Saamu

Saamu 68

Psalm 68 in Yoruba and English (KJV) · Orin Dafidi 68Tap any highlighted word for context

About this Psalm

The Psalm heading names David as its author. This is a praise Psalm that celebrates God's triumphant rule and care for the fatherless and prisoners.

Saamu 68 — Scripture text (Biblica® Open Yoruba Contemporary Bible)

Kí Ọlọ́run kí ó dìde, kí àwọn ọ̀tá rẹ̀ kí ó fọ́nká; kí àwọn ọ̀tá rẹ̀ kí ó sá níwájú rẹ̀.

KJV verse 1: Let God arise, let his enemies be scattered: let them also that hate him flee before him.

Bí ìjì ti ń fẹ́ èéfín lọ, kí ó fẹ́ wọn lọ; bí ìda ti í yọ́ níwájú iná, kí olùṣe búburú ṣègbé níwájú Ọlọ́run.

KJV verse 2: As smoke is driven away, so drive them away: as wax melteth before the fire, so let the wicked perish at the presence of God.

Ṣùgbọ́n kí inú olódodo kí ó dùn kí ó sì kún fún ayọ̀ níwájú Ọlọ́run; kí inú wọn kí ó dùn, kí ó sì kún fún ayọ̀.

KJV verse 3: But let the righteous be glad; let them rejoice before God: yea, let them exceedingly rejoice.

Ẹ kọrin sí Ọlọ́run, ẹ kọrin ìyìn sí i, ẹ la ọ̀nà fún ẹni tí ń rékọjá ní aginjù. Olúwa ni orúkọ rẹ̀, kí ẹ sì máa yọ̀ níwájú rẹ̀.

KJV verse 4: Sing unto God, sing praises to his name: extol him that rideth upon the heavens by his name JAH, and rejoice before him.

Baba àwọn aláìní baba àti ídàájọ́ àwọn opó ni Ọlọ́run ní ibùgbé rẹ̀ mímọ́

KJV verse 5: A father of the fatherless, and a judge of the widows, is God in his holy habitation.

Ọlọ́run gbé aláìlera kalẹ̀ nínú ìdílé, ó darí àwọn ẹlẹ́wọ̀n pẹ̀lú orin, ṣùgbọ́n àwọn ọlọ́tẹ̀ ní ń gbé nínú ilẹ̀ gbígbẹ.

KJV verse 6: God setteth the solitary in families: he bringeth out those which are bound with chains: but the rebellious dwell in a dry land.

Nígbà tí ìwọ bá jáde lónìí níwájú àwọn ènìyàn rẹ, Ọlọ́run, tí ń kọjá lọ láàrín aginjù, .

KJV verse 7: O God, when thou wentest forth before thy people, when thou didst march through the wilderness; Selah:

Ilẹ̀ mì títí, àwọn ọ̀run ń rọ òjò jáde, níwájú Ọlọ́run, ẹni , níwájú Ọlọ́run, Ọlọ́run ẹli.

KJV verse 8: The earth shook, the heavens also dropped at the presence of God: even Sinai itself was moved at the presence of God, the God of Israel.

Ìwọ fún wa ní ọ̀pọ̀lọpọ̀ òjò, Ọlọ́run; ìwọ tu ilẹ̀ ìní rẹ̀ lára nígbà tí ó rẹ̀ ẹ́ tan.

KJV verse 9: Thou, O God, didst send a plentiful rain, whereby thou didst confirm thine inheritance, when it was weary.

Àwọn ènìyàn rẹ tẹ̀dó síbẹ̀ nínú ọ̀pọ̀lọpọ̀ ìní rẹ, Ọlọ́run, ìwọ pèsè fún àwọn aláìní.

KJV verse 10: Thy congregation hath dwelt therein: thou, O God, hast prepared of thy goodness for the poor.

Olúwa ti pàṣẹ ọ̀rọ̀, púpọ̀ ní ogun àwọn ẹni tí ó ń ròyìn rẹ̀.

