Joshua 14:7
“Mo jẹ́ ọmọ ogójì ọdún nígbà tí Mose ìránṣẹ́ Olúwa rán mi láti Kadeṣi-Barnea lọ rin ilẹ̀ náà wò. Mo sì mú ìròyìn wá fún un gẹ́gẹ́ bí o ti dá mi lójú,”
Joshua 14:7 — Biblica® Open Yoruba Contemporary Bible
Verse 7 of 15 in Joshua chapter 14 — Biblica® Open Yoruba Contemporary Bible. Read it in context below, with maps, timelines and thematic connections beside the text.
Joshua 14 — full chapter (Biblica® Open Yoruba Contemporary Bible)
Ìwọ̀nyí ni ilẹ̀ tí àwọn ọmọ ẹli gbà gẹ́gẹ́ bí ogún ní ilẹ̀ , tí àlùfáà, Joṣua ọmọ àti olórí ẹ̀yà àwọn agbo ilé ẹli pín fún wọn. Ìbò ni a fi pín ìní wọn fún àwọn ẹ̀yà mẹ́sàn-án ààbọ̀ gẹ́gẹ́ bí Olúwa ti pàṣẹ láti ọwọ́ . Mose ti fún àwọn ẹ̀yà méjì àti ààbọ̀ ní ogún wọn ní ìlà-oòrùn , ṣùgbọ́n àwọn ọmọ ni kò fi ìní fún ní àárín àwọn tí ó kù. Àwọn ọmọ ẹfu sì di ẹ̀yà méjì, Manase àti . Àwọn ọmọ kò gba ìpín ní ilẹ̀ náà bí kò ṣe àwọn ìlú tí wọn yóò máa gbé, pẹ̀lú pápá oko tútù fún ọ̀wọ́ ẹran àti agbo ẹran wọn. Bẹ́ẹ̀ ni àwọn ará ẹli pín ilẹ̀ náà, gẹ́gẹ́ bí Olúwa ti pàṣẹ fún . Àwọn ọkùnrin wá sí ọ̀dọ̀ Joṣua ní . Kalebu ọmọ ti wí fún un pé, “Ìwọ rántí ohun tí Olúwa sọ fún ènìyàn Ọlọ́run ní ṣi- nípa ìwọ àti èmi. Mo jẹ́ ọmọ ogójì ọdún nígbà tí ìránṣẹ́ Olúwa rán mi láti ṣi- lọ rin ilẹ̀ náà wò. Mo sì mú ìròyìn wá fún un gẹ́gẹ́ bí o ti dá mi lójú, ṣùgbọ́n àwọn arákùnrin mi tí wọ́n bá mi lọ mú àyà àwọn ènìyàn já. Ṣùgbọ́n ní tèmi, èmi fi gbogbo ọkàn tẹ̀lé Olúwa Ọlọ́run mi. Ní ọjọ́ náà, Mose búra fún mi pé, ‘Ilẹ̀ tí ẹsẹ̀ rẹ ti rìn ni yóò jẹ́ ìní rẹ àti ti àwọn ọmọ rẹ láéláé, nítorí pé ìwọ fi tọkàntọkàn wà pẹ̀lú Olúwa Ọlọ́run mi.’ “Ǹjẹ́ nísinsin yìí, kíyèsi i Olúwa dá mi sí gẹ́gẹ́ bí ó ti wí, láti ọdún márùndínláàádọ́ta yìí wá, láti ìgbà tí Olúwa ti sọ ọ̀rọ̀ yìí fún , nígbà tí ẹli ń rìn kiri nínú aginjù, sì kíyèsi i nísinsin yìí, èmi nìyìí lónìí, ọmọ àrùndínláàdọ́rùn-ún ọdún. Síbẹ̀ èmi ní agbára lónìí, bí ìgbà tí rán mi jáde. Èmi sì ní agbára láti jáde fún ogun nísinsin yìí gẹ́gẹ́ bí mo ti wà ní ìgbà náà. Nísinsin yìí fi ìlú orí òkè fún mi èyí tí Olúwa ṣe ìlérí fún mi ní ọjọ́ náà. Ìwọ gbọ́ ní ìgbà náà pé àwọn ọmọ ti wà ní ibẹ̀, àti àwọn ìlú wọn tóbi, pé ó sì ṣe olódi, ṣùgbọ́n bí Olúwa ba fẹ́, èmi yóò lé wọn jáde, gẹ́gẹ́ bí ó ti sọ.” Bẹ́ẹ̀ ni Joṣua súre fun ọmọ ó si fun un ní ni ilẹ̀ ìní. Bẹ́ẹ̀ ni jẹ́ ti ọmọ ará láti ìgbà náà, nítorí tí ó tẹ̀lé Olúwa Ọlọ́run ẹli tọkàntọkàn. (Hebroni a sì máa jẹ́ - ní ẹ̀yìn , èyí tí ó jẹ́ ènìyàn ńlá nínú àwọn ọmọ .) Nígbà náà ni ilẹ̀ náà sinmi ogun.
Every verse in Joshua 14
Chapter navigation
Biblica® ní oore ọ̀fẹ́ láti lo Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní™ / Biblica® Open Yoruba Contemporary Bible™ Copyright © 2009, 2017 by Biblica, Inc. “Biblica” is a trademark registered in the United States Patent and Trademark Office by Biblica, Inc. Used with permission. Licensed under CC BY-SA 4.0.