Joshua 16:9

“Ó tún mú àwọn ìlú àti ìletò wọn tí ó yà sọ́tọ̀ fún àwọn ọmọ Efraimu tí ó wà ní àárín ìní àwọn ọmọ Manase.”

Joshua 16:9 — Biblica® Open Yoruba Contemporary Bible

Verse 9 of 10 in Joshua chapter 16 — Biblica® Open Yoruba Contemporary Bible. Read it in context below, with maps, timelines and thematic connections beside the text.

Joshua 16 — full chapter (Biblica® Open Yoruba Contemporary Bible)

Ìpín ti àwọn ọmọ ẹfu láti lẹ́bàá , ní omi ní ìhà ìlà-oòrùn, àní aginjù, tí ó gòkè láti lọ dé ilẹ̀ òkè . Ó sì tẹ̀síwájú láti (tí í ṣe ) kọjá lọ sí agbègbè àwọn ará ní , Ó sì sọ̀kalẹ̀ lọ sí ìhà ìwọ̀-oòrùn agbègbè àwọn ará , títí dé ilẹ̀ ìsàlẹ̀ -, àní dé , ó sì parí sí etí Òkun. Báyìí ni àti , àwọn ọmọ ẹfu, gba ilẹ̀ ìní wọn. Èyí ni ilẹ̀ , ní agbo ilé agbo ilé. Ààlà ìní wọn lọ láti - ní ìlà-oòrùn lọ sí òkè -. Ó sì lọ títí dé Òkun. Láti ní ìhà àríwá, ó sì yí lọ sí ìhà ìlà-oòrùn lọ sí -Ṣilo, ó sì kọjá ní ẹ̀bá rẹ̀ lọ sí ní ìlà-oòrùn. Láti ó yípo lọ sí gúúsù sí àti , ó sì dé , ó sì pín sí odò . Láti ààlà náà sì lọ sí ìhà ìwọ̀-oòrùn, ní -, ó sì parí ní Òkun. Èyí ni ìní ẹ̀yà àwọn ọmọ , ní agbo ilé agbo ilé. Ó tún mú àwọn ìlú àti ìletò wọn tí ó yà sọ́tọ̀ fún àwọn ọmọ tí ó wà ní àárín ìní àwọn ọmọ . Wọn kò lé àwọn ara tí ń gbé ni kúrò, títí di òní yìí ni àwọn ará ń gbé láàrín àwọn ènìyàn , ṣùgbọ́n wọ́n mú wọ́n sìn.

Every verse in Joshua 16

Chapter navigation

Biblica® ní oore ọ̀fẹ́ láti lo Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní™ / Biblica® Open Yoruba Contemporary Bible™ Copyright © 2009, 2017 by Biblica, Inc. “Biblica” is a trademark registered in the United States Patent and Trademark Office by Biblica, Inc. Used with permission. Licensed under CC BY-SA 4.0.

0:000:00