KJV verse 11: The Lord gave the word: great was the company of those that published it.

“Àwọn ọba àti àwọn ológun yára sálọ; obìnrin tí ó sì jókòó ni ilé ní ń pín ìkógun náà.

KJV verse 12: Kings of armies did flee apace: and she that tarried at home divided the spoil.

Nígbà tí ẹ̀yin dùbúlẹ̀ láàrín agbo ẹran, nígbà náà ni ẹ̀yin ó dàbí ìyẹ́ àdàbà ti a bò ní fàdákà, àti ìyẹ́ rẹ̀ pẹ̀lú wúrà pupa.”

KJV verse 13: Though ye have lien among the pots, yet shall ye be as the wings of a dove covered with silver, and her feathers with yellow gold.

Nígbà tí Olódùmarè fọ́n àwọn ọba ká ní ilẹ̀ náà, ó dàbí òjò dídi ní .

KJV verse 14: When the Almighty scattered kings in it, it was white as snow in Salmon.

Òkè Baṣani jẹ́ òkè Ọlọ́run; òkè tí ó ní orí púpọ̀ ni òkè Baṣani.

KJV verse 15: The hill of God is as the hill of Bashan; an high hill as the hill of Bashan.

Kí ló dé tí ẹ̀yin fi ń ṣe ìlara, ẹ̀yin òkè wúwo, òkè tí Ọlọ́run ti fẹ́ láti jẹ ọba níbi tí Olúwa fúnra rẹ̀ yóò máa gbé títí láé?

KJV verse 16: Why leap ye, ye high hills? this is the hill which God desireth to dwell in; yea, the LORD will dwell in it for ever.

Ẹgbẹ̀rún mẹ́wàá ni kẹ̀kẹ́ ogun Ọlọ́run ẹgbẹ̀rún lọ́nà ẹgbẹ̀rún; Olúwa ń bẹ láàrín wọn, ní ni ibi mímọ́ rẹ̀.

KJV verse 17: The chariots of God are twenty thousand, even thousands of angels: the Lord is among them, as in Sinai, in the holy place.

Ìwọ ti gòkè sí ibi gíga ìwọ ti di ìgbèkùn ní ìgbèkùn lọ; ìwọ ti gba ẹ̀bùn fún ènìyàn: nítòótọ́, fún àwọn ọlọ̀tẹ̀ pẹ̀lú, kí Olúwa Ọlọ́run lè máa bá wọn gbé.

KJV verse 18: Thou hast ascended on high, thou hast led captivity captive: thou hast received gifts for men; yea, for the rebellious also, that the LORD God might dwell among them.

Olùbùkún ni Olúwa, Ọlọ́run Olùgbàlà wa, ẹni tí ó ń fi ojoojúmọ́ gba ẹrù wa rù. .

KJV verse 19: Blessed be the Lord, who daily loadeth us with benefits, even the God of our salvation. Selah.

Ọlọ́run wa jẹ́ Ọlọ́run tó ń gbàlà àti sí Olúwa Olódùmarè ni ó ń gbà wá lọ́wọ́ ikú.

KJV verse 20: He that is our God is the God of salvation; and unto God the Lord belong the issues from death.

Ṣùgbọ́n Ọlọ́run yóò tẹ orí àwọn ọ̀tá rẹ̀, àti agbárí írun àwọn tó ń tẹ̀síwájú nínú ẹ̀ṣẹ̀ wọn

KJV verse 21: But God shall wound the head of his enemies, and the hairy scalp of such an one as goeth on still in his trespasses.

Olúwa wí pé, “Èmi ó mú wọn wá láti Baṣani; èmi ó mú wọn wá láti ibú omi Òkun,

KJV verse 22: The Lord said, I will bring again from Bashan, I will bring my people again from the depths of the sea:

kí ẹsẹ̀ rẹ kí ó le pọ́n ní inú ẹ̀jẹ̀ àwọn ọ̀tá rẹ, àti ahọ́n àwọn ajá rẹ ní ìpín tiwọn lára àwọn ọ̀tá rẹ.”

