Exodus

Exodus 1

Biblica® Open Yoruba Contemporary Bible · tap any highlighted word for context

Exodus 1 — Scripture text (Biblica® Open Yoruba Contemporary Bible)

Ìwọ̀nyí ni àwọn orúkọ ọmọ ẹli tí wọ́n bá ọbu lọ sí , ẹnìkọ̀ọ̀kan pẹ̀lú ìdílé rẹ̀: Reubeni, Simeoni, Lefi àti ; Isakari, Sebuluni àti ; Dani àti ; Gadi àti Aṣeri. Àwọn ìran ọbu sì jẹ́ àádọ́rin ní àpapọ̀; Josẹfu sì ti wà ní . Wàyí o, Josẹfu àti gbogbo àwọn arákùnrin rẹ̀ àti gbogbo ìran náà kú, ṣùgbọ́n àwọn ará ẹli ń bí sí i, wọ́n ń pọ̀ sí i gidigidi, wọ́n kò sì ní òǹkà tí ó fi jẹ́ pé wọ́n kún ilẹ̀ náà. Nígbà náà ni ọba tuntun mìíràn tí kò mọ ẹfu jẹ ní ilẹ̀ . Ó sọ fún àwọn ènìyàn rẹ̀, “Ẹ wò ó, àwọn ará ẹli ti pọ̀ ní iye àti agbára jù fún wa. Ẹ wá, ẹ jẹ́ kí a lo ọgbọ́n àlùmọ̀kọ́rọ́yí láti dá wọn lẹ́kun, bí kò ṣe bẹ́ẹ̀ wọn yóò túbọ̀ máa pọ̀ sí i. Bí ogun bá sì bẹ́ sílẹ̀, wọn yóò darapọ̀ mọ́ àwọn ọ̀tá wa, wọn yóò sì da ojú ìjà kọ wá, wọn yóò sì sá àsálà kúrò ní ilẹ̀ yìí.” Nítorí náà, wọ́n yan àwọn ọ̀gá akóniṣiṣẹ́ lé wọn lórí láti máa ni wọ́n lára pẹ̀lú iṣẹ́ àṣekára. Wọ́n sì kọ́ àti gẹ́gẹ́ bí ìlú ìṣúra pamọ́ sí fún . Ṣùgbọ́n bí a ti ń ni wọ́n lára tó, bẹ́ẹ̀ ni wọ́n ń pọ̀ sí i, tí wọ́n sì ń tànkálẹ̀. Nítorí náà, àwọn ará bẹ̀rù nítorí àwọn ará ẹli. Àwọn ará sì mú àwọn ọmọ ẹli sìn ní àsìnpa. Wọ́n mú wọn gbé ìgbé ayé kíkorò nípa iṣẹ́ bíríkì àti àwọn írúú iṣẹ́ oko; àwọn ará ń lò wọ́n ní ìlòkulò. Ọba sọ fún àwọn agbẹ̀bí ti orúkọ wọn ń jẹ́ Ṣifura àti pé, “Nígbà ti ẹ̀yin bá ń gbẹ̀bí àwọn obìnrin , tí ẹ sì kíyèsi wọn lórí ìkúnlẹ̀ ìrọbí wọn, bí ó bá jẹ́ ọkùnrin ni ọmọ náà, ẹ pa á; ṣùgbọ́n bí ó bá jẹ́ obìnrin, ẹ jẹ́ kí ó wà láààyè.” Ṣùgbọ́n àwọn agbẹ̀bí bẹ̀rù Ọlọ́run, wọn kò sì ṣe gẹ́gẹ́ bí ọba ti wí fún wọn; wọ́n jẹ́ kí àwọn ọmọkùnrin wà láààyè. Ọba pe àwọn agbẹ̀bí ó sì béèrè lọ́wọ́ wọn pé, “Èéṣe tí ẹ̀yin fi ṣe èyí? Èéṣe tí ẹ̀yin fi dá àwọn ọmọkùnrin si?” Àwọn agbẹ̀bí náà sì dá lóhùn pé, “Àwọn obìnrin kò rí bí àwọn obìnrin , wọ́n ní agbára, wọ́n sì ti máa ń bí ọmọ kí àwọn agbẹ̀bí tó dé ọ̀dọ̀ wọn.” Nítorí náà Ọlọ́run ṣàánú fún àwọn agbẹ̀bí náà, àwọn ọmọ ẹli sì ń le sí i, wọ́n sì ń pọ̀ sí i jọjọ. Nítorí pé àwọn agbẹ̀bí bẹ̀rù Ọlọ́run, Ọlọ́run sì fún wọn ni ìdílé tiwọn. Nígbà náà ni pàṣẹ yìí fún gbogbo àwọn ènìyàn rẹ̀ pé, “Gbogbo ọmọkùnrin tí a bí ni kí ẹ gbé jù sínú odò , ṣùgbọ́n gbogbo àwọn ọmọbìnrin ni kí ẹ jẹ́ kí wọn ó wà láààyè.”

Every verse in Exodus 1

Chapter navigation

Biblica® ní oore ọ̀fẹ́ láti lo Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní™ / Biblica® Open Yoruba Contemporary Bible™ Copyright © 2009, 2017 by Biblica, Inc. “Biblica” is a trademark registered in the United States Patent and Trademark Office by Biblica, Inc. Used with permission. Licensed under CC BY-SA 4.0.

0:000:00