Joshua 19:46

“Me Jakoni àti Rakkoni, pẹ̀lú ilẹ̀ tí ó kọjú sí Joppa.”

Joshua 19:46 — Biblica® Open Yoruba Contemporary Bible

Verse 46 of 51 in Joshua chapter 19 — Biblica® Open Yoruba Contemporary Bible. Read it in context below, with maps, timelines and thematic connections beside the text.

Joshua 19 — full chapter (Biblica® Open Yoruba Contemporary Bible)

Kèké kejì jáde fún ẹ̀yà , ní agbo ilé, ní agbo ilé. Ìní wọn sì wà ní àárín ilẹ̀ . Lára ìpín wọn ní: Beerṣeba (tàbí Ṣeba), Molada, Hasari-Ṣuali, Bala, Esemu, Eltoladi, Betuli, Horma, Siklagi, Beti-, Hasari , Beti- àti Ṣarueli, ìlú wọn jẹ́ mẹ́tàlá àti ìletò wọn. Aini, Rimoni, Eteri àti Aṣani, ìlú wọn jẹ́ mẹ́rin àti ìletò wọn, àti gbogbo àwọn agbègbè ìlú wọ̀nyí títí dé - ( ní gúúsù). Èyí ni ilẹ̀ ìní ẹ̀yà àwọn ọmọ , agbo ilé, ní agbo ilé. A mú ogún ìní àwọn ọmọ láti ìpín , nítorí ìpín pọ̀ ju èyí tí wọ́n nílò lọ. Báyìí ni àwọn ọmọ gba ìní wọn ní àárín ilẹ̀ . Kèké kẹta jáde fún , ní agbo ilé ní agbo ilé ààlà ìní wọn sì lọ títí dé . Ó sì lọ sí ìwọ̀-oòrùn ní , ó sì dé ṣeti, ó sì lọ títí dé odo ní ẹ̀bá . Ó sì yípadà sí ìlà-oòrùn láti sí ìhà ìlà-oòrùn dé ilẹ̀ -, ó sì lọ sí , ó sì gòkè lọ sí . Nígbà náà ní o lọ sí ìhà ìlà-oòrùn lọ sí - àti -Kaṣini, ó sì jáde ní , ó sì yí sí ìhà . Ní ibẹ̀, ààlà sì yíká ní ìhà àríwá lọ sí ó sì pín ní àfonífojì -. Lára wọn ni , Nahalali, Ṣimroni, Idala àti Bẹtilẹhẹmu. Wọ́n sì jẹ́ ìlú méjìlá àti ìletò wọn. Ìlú wọ̀nyí àti ìletò wọn jẹ́ ìní , ní agbo ilé agbo ilé. Kèké kẹrin jáde fún , agbo ilé ní agbo ilé. Lára ilẹ̀ wọn ni èyí: Jesreeli, Kesuloti, Ṣunemu, Hafraimu, Ṣihoni, Anaharati, Rabiti, Kiṣioni, Ebesi, Remeti, Eni-, Eni- àti -. Ààlà náà sì dé , Ṣahasuma, àti -Ṣemeṣi, ó sì pin ní . Wọ́n sì jẹ́ ìlú mẹ́rìndínlógún àti ìletò wọn. Ìlú wọ̀nyí àti ìletò wọn jẹ́ ìní ẹ̀yà , ní agbo ilé agbo ilé. Kèké karùn-ún jáde fún ẹ̀yà Aṣeri, ní agbo ilé agbo ilé. Lára ilẹ̀ wọn ni èyí: Helikati, Hali, Beteni, Akṣafu, Allameleki, Amadi, àti Miṣali. Ní ìhà ìwọ̀-oòrùn ààlà náà dé àti Ṣihori-. Nígbà náà ni o yí sí ìhà ìlà-oòrùn -, dé àti àfonífojì -, ó sì lọ sí àríwá sí - àti , ó