Exodus
Exodus 11
Biblica® Open Yoruba Contemporary Bible · tap any highlighted word for context
Exodus 11 — Scripture text (Biblica® Open Yoruba Contemporary Bible)
Nísinsin yìí, Olúwa sọ fún pé èmi yóò mú ààrùn kan sí i wá sí orí àti ilẹ̀ . Lẹ́yìn náà yóò jẹ́ kí ẹ̀yin kí ó lọ kúrò níhìn-ín yìí, nígbà tí ó bá sì ṣe bẹ́ẹ̀ yóò lé yín jáde pátápátá. Sọ fún àwọn ènìyàn náà pé kí tọkùnrin tobìnrin wọn béèrè fún ohun èlò fàdákà àti wúrà lọ́wọ́ aládùúgbò rẹ̀. (Olúwa jẹ́ kí wọn rí ojúrere àwọn ará , pàápàá, Mose fúnra rẹ̀ di ènìyàn pàtàkì ní ilẹ̀ ní iwájú àwọn ìjòyè àti ní iwájú àwọn ènìyàn pẹ̀lú). Nígbà náà ni wí pé, “Èyí ni ohun tí Olúwa sọ, ‘Ní ọ̀gànjọ́ òru èmi yóò la ilẹ̀ kọjá. Gbogbo àkọ́bí ọmọkùnrin tí ó wà ní ilẹ̀ ni yóò kùú, bẹ̀rẹ̀ lórí àkọ́bí ọkùnrin tí ó jókòó lórí ìtẹ́ rẹ̀, tí ó fi dé orí àkọ́bí ọmọkùnrin ti ẹrúbìnrin tí ń lọ ọlọ àti gbogbo àkọ́bí ẹran ọ̀sìn pẹ̀lú. Igbe ẹkún ńlá yóò sọ jákèjádò gbogbo ilẹ̀ . Irú ohun búburú tí kò ṣẹlẹ̀ rí tí kò sí tún ni ṣẹlẹ̀ mọ́. Ṣùgbọ́n láàrín àwọn ará ẹli ajá lásán kò ní gbó àwọn ènìyàn tàbí àwọn ẹran wọn.’ Nígbà náà ni ẹ̀yin yóò mọ̀ pé Olúwa ti fi ìyàtọ̀ sáàrín àwọn ará àti ẹli. Gbogbo àwọn ìjòyè rẹ̀ wọ̀nyí yóò tọ̀ mí wá, wọn yóò wólẹ̀ ni iwájú, mi wọn yóò sì máa wí pé, ‘Lọ àti àwọn ènìyàn tí ó tẹ̀lé ọ!’ Lẹ́yìn náà èmi yóò jáde.” Nígbà náà ni fi ìbínú jáde kúrò ní iwájú . Olúwa ti sọ fún pé, “Farao yóò kọ̀ láti fetísílẹ̀ sí ọ kí iṣẹ́ ìyanu mí le pọ̀ sí ní .” Mose àti ṣe àwọn iṣẹ́ ìyanu wọ̀nyí níwájú , ṣùgbọ́n Olúwa sé ọkàn le, òun kò sí jẹ́ kí àwọn ẹli jáde kúrò ni orílẹ̀-èdè rẹ̀.
Every verse in Exodus 11
Chapter navigation
Biblica® ní oore ọ̀fẹ́ láti lo Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní™ / Biblica® Open Yoruba Contemporary Bible™ Copyright © 2009, 2017 by Biblica, Inc. “Biblica” is a trademark registered in the United States Patent and Trademark Office by Biblica, Inc. Used with permission. Licensed under CC BY-SA 4.0.