Judges

Judges 12

Biblica® Open Yoruba Contemporary Bible · tap any highlighted word for context

Judges 12 — Scripture text (Biblica® Open Yoruba Contemporary Bible)

Àwọn ọkùnrin pe àwọn ológun wọn jáde, wọ́n sì rékọjá sí ìhà àríwá, wọ́n sì bi pé, “Èéṣe tí o fi lọ bá àwọn ará jagun láì ké sí wa láti bá ọ lọ? Àwa yóò sun ilé rẹ mọ́ ọ lórí.” Jefta dáhùn pé, “Èmi àti àwọn ènìyàn ní ìyọnu ńlá pẹ̀lú àwọn ará , bí ó tilẹ̀ jẹ́ pé mo pè yín, ẹ̀yin kò gbà mí sílẹ̀ ní ọwọ́ wọn. Nígbà tí mo rí i pé ẹ̀yin kò gbà mí, mo fi ẹ̀mí mi wéwu. Mó sì gòkè lọ láti bá àwọn ará jà, Olúwa sì fún mi ní ìṣẹ́gun lórí wọn, èéṣe báyìí tí ẹ fi dìde wá lónìí láti bá mi jà?” Nígbà náà ni kó gbogbo ọkùnrin jọ, ó sì bá jà. Àwọn ọkùnrin sì kọlù , nítorí wọ́n ti sọtẹ́lẹ̀ pé, “Ẹ̀yin ará jẹ́ àsáwọ̀ àwọn ará àti ti .” Àwọn ará gba à bá wọ odò tí wọ́n máa gbà lọ sí , nígbàkígbà tí àwọn ará bá wí pé, “Jẹ́ kí ń sálọ sí òkè,” lọ́hùn ún àwọn ará yóò bi í pé, “Ṣé ará ni ìwọ ń ṣe?” Tí ó bá wí pé, “Bẹ́ẹ̀ kọ́,” wọ́n ó wí fún un pé, “Ó dá à wí pé ‘Ṣibolẹti.’ ” Tí ó bá ní, “Sibolẹti,” torí pé kò ní mọ̀ ọ́n pé dáradára, wọ́n á mú un wọn, a sì pa á ni à bá wọ odò . Àwọn ará tí wọn pa ní àkókò yìí jẹ́ ẹgbẹ̀rún méjìlélógójì (42,000) ọkùnrin. Jefta ṣe ìdájọ́ ẹli ní ọdún mẹ́fà. Lẹ́yìn náà ará kú, wọ́n sì sin ín sí ọ̀kan nínú àwọn ìlú . Lẹ́yìn , Ibsani ará Bẹtilẹhẹmu ṣe ìdájọ́ àwọn ọmọ ẹli. Ó ní ọgbọ̀n ọmọkùnrin àti ọgbọ̀n ọmọbìnrin fún àwọn tí kì í ṣe ẹ̀yà rẹ̀ gẹ́gẹ́ bí ìyàwó, ó sì fẹ́ ọgbọ̀n àwọn ọmọbìnrin fún àwọn ọmọ rẹ̀ ọkùnrin lára àwọn tí kì í ṣe ẹ̀yà rẹ̀. Ibsani ṣe ìdájọ́ ẹli fún ọdún méje. Lẹ́yìn náà ni kú, wọ́n sì sin ín sí Bẹtilẹhẹmu. Lẹ́yìn rẹ̀, Eloni ti ẹ̀yà ṣe àkóso ẹli fún ọdún mẹ́wàá. Eloni sì kú, wọ́n sì sin ín sí ní ilẹ̀ . Lẹ́yìn rẹ̀ ni ọmọ tí n ṣe àkóso ẹli. Òun ní ogójì ọmọkùnrin àti ọgbọ̀n ọmọ ọmọ àwọn tí ó ń gun àádọ́rin kẹ́tẹ́kẹ́tẹ́. Ó ṣe ìdájọ́ ẹli ní ọdún mẹ́jọ. Abdoni ọmọ sì kú, wọ́n sin ín sí ní ilé ní ìlú òkè àwọn ará .

Every verse in Judges 12

Chapter navigation

Biblica® ní oore ọ̀fẹ́ láti lo Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní™ / Biblica® Open Yoruba Contemporary Bible™ Copyright © 2009, 2017 by Biblica, Inc. “Biblica” is a trademark registered in the United States Patent and Trademark Office by Biblica, Inc. Used with permission. Licensed under CC BY-SA 4.0.

0:000:00