KJV verse 23: That thy foot may be dipped in the blood of thine enemies, and the tongue of thy dogs in the same.

Wọ́n ti rí ìrìn rẹ, Ọlọ́run, ìrìn Ọlọ́run mi àti ọba mi ní ibi mímọ́ rẹ̀.

KJV verse 24: They have seen thy goings, O God; even the goings of my God, my King, in the sanctuary.

Àwọn akọrin wà ní iwájú, àwọn olórin wà lẹ́yìn; àwọn ọmọbìnrin tí ń lu ṣaworo sì wà pẹ̀lú wọn.

KJV verse 25: The singers went before, the players on instruments followed after; among them were the damsels playing with timbrels.

Ẹ fi ìyìn fún Olúwa ní ẹgbẹgbẹ́; àní fún Olúwa ẹ̀yin tí ó ti orísun ẹli wá.

KJV verse 26: Bless ye God in the congregations, even the Lord, from the fountain of Israel.

Níbẹ̀ ní ẹ̀yà kékeré wà, tí ó ń darí wọn, níbẹ̀ ni àwọn ọmọ-aládé , níbẹ̀ ni àwọn ọmọ-aládé àti tí .

KJV verse 27: There is little Benjamin with their ruler, the princes of Judah and their council, the princes of Zebulun, and the princes of Naphtali.

Pàṣẹ agbára rẹ, Ọlọ́run; fi agbára rẹ hàn wá, Ọlọ́run, gẹ́gẹ́ bí ìwọ ti ṣe ní ìṣáájú.

KJV verse 28: Thy God hath commanded thy strength: strengthen, O God, that which thou hast wrought for us.

Nítorí tẹmpili rẹ ni ẹmu àwọn ọba yóò mú ẹ̀bùn wá fún ọ.

KJV verse 29: Because of thy temple at Jerusalem shall kings bring presents unto thee.

Bá àwọn ẹranko búburú wí, tí ń gbé láàrín eèsún ọ̀pọ̀lọpọ̀ àwọn akọ màlúù pẹ̀lú àwọn ọmọ màlúù títí olúkúlùkù yóò fi foríbalẹ̀ pẹ̀lú ìwọ̀n fàdákà: tú àwọn ènìyàn tí ń ṣe inú dídùn sí ogun ká.

KJV verse 30: Rebuke the company of spearmen, the multitude of the bulls, with the calves of the people, till every one submit himself with pieces of silver: scatter thou the people that delight in war.

Àwọn ọmọ-aládé yóò wá láti ; Etiopia yóò na ọwọ́ rẹ̀ sí Ọlọ́run.

KJV verse 31: Princes shall come out of Egypt; Ethiopia shall soon stretch out her hands unto God.

Kọrin sí Ọlọ́run, ẹ̀yin ìjọba ayé, kọrin ìyìn sí Olúwa, .

KJV verse 32: Sing unto God, ye kingdoms of the earth; O sing praises unto the Lord; Selah:

Sí ẹni tí ń gun ọ̀run dé ọ̀run àtijọ́ lókè, tó ń fọhùn rẹ̀, ohùn ńlá.

KJV verse 33: To him that rideth upon the heavens of heavens, which were of old; lo, he doth send out his voice, and that a mighty voice.

Kéde agbára Ọlọ́run, ọláńlá rẹ̀ wà lórí ẹli, tí agbára rẹ̀ wà lójú ọ̀run.

KJV verse 34: Ascribe ye strength unto God: his excellency is over Israel, and his strength is in the clouds.

Ìwọ ní ẹ̀rù, Ọlọ́run, ní ibi mímọ́ rẹ; Ọlọ́run ẹli fi agbára àti okun fún àwọn ènìyàn rẹ. Olùbùkún ní