Judges

Judges 1

Biblica® Open Yoruba Contemporary Bible · tap any highlighted word for context

Judges 1 — Scripture text (Biblica® Open Yoruba Contemporary Bible)

Lẹ́yìn ikú Joṣua, ni orílẹ̀-èdè ẹli béèrè lọ́wọ́ Olúwa pé, “Èwo nínú ẹ̀yà wa ni yóò kọ́kọ́ gòkè lọ bá àwọn ará jagun fún wa?” Olúwa sì dáhùn pé, “Juda ni yóò lọ; nítorí pé èmi ti fi ilẹ̀ náà lé e lọ́wọ́.” Nígbà náà ni àwọn olórí ẹ̀yà béèrè ìrànlọ́wọ́ láti ọ̀dọ̀ àwọn ọmọ arákùnrin wọn pé, “Ẹ wá bá wa gòkè lọ sí ilẹ̀ tí a ti fi fún wa, láti bá àwọn ará jà kí a sì lé wọn kúrò, àwa pẹ̀lú yóò sì bá a yín lọ sí ilẹ̀ tiyín bákan náà láti ràn yín lọ́wọ́.” Àwọn ọmọ-ogun sì bá àwọn ọmọ-ogun lọ. Nígbà tí àwọn ọmọ-ogun sì kọlu wọ́n, Olúwa sì fi àwọn ará àti àwọn ará lé wọn lọ́wọ́, wọ́n sì pa ẹgbẹ̀rún mẹ́wàá (10,000) ọkùnrin ní . Ní ni wọ́n ti rí -, wọ́n sì bá a jagun, wọ́n sì ṣẹ́gun àwọn ará àti . Ọba - sá àsálà, ṣùgbọ́n ogun ẹli lépa rẹ̀ wọ́n sì bá a, wọ́n sì gé àwọn àtàǹpàkò ọwọ́ àti ẹsẹ̀ rẹ̀. Nígbà náà ni - wí pé, “Àádọ́rin ọba ni èmi ti gé àtàǹpàkò wọn tí wọ́n sì ń ṣa èérún oúnjẹ jẹ lábẹ́ tábìlì mi. Báyìí Ọlọ́run ti san án fún mi gẹ́gẹ́ bí ohun tí mo ṣe sí wọn.” Wọ́n sì mú un wá sí ẹmu, ó sì kú síbẹ̀. Àwọn ológun sì ṣẹ́gun ẹmu, wọ́n sì kó o, wọ́n sì fi ojú idà kọlù ú, wọ́n sì dáná sun ìlú náà. Lẹ́yìn nǹkan wọ̀nyí ni àwọn ogun sọ̀kalẹ̀ lọ láti bá àwọn ará tí ń gbé ní àwọn ìlú orí òkè ní gúúsù àti ní pẹ̀tẹ́lẹ̀ òkè lápá ìwọ̀-oòrùn jagun. Ogun sì tún ṣígun tọ ará tí ń gbé (tí orúkọ rẹ̀ ń jẹ́ -) ó sì ṣẹ́gun Ṣeṣ, Ahimani àti . Láti ibẹ̀, wọ́n sì wọ́de ogun láti ibẹ̀ lọ bá àwọn ènìyàn tí ń gbé ní (tí à ń pè ní - nígbà kan rí). Kalebu sì wí pé, “Èmi yóò fi ọmọbìnrin mi fún ọkùnrin tí ó bá kọlu -, tí ó sì gbà á ní ìgbéyàwó.” Otnieli ọmọ , àbúrò sì gbà á, báyìí ni sì fi ọmọbìnrin rẹ̀ fún un ní ìyàwó. Ní ọjọ́ kan, nígbà tí lọ sí ọ̀dọ̀ , ó rọ̀ ọ́ kí ó béèrè ilẹ̀ oko lọ́wọ́ baba rẹ̀. Nígbà náà ni sọ̀kalẹ̀ ní orí kẹ́tẹ́kẹ́tẹ́ rẹ̀, Kalebu sì béèrè pé, “Kí ni kí èmi ṣe fún ọ?” Aksa sì dáhùn pé, “Mo ń fẹ́ kí o ṣe ojúrere kan fún mi, nígbà ti o ti fún mi ní ilẹ̀ ní gúúsù, fún mi ní ìsun omi náà pẹ̀lú.” sì fún un ní ìsun òkè àti ìsun ìsàlẹ̀. Àwọn ìran tí wọ́n jẹ́ àna bá àwọn ọmọ gòkè láti ìlú ọ̀pẹ lọ sí aginjù ní gúúsù ; wọ́n sì lọ, orílẹ̀-èdè méjèèjì sì jùmọ̀ ń gbé pọ̀ láti ìgbà náà. Ó sì ṣe, àwọn ológun tẹ̀lé àwọn ológun arákùnrin wọn, wọ́n sì lọ bá àwọn ará tí ń gbé jagun, wọ́n sì run ìlú náà pátápátá, ní báyìí àwa yóò pe ìlú náà ní ( èyí tí ń jẹ́ ìparun). Àwọn ogun sì ṣẹ́gun àti àwọn agbègbè rẹ̀, Aṣkeloni àti