sì kọjá lọ sí ní apá òsì. Ó sì lọ sí , Rehobu, Hammoni àti títí dé ńlá. Ààlà náà sì tẹ̀ sí ìhà , ó sì lọ sí ìlú olódi , ó sì yà sí , ó sì jáde ní Òkun Ńlá ní ilẹ̀ , Uma, Afeki àti . Wọ́n sì jẹ́ ìlú méjìlélógún àti ìletò wọn. Àwọn ìlú wọ̀nyí àti ìletò wọn ní ìní ẹ̀yà Aṣeri, ní agbo ilé agbo ilé. Ìpín kẹfà jáde fún , agbo ilé ní agbo ilé, ààlà wọn lọ láti àti igi ńlá ní nímù; kọjá lọ sí àti dé , ó sì pín ní . Ààlà náà gba ìhà ìwọ̀-oòrùn lọ sí - ó sì jáde ní . Ó sì dé , ní ìhà gúúsù Aṣeri ní ìhà ìwọ̀-oòrùn àti ní ní ìhà ìlà-oòrùn. Àwọn ìlú olódi sì , Seri, Hamati, Rakàti, Kinnereti, Adama, Rama , Kedeṣi, Edrei, Eni-Aṣọri, Ironi, Migdali-, Horemu, Beti- àti -Ṣemeṣi. Wọ́n sì jẹ́ ìlú mọ́kàndínlógún àti ìletò wọn. Àwọn ìlú wọ̀nyí àti ìletò wọn ní ìní ẹ̀yà , ní agbo ilé sí agbo ilé. Ìbò kéje jáde fún ẹ̀yà , ní agbo ilé ní agbo ilé. Ilẹ̀ ìní wọn nìwọ̀nyí: Sora, Eṣtaoli, Iri-Ṣemesi, Ṣaalabini, Aijaloni, Itila, Eloni, Timna, Ekroni, Elteke, Gibetoni, Baalati, Jehudu, Bene-, Gati-, Me àti , pẹ̀lú ilẹ̀ tí ó kọjú sí . (Ṣùgbọ́n àwọn ará ní ìṣòro láti gba ilẹ̀ ìní wọn, bẹ́ẹ̀ ni wọ́n gòkè lọ, wọ́n sì kọlu Leṣemu, wọ́n sì gbà á, wọ́n sì fi idà kọlù ú, wọ́n sì ń gbé ibẹ̀. Wọ́n sì ń gbé ní Leṣemu, wọ́n sì pe orúkọ rẹ̀ ní orúkọ baba ńlá wọn). Àwọn ìlú wọ́n yí àti ìletò wọn ní ìní ẹ̀yà , ní agbo ilé agbo ilé. Nígbà tí wọ́n ti parí pínpín ilẹ̀ náà ní ìpín ti olúkúlùkù, àwọn ará ẹli fún Joṣua ọmọ ní ìní ní àárín wọn, bí Olúwa ti pàṣẹ, wọ́n fún un ni ìlú tí ó béèrè fún, Timnati ní ìlú òkè . Ó sì kọ́ ìlú náà, ó sì ń gbé ibẹ̀. Wọ̀nyí ni àwọn ilẹ̀ tí àlùfáà, Joṣua ọmọ àti àwọn olórí ẹ̀yà agbo ilé ẹli fi ìbò pín ní Ṣilo ní iwájú Olúwa ní ẹnu-ọ̀nà àgọ́ ìpàdé. Báyìí ni wọ́n parí pínpín ilẹ̀ náà.

Every verse in Joshua 19

Chapter navigation

Biblica® ní oore ọ̀fẹ́ láti lo Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní™ / Biblica® Open Yoruba Contemporary Bible™ Copyright © 2009, 2017 by Biblica, Inc. “Biblica” is a trademark registered in the United States Patent and Trademark Office by Biblica, Inc. Used with permission. Licensed under CC BY-SA 4.0.

0:000:00