Jeremiah
Jeremiah 37
Biblica® Open Yoruba Contemporary Bible · tap any highlighted word for context
Jeremiah 37 — Scripture text (Biblica® Open Yoruba Contemporary Bible)
Sedekiah ọmọ sì jẹ ọba ní ipò ọmọ ẹni tí ọba fi jẹ ọba ní ilẹ̀ . Ṣùgbọ́n àti òun àti àwọn ìránṣẹ́ rẹ̀ àti àwọn ènìyàn ilẹ̀ náà kò fetísí ọ̀rọ̀ Olúwa tí ó sọ nípa wòlíì . Sedekiah ọba sì rán ọmọ Ṣelemiah àti ọmọ sí wòlíì wí pé, “Jọ̀wọ́ gbàdúrà sí Olúwa Ọlọ́run wa fún wa.” Nígbà yìí sì ń wọlé, ó sì ń jáde láàrín àwọn ènìyàn nítorí wọ́n ti fi sínú túbú. Àwọn ọmọ-ogun ti jáde kúrò nílẹ̀ àti nígbà tí àwọn ará tó ń ṣàtìpó ní ẹmu gbọ́ ìròyìn nípa wọn, wọ́n kúrò ní ẹmu. Nígbà náà ni ọ̀rọ̀ Olúwa tọ wòlíì Ọlọ́run wá: “Èyí ni, ohun tí Olúwa Ọlọ́run àwọn ẹli sọ fún ọba àwọn tó rán ọ láti wádìí nípa mi. ‘Àwọn ọmọ-ogun tó jáde láti kún ọ lọ́wọ́ yóò padà sílẹ̀ wọn sí . Nígbà náà ni àwọn ará yóò padà láti gbógun ti ìlú. Wọn yóò mú wọn nígbèkùn, wọn yóò sì fi iná jó ìlú náà kanlẹ̀.’ “Èyí ni ohun tí Olúwa wí, ẹ má ṣe tan ara yín jẹ ní èrò wí pé, ‘Àwọn ará yóò fi wá sílẹ̀ pẹ̀lú ìdánilójú.’ Wọn kò ní ṣe bẹ́ẹ̀. Kódà tó bá ṣe pé wọn yóò ṣẹ́gun àwọn ọmọ-ogun tí ń gbóguntì yín àti àwọn tí ìjàǹbá ṣe, tí wọ́n ti fi sílẹ̀ ní ibùdó wọn; wọn yóò jáde láti jó ìlú náà kanlẹ̀.” Lẹ́yìn tí àwọn ọmọ-ogun ti kúrò ní ẹmu nítorí àwọn ọmọ-ogun . múra láti fi ìlú náà sílẹ̀, láti lọ sí olú ìlú láti gba ẹ̀tọ́ rẹ̀ nínú ohun ìní láàrín àwọn ènìyàn tó wà níbẹ̀. Ṣùgbọ́n nígbà tí wọ́n dé ẹnu ibodè , olórí àwọn olùṣọ́ tí orúkọ rẹ ń jẹ́ ọmọ Ṣelemiah ọmọ mú un, ó wí pé, “Ìwọ ń fi ara mọ́ àwọn ará .” sọ wí pé, “Èyí kì í ṣe òtítọ́! Èmi kò yapa sí àwọn ará .” Ṣùgbọ́n ko gbọ́ tirẹ̀, dípò èyí a mú , ó sì mú un lọ sí ọ̀dọ̀ àwọn ìjòyè. Nítorí náà ni àwọn ìjòyè ṣe bínú sí , wọ́n jẹ ẹ́ ní yà, wọ́n tún fi sí túbú nílé akọ̀wé nítorí wọ́n ti fi èyí ṣe ilé túbú. Wọ́n fi sínú túbú tí ó ṣókùnkùn biribiri; níbi tí ó wà fún ìgbà pípẹ́. Nígbà náà ni ọba ránṣẹ́ sí i, tí ó sì pàṣẹ pé kí wọ́n mú wá sí ààfin níbi tí ó ti bi í ní ìkọ̀kọ̀ pé, “Ǹjẹ́ ọ̀rọ̀ kan wà láti ọ̀dọ̀ Olúwa?” fèsì pé, “Bẹ́ẹ̀ ni, wọn ó fi ọ́ lé ọwọ́ ọba .” Nígbà náà, sọ fún ọba pé, “Irú ẹ̀ṣẹ̀ wo ni mo ṣẹ̀ yín, àwọn ìjòyè yín pẹ̀lú àwọn ènìyàn tí ẹ fi sọ mí sínú túbú? Níbo ni àwọn wòlíì yín tí wọ́n ń sọ àsọtẹ́lẹ̀ fún un yín wí pé ọba kò ní gbóguntì yín wá? Ṣùgbọ́n ní báyìí, olúwa mi ọba, èmí bẹ̀ ọ. Jẹ́ kí n mú ẹ̀dùn ọkàn mi tọ̀ ọ́ wá; má ṣe rán mi padà sí ilé akọ̀wé, àfi kí n kú síbẹ̀.” Ọba wá pàṣẹ pé kí wọ́n fi sínú àgbàlá àwọn ẹ̀ṣọ́, àti kí wọn sì fún ní àkàrà ní ọjọ́ kọ̀ọ̀kan títí tí àkàrà tó wà ní ìlú yóò fi tán; bẹ́ẹ̀ ni wà nínú àgbàlá náà.
Every verse in Jeremiah 37
Chapter navigation
Biblica® ní oore ọ̀fẹ́ láti lo Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní™ / Biblica® Open Yoruba Contemporary Bible™ Copyright © 2009, 2017 by Biblica, Inc. “Biblica” is a trademark registered in the United States Patent and Trademark Office by Biblica, Inc. Used with permission. Licensed under CC BY-SA 4.0.