Saamu

Saamu 133

Psalm 133 in Yoruba and English (KJV) · Orin Dafidi 133Tap any highlighted word for context

About this Psalm

The Psalm heading names David as its author. This is a song of ascents that celebrates the goodness of God's people dwelling together in unity.

Saamu 133 — Scripture text (Biblica® Open Yoruba Contemporary Bible)

Kíyèsi, ó ti dára ó sì ti dùn tó fún àwọn ará láti máa jùmọ̀ gbé ní ìrẹ́pọ̀.

KJV verse 1: Behold, how good and how pleasant it is for brethren to dwell together in unity!

Ó dàbí òróró ìkunra iyebíye ní orí, tí ó sàn dé irùngbọ̀n, àní irùngbọ̀n : tí ó sì sàn sí etí aṣọ sórí rẹ̀.

KJV verse 2: It is like the precious ointment upon the head, that ran down upon the beard, even Aaron’s beard: that went down to the skirts of his garments;

Bí ìrì tí o sàn sórí òkè . Nítorí níbẹ̀ ní Olúwa gbé pàṣẹ ìbùkún, àní ìyè láéláé.

KJV verse 3: As the dew of Hermon, and as the dew that descended upon the mountains of Zion: for there the LORD commanded the blessing, even life for evermore.

Every verse in Saamu 133

Chapter navigation

Biblica® ní oore ọ̀fẹ́ láti lo Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní™ / Biblica® Open Yoruba Contemporary Bible™ Copyright © 2009, 2017 by Biblica, Inc. “Biblica” is a trademark registered in the United States Patent and Trademark Office by Biblica, Inc. Used with permission. Licensed under CC BY-SA 4.0.

KJV: public domain

Most-read Psalms in Yoruba

Saamu 1330:00 / 0:00