pẹ̀lú àwọn ìlú tí ó yí ọ̀kọ̀ọ̀kan wọn ká. Olúwa sì wà pẹ̀lú ẹ̀yà , wọ́n gba ilẹ̀ òkè, ṣùgbọ́n wọn kò le lé àwọn ènìyàn tí ó wà ní pẹ̀tẹ́lẹ̀, nítorí wọ́n ní kẹ̀kẹ́ ogun írin. Gẹ́gẹ́ bí ti ṣèlérí, wọ́n fún ní , ó sì lé àwọn tí ń gbé ibẹ̀ kúrò; àwọn náà ni ìran àwọn ọmọ mẹ́ta. Àwọn ẹ̀yà ni wọn kò le lé àwọn tí wọ́n ń gbé ẹmu, nítorí náà wọ́n ń gbé àárín àwọn ẹli títí di òní. Àwọn ẹ̀yà ẹfu sì bá jagun, Olúwa síwájú pẹ̀lú wọn. Nígbà tí ẹ̀yà ẹfu rán àwọn ènìyàn láti lọ yọ́ wò (orúkọ ìlú náà tẹ́lẹ̀ rí ni ). Àwọn ayọ́lẹ̀wò náà rí ọkùnrin kan tí ń jáde láti inú ìlú náà wá, wọ́n sì wí fún un pé, “Fi ọ̀nà àtiwọ ìlú yìí hàn wá, àwa ó sì dá ẹ̀mí rẹ sí, a ó sì ṣe àánú fún ọ.” Ó sì fi ọ̀nà ìlú náà hàn wọ́n, wọ́n sì fi ojú idà kọlu ìlú náà, ṣùgbọ́n wọ́n dá ọkùnrin náà àti gbogbo ìdílé rẹ̀ si. Ọkùnrin náà sí lọ sí ilẹ̀ àwọn ará , ó sì tẹ ìlú kan dó, ó sì pe orúkọ rẹ̀ ní , èyí sì ni orúkọ rẹ̀ títí di òní. Ṣùgbọ́n kò lé àwọn ará -Ṣeani àti ìlú rẹ̀ wọ̀n-ọn-nì jáde, tàbí àwọn ará àti àwọn ìgbèríko rẹ̀, tàbí àwọn ará àti àwọn ìgbèríko rẹ̀, tàbí àwọn ará àti àwọn ìgbèríko rẹ̀, tàbí àwọn ará àti àwọn ìgbèríko tí ó yí i ká, torí pé àwọn ará ti pinnu láti máa gbé ìlú náà. Nígbà tí àwọn ọmọ ẹli di alágbára, wọ́n mú àwọn ará sìn bí i ẹrú, ṣùgbọ́n wọn kò fi agbára lé wọn jáde kúrò ní ilẹ̀ náà. Efraimu náà kò lé àwọn ará tí ó ń gbé jáde, ṣùgbọ́n àwọn ará sì ń gbé láàrín àwọn ẹ̀yà . Bẹ́ẹ̀ ni àwọn kò lé àwọn ará tí ń gbé jáde tàbí àwọn ará , ṣùgbọ́n wọ́n sọ wọ́n di ẹrú. Wọ́n sì ń sin àwọn ará . Bẹ́ẹ̀ ni Aṣeri kò lé àwọn tí ń gbé ní tàbí ní tàbí ní tàbí ní tàbí ní tàbí ní tàbí ní . Ṣùgbọ́n nítorí àwọn ará Aṣeri ń gbé láàrín àwọn ará tí wọ́n ni ilẹ̀ náà. Àwọn ẹ̀yà pẹ̀lú kò lé àwọn ará -Ṣemeṣi àti - jáde; ṣùgbọ́n àwọn ẹ̀yà náà ń gbé àárín àwọn ará tí ó ti ní ilẹ̀ náà rí, ṣùgbọ́n àwọn tí ń gbé -Ṣemeṣi àti - ń sìn ìsìn tipátipá. Àwọn ará fi agbára dá àwọn ẹ̀yà dúró sí àwọn ìlú orí òkè, wọn kò sì jẹ́ kí wọn sọ̀kalẹ̀ wá sí pẹ̀tẹ́lẹ̀. Àwọn ará ti pinnu láti dúró lórí òkè àti òkè àti ti Ṣaalbimu, ṣùgbọ́n nígbà tí ẹ̀yà ẹfu di alágbára wọ́n borí wọ́n sì mú wọn sìn. Ààlà àwọn ará sì bẹ̀rẹ̀ láti ìgòkè kọjá lọ sí àti síwájú sí i.

Every verse in Judges 1

Chapter navigation

Biblica® ní oore ọ̀fẹ́ láti lo Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní™ / Biblica® Open Yoruba Contemporary Bible™ Copyright © 2009, 2017 by Biblica, Inc. “Biblica” is a trademark registered in the United States Patent and Trademark Office by Biblica, Inc. Used with permission. Licensed under CC BY-SA 4.0.

0:000:00