùn mi mọ́: láti ìsinsin yìí lọ, èmi yóò tọ àwọn aláìkọlà lọ.” Ó sì lọ kúrò níbẹ̀, ó wọ ilé ọkùnrin kan tí a ń pé ní , ẹni tí o ń sin Ọlọ́run; ilé rẹ̀ sì wà lẹ́gbẹ̀ ọgu tímọ́tímọ́. Krisipu, olórí ọgu, sì gba Olúwa gbọ́ pẹ̀lú gbogbo ilé rẹ̀, àti ọ̀pọ̀ nínú àwọn ara Kọrinti, nígbà tí wọ́n gbọ́, wọ́n gbàgbọ́, a sì bamitiisi wọn. Olúwa sì sọ fún lóru ni ojúran pé, “Má bẹ̀rù, ṣá máa sọ, má sì ṣe pa ẹnu rẹ̀ mọ́. Nítorí tí èmí wà pẹ̀lú rẹ, kò sì sí ẹni tí yóò dìde sí ọ láti pa ọ lára: nítorí mo ní ènìyàn púpọ̀ ni ìlú yìí.” Ó sì jókòó níbẹ̀ ní ọdún kan àti oṣù mẹ́fà, ó ń kọ́ni ní ọ̀rọ̀ Ọlọ́run láàrín wọn. Nígbà tí sì jẹ baálẹ̀ , àwọn Júù fi ìfìmọ̀ṣọ̀kan dìde sí wọn sì mú un wá síwájú ìtẹ́ ìdájọ́. Wọ́n wí pé, “Ọkùnrin yìí ń yí àwọn ènìyàn lọ́kàn padà, láti máa sin Ọlọ́run lòdì sí òfin.” Nígbà tí ń fẹ́ dáhùn, Gallioni wí fún àwọn Júù pé, “Ìbá ṣe pé ọ̀ràn búburú tàbí tí jàgídíjàgan kan ni, èmi ìbá gbè yín, ẹ̀yin Júù, Ṣùgbọ́n bí ó ti ṣe ọ̀ràn nípa ọ̀rọ̀ àti orúkọ, àti ti òfin yín ni, ki ẹ̀yin bojútó o fúnra yín; nítorí tí èmi kò fẹ́ ṣe ídàájọ́ nǹkan báwọ̀nyí.” Ó sì lé wọn kúrò ní ibi ìtẹ́ ìdájọ́. Gbogbo àwọn sì mú , olórí ọgu, wọ́n sì lù ú níwájú ìtẹ́ ìdájọ́. Gallioni kò sì bìkítà fún nǹkan wọ̀nyí. Paulu sì dúró sí i níbẹ̀ lọ́jọ́ púpọ̀, nígbà tí ó sì dágbére fún àwọn arákùnrin, ó bá ọkọ̀ ojú omi lọ si , àti àti pẹ̀lú rẹ̀; ó tí fá orí rẹ̀ ni , nítorí tí ó ti jẹ́ ẹ̀jẹ́. Ó sì sọ̀kalẹ̀ wá sí , ó sì fi wọ́n sílẹ̀ níbẹ̀, ṣùgbọ́n òun tìkára rẹ̀ wọ inú ọgu lọ, ó sì bá àwọn Júù fi ọ̀rọ̀ wé ọ̀rọ̀. Nígbà tí wọ́n sì bẹ̀ ẹ́ pé, kí ó bá àwọn jókòó díẹ̀ sí i, ó kọ̀. Ṣùgbọ́n ó dágbére fún wọn, ó sì wí pé, “Èmi ó tún padà tọ̀ yín wá, bí Ọlọ́run bá fẹ́.” Ó sì lọ kúrò láti . Nígbà tí ó sì tí gúnlẹ̀ ni , ó gòkè lọ si ẹmu láti kí ìjọ, lẹ́yìn náà ó sọ̀kalẹ̀ lọ sí . Nígbà tí ó sì gbé ọjọ́ díẹ̀ níbẹ̀, ó n lọ, láti káàkiri ni agbègbè àti , o ń mu àwọn ọmọ-ẹ̀yìn lọ́kàn le. Júù kan sì wà tí a ń pè ni , tí a bí ni , ó wá sí . Ó ní ẹ̀bùn ọ̀rọ̀ sísọ, ó sì mọ ìwé mímọ́ púpọ̀. Ọkùnrin yìí ni a tí kọ́ ní ọ̀nà tí Olúwa; ó sì ṣe ẹni tí ó ní ìtara tí ẹ̀mí, ó ń sọ̀rọ̀ ó sì ń kọ́ni ní àwọn ohun tí i ṣe ti dáradára; kìkì bamitiisi tí ní ó mọ̀. Ó sì bẹ̀rẹ̀ sí fi ìgboyà sọ̀rọ̀ ni ọgu. Nígbà tí àti gbọ́ ọ̀rọ̀ rẹ̀, wọ́n mú un sọ́dọ̀, wọ́n sì túbọ̀ sọ ọ̀nà Ọlọ́run fún un dájúdájú. Nígbà tí ó sì ń fẹ́ kọjá lọ sì , àwọn arákùnrin gbà á ní ìyànjú, wọ́n sì kọ̀wé sí àwọn ọmọ-ẹ̀yìn kí wọ́n gbà á, nígbà tí ó sì dé, ó ràn àwọn tí ó gbàgbọ́ nípasẹ̀ oore-ọ̀fẹ́ lọ́wọ́ púpọ̀. Nítorí tí o sọ àsọyé fún àwọn Júù ní gbangba, ó ń fi í hàn nínú ìwé mímọ́ pé, Jesu ni .

Every verse in Acts 18

Chapter navigation

Biblica® ní oore ọ̀fẹ́ láti lo Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní™ / Biblica® Open Yoruba Contemporary Bible™ Copyright © 2009, 2017 by Biblica, Inc. “Biblica” is a trademark registered in the United States Patent and Trademark Office by Biblica, Inc. Used with permission. Licensed under CC BY-SA 4.0.

0:000:00