Jeremiah

Jeremiah 43

Biblica® Open Yoruba Contemporary Bible · tap any highlighted word for context

Jeremiah 43 — Scripture text (Biblica® Open Yoruba Contemporary Bible)

Nígbà tí parí sísọ ọ̀rọ̀ tí Olúwa Ọlọ́run rán an sí wọn tan. Asariah ọmọ Hoṣaiah àti ọmọ , àti gbogbo àwọn agbéraga ọkùnrin sọ fún pé, “Ìwọ ń pa irọ́! Olúwa Ọlọ́run wa kò rán ọ láti sọ pé, ‘Ẹ má lọ sí láti ṣàtìpó níbẹ̀.’ Ṣùgbọ́n , ọmọ , ni ó fi ọ̀rọ̀ sí ọ lẹ́nu sí wa, láti fà wá lé àwọn ará lọ́wọ́, láti pa wá àti láti kó wa ní ìgbèkùn lọ sí .” Nítorí náà, Johanani ti àti gbogbo àwọn olórí ogun, àti gbogbo àwọn ènìyàn tàpá sí àṣẹ Olúwa nípa dídúró sí . Dípò bẹ́ẹ̀, Johanani ọmọ àti gbogbo àwọn olórí ogun sì ko àwọn àjẹkù tí wọ́n wá láti gbé ilẹ̀ láti orílẹ̀-èdè gbogbo tí wọ́n ti tú wọn ká. Wọ́n tún kó àwọn ọkùnrin, àwọn obìnrin àti àwọn ọmọdé, àti àwọn ọmọ ọba tí ó jẹ́ obìnrin èyí tí balógun ẹ̀ṣọ́ ti fi sílẹ̀ pẹ̀lú ọmọ , ọmọ Ṣafani, àti wòlíì náà àti ọmọ . Nítorí náà, wọn wọ pẹ̀lú àìgbọ́ràn sí àṣẹ Olúwa, wọ́n sì lọ títí dé . Ní ọ̀rọ̀ Olúwa tọ wá: “Nígbà tí àwọn Júù ń wòye mú àwọn òkúta pẹ̀lú rẹ, kí o sì rì wọ́n mọ́ inú amọ̀ tí ó wà nínú bíríkì tí ó wà níbi pèpéle ẹnu-ọ̀nà ààfin ní . Báyìí kí o sì sọ fún wọn pé, ‘Èyí ni ohun tí Olúwa àwọn ọmọ-ogun, Ọlọ́run ẹli wí. Èmi yóò ránṣẹ́ sí ìránṣẹ́ mi ọba , Èmi yóò gbé ìjọba rẹ̀ ka orí àwọn òkúta; èyí tí mo ti rì sí ibí yìí, yóò tan ìjọba rẹ̀ jù wọ́n lọ. Yóò gbé ogun sí ; yóò mú ikú bá àwọn tí ó yan ikú; ìgbèkùn fún àwọn tí ó ti yan ìgbèkùn, àti idà fún àwọn tí ó yan idà. Yóò dá, iná sun tẹmpili àwọn òrìṣà , yóò sun tẹmpili àwọn òrìṣà , yóò sì mú wọn lọ ìgbèkùn. Gẹ́gẹ́ bí olùṣọ́-àgùntàn, yóò ró aṣọ rẹ̀ mọ́ra, bẹ́ẹ̀ gẹ́gẹ́ ni yóò ró òun yóò sì lọ kúrò níbẹ̀ ní àlàáfíà. Ní tẹmpili ni yóò ti fọ́ ère ilé oòrùn tí ó wà ní ilẹ̀ túútúú, yóò sì sun àwọn tẹmpili àwọn òrìṣà .’ ”

Every verse in Jeremiah 43

Chapter navigation

Biblica® ní oore ọ̀fẹ́ láti lo Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní™ / Biblica® Open Yoruba Contemporary Bible™ Copyright © 2009, 2017 by Biblica, Inc. “Biblica” is a trademark registered in the United States Patent and Trademark Office by Biblica, Inc. Used with permission. Licensed under CC BY-SA 4.0.

0:000:00