Jeremiah 41:9

“Nísinsin yìí, ihò náà tí ó kó gbogbo ara àwọn ọkùnrin tí ó ti pa pẹ̀lú Gedaliah sí ni ọba Asa ń lò gẹ́gẹ́ bí i ààbò nítorí ọba Baaṣa ti Israẹli. Iṣmaeli ọmọ Netaniah sì ti kó òkú kún inú rẹ̀.”

Jeremiah 41:9 — Biblica® Open Yoruba Contemporary Bible

Verse 9 of 18 in Jeremiah chapter 41 — Biblica® Open Yoruba Contemporary Bible. Read it in context below, with maps, timelines and thematic connections beside the text.

Jeremiah 41 — full chapter (Biblica® Open Yoruba Contemporary Bible)

Ní oṣù keje Iṣmaeli, ọmọ ọmọ ṣama, nínú irú-ọmọ ọba, àti àwọn ìjòyè ọba, àti àwọn ọkùnrin mẹ́wàá pẹ̀lú rẹ̀, wọ́n tọ ọmọ wá ní ; níbẹ̀ ni wọ́n jùmọ̀ jẹun ní . Iṣmaeli ọmọ àti àwọn ọkùnrin mẹ́wàá tí wọ́n wà pẹ̀lú rẹ̀, sì dìde wọ́n kọlu ọmọ , ọmọ Ṣafani pẹ̀lú idà. Wọ́n sì pa á, ẹni tí ọba ti fi jẹ baálẹ̀ lórí ilẹ̀ náà. Iṣmaeli sì tún pa gbogbo àwọn Júù tí wọ́n wà pẹ̀lú ní , àti gbogbo àwọn ọmọ-ogun tí wọ́n wà níbẹ̀ bákan náà. Ní ọjọ́ kejì tí wọ́n pa kí ó tó di wí pé ẹnikẹ́ni mọ̀, àwọn ọgọ́rin ọkùnrin wá láti Ṣekemu, Ṣilo àti , wọ́n fa irùngbọ̀n wọn, wọ́n ya aṣọ wọn, wọ́n ṣá ara wọn lọ́gbẹ́, wọ́n mú ẹbọ ọpẹ́ àti tùràrí wá sí ilé Olúwa. Iṣmaeli ọmọkùnrin jáde kúrò láti láti lọ pàdé wọn. Ó sì ń sọkún bí ó ti ṣe ń lọ, nígbà tí ó pàdé wọn, ó wí pé, “Ẹ wá sọ́dọ̀ ọmọkùnrin .” Nígbà tí wọ́n dé ìlú náà; Iṣmaeli ọmọkùnrin àti àwọn ọkùnrin tí ó wà pẹ̀lú rẹ̀ pa wọ́n, wọ́n sì sọ òkú wọn sínú ihò kan. Ṣùgbọ́n mẹ́wàá nínú wọn sọ fún Iṣmaeli pé, “Má ṣe pa wá! Àwa ní ọkà àti barle, òróró àti oyin ní ìpamọ́ nínú oko.” Nítorí náà, ó fi wọ́n sílẹ̀: kò sì pa wọ́n pẹ̀lú àwọn yòókù. Nísinsin yìí, ihò náà tí ó kó gbogbo ara àwọn ọkùnrin tí ó ti pa pẹ̀lú sí ni ọba ń lò gẹ́gẹ́ bí i ààbò nítorí ọba ṣa ti ẹli. Iṣmaeli ọmọ sì ti kó òkú kún inú rẹ̀. Iṣmaeli sì kó gbogbo àwọn ènìyàn tí ó wà ní nígbèkùn, ọmọbìnrin ọba àti gbogbo àwọn ènìyàn tókù síbẹ̀ lórí àwọn tí balógun àwọn ẹ̀ṣọ́ ti fi yan ọmọkùnrin ṣe olórí. Iṣmaeli ọmọkùnrin kó wọn ní ìgbèkùn, ó sì jáde rékọjá sí ọ̀dọ̀ àwọn . Nígbà tí ọmọkùnrin àti gbogbo àwọn olórí ogun tí wọ́n wà pẹ̀lú rẹ̀ gbọ́ nípa gbogbo ìpànìyàn náà tí Iṣmaeli ọmọ ti ṣe. Wọ́n kó gbogbo àwọn ọkùnrin wọn, wọ́n sì, lọ bá Iṣmaeli ọmọ jà. Wọ́n pàdé rẹ̀ ní odò kan lẹ́bàá . Nígbà tí gbogbo àwọn ènìyàn Iṣmaeli tí wọ́n wà pẹ̀lú rẹ̀ rí ọmọkùnrin àti àwọn olórí ogun rẹ̀ pẹ̀lú rẹ̀, wọ́n sì yọ̀. Gbogbo àwọn ènìyàn tí Iṣmaeli ti kó ní ìgbèkùn ní yípadà, wọ́n sì lọ sọ́dọ̀ ọmọ . Ṣùgbọ́n Iṣmaeli ọmọkùnrin àti àwọn mẹ́jọ nínú àwọn ọkùnrin rẹ̀ bọ́ lọ́wọ́ , wọ́n sì sálọ sí . Lẹ́yìn náà ọmọkùnrin àti gbogbo àwọn ọmọ-ogun tí wọn wà pẹ̀lú rẹ̀ sì kó gbogbo àwọn tí ó kù ní ; àwọn tí ó ti rí gbà lọ́wọ́ Iṣmaeli ọmọkùnrin ; lẹ́yìn ìgbà tí ó ti pa ọmọ . Àwọn ọmọ-ogun, àwọn obìnrin, àwọn ọmọdé àti àwọn olórí ilé ẹjọ́ tí ó ti kó wa láti . Wọ́n sì kúrò níbẹ̀, wọ́n dúró ní ní ẹ̀bá Bẹtilẹhẹmu ní ọ́nà ìrìnàjò wọn sí . Láti gba àwọn sílẹ̀. Wọ́n bẹ̀rù wọn nítorí wí pé, “Iṣmaeli ọmọ ti pa ọmọ èyí tí ọba ti yàn gẹ́gẹ́ bí i gómìnà lórí ilẹ̀ náà.”

Every verse in Jeremiah 41

Chapter navigation

Biblica® ní oore ọ̀fẹ́ láti lo Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní™ / Biblica® Open Yoruba Contemporary Bible™ Copyright © 2009, 2017 by Biblica, Inc. “Biblica” is a trademark registered in the United States Patent and Trademark Office by Biblica, Inc. Used with permission. Licensed under CC BY-SA 4.0.

0:000:00