Joshua 17:1

“Èyí ní ìpín ẹ̀yà Manase tí í ṣe àkọ́bí Josẹfu, fún Makiri, àkọ́bí Manase. Makiri sì ni baba ńlá àwọn ọmọ Gileadi, tí ó ti gba Gileadi àti Baṣani nítorí pé àwọn ọmọ Makiri jẹ́ jagunjagun ńlá.”

Joshua 17:1 — Biblica® Open Yoruba Contemporary Bible

Verse 1 of 18 in Joshua chapter 17 — Biblica® Open Yoruba Contemporary Bible. Read it in context below, with maps, timelines and thematic connections beside the text.

Joshua 17 — full chapter (Biblica® Open Yoruba Contemporary Bible)

Èyí ní ìpín ẹ̀yà tí í ṣe àkọ́bí ẹfu, fún , àkọ́bí . Makiri sì ni baba ńlá àwọn ọmọ , tí ó ti gba àti Baṣani nítorí pé àwọn ọmọ jẹ́ jagunjagun ńlá. Nítorí náà ìpín yìí wà fún ìyókù àwọn ènìyàn : ní agbo ilé , Heleki, Asrieli, Ṣekemu, Heferi àti Ṣemida. Ìwọ̀nyí ní àwọn ọmọ ọkùnrin ọmọ ẹfu ní agbo ilé wọn. Nísinsin yìí ọmọ , ọmọ , ọmọ , ọmọ , kò ní ọmọkùnrin, bí kò ṣe àwọn ọmọbìnrin, tí orúkọ wọn jẹ́: Mahila, Noa, Hogla, Milka àti . Wọ́n sì lọ bá àlùfáà, Joṣua ọmọ , àti àwọn olórí wí pé, “Olúwa pàṣẹ fún láti fún wa ní ìní ní àárín àwọn arákùnrin wa.” Bẹ́ẹ̀ ni Joṣua fún wọn ní ìní pẹ̀lú àwọn arákùnrin baba wọn, gẹ́gẹ́ bí àṣẹ Olúwa. Ìpín ilẹ̀ sì jẹ́ ìsọ̀rí mẹ́wàá ní ẹ̀bá àti Baṣani ìlà-oòrùn , nítorí tí àwọn ọmọbìnrin ẹ̀yà gba ìní ní àárín àwọn ọmọkùnrin. Ilẹ̀ sì jẹ́ ti ìyókù àwọn ọmọ . Agbègbè sì fẹ̀ láti Aṣeri títí dé ní ìlà-oòrùn Ṣekemu. Ààlà rẹ̀ sì lọ sí ìhà gúúsù títí tó fi dé ibi tí àwọn ènìyàn ń gbé ní , (Manase lo ni ilẹ̀ , ṣùgbọ́n fúnra rẹ̀ to wà ni ààlà ilẹ̀ jẹ ti àwọn ará .) Ààlà rẹ̀ sì sọ̀kalẹ̀ lọ odò , ní ìhà gúúsù odò náà. Àwọn ìlú tí ó jẹ́ ti wà ní àárín àwọn ìlú , ṣùgbọ́n ààlà ni ìhà àríwá odò náà, ó sì yọ sí Òkun. Ìhà gúúsù ilẹ̀ náà jẹ́ ti , ṣùgbọ́n ìhà àríwá jẹ́ ti . Ilẹ̀ dé Òkun, Aṣeri sì jẹ́ ààlà rẹ̀ ní àríwá, nígbà tí jẹ́ ààlà ti ìlà-oòrùn. Ní àárín àti Aṣeri, Manase tún ni -Ṣeani, Ibleamu àti àwọn ènìyàn , Endori, Taanaki àti pẹ̀lú àwọn abúlé tí ó yí wọn ká (ẹ̀kẹ́ta nínú orúkọ wọn ní ). Síbẹ̀, àwọn ọmọ kò lè gba àwọn ìlú wọ̀nyí, nítorí àwọn ará ti pinnu láti gbé ní ilẹ̀ náà. Ṣùgbọ́n nígbà tí àwọn ará ẹli di alágbára, wọ́n mú àwọn ọmọ sìn, ṣùgbọ́n wọn kò lé wọn jáde pátápátá. Àwọn ọmọ ẹfu sì wí fún Joṣua pé, “Èéṣe tí ìwọ fi fún wa ní ìpín ilẹ̀ kan àti ìdákan ní ìní? Nítorí àwa jẹ́ ọ̀pọ̀ ènìyàn tí Olúwa ti bùkún lọ́pọ̀lọ́pọ̀.” Joṣua dá wọn lóhùn pé, “Bí ẹ bá pọ̀ bẹ́ẹ̀, tí òkè ìlú bá kéré fún yin, ẹ gòkè lọ sí igbó kí ẹ sì ṣán ilẹ̀ òkè fún ara yín ní ibẹ̀ ní ilẹ̀ àwọn ará àti ará .” Àwọn ènìyàn ẹfu dáhùn pé, “Òkè kò tó fún wa, bẹ́ẹ̀ ni gbogbo àwọn ará tí ó gbé ní pẹ̀tẹ́lẹ̀, àti gbogbo àwọn tí ń bẹ ní -Ṣeani àti àwọn ìletò àti àwọn tí ń gbé ní àfonífojì ní kẹ̀kẹ́ ogun írin.” Ṣùgbọ́n Joṣua sọ fún àwọn ilé ẹfu: fún àti pé, “Lóòtítọ́ ni ẹ pọ̀ lọ́pọ̀lọ́pọ̀, ẹ sì jẹ́ alágbára. Ẹ̀yin kí yóò sì ní ìpín kan ṣoṣo. Ṣùgbọ́n ilẹ̀ orí òkè igbó jẹ́ tiyín pẹ̀lú. Ẹ ṣán ilẹ̀ náà, òpin rẹ̀ yóò jẹ́ tiyín pátápátá. Bí ó tilẹ̀ jẹ́ pé àwọn ará ní kẹ̀kẹ́ ogun irin, tí ó sì jẹ́ pé wọ́n ní agbára, síbẹ̀ ẹ lè lé wọn jáde.”

Every verse in Joshua 17

Chapter navigation

Biblica® ní oore ọ̀fẹ́ láti lo Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní™ / Biblica® Open Yoruba Contemporary Bible™ Copyright © 2009, 2017 by Biblica, Inc. “Biblica” is a trademark registered in the United States Patent and Trademark Office by Biblica, Inc. Used with permission. Licensed under CC BY-SA 4.0.

0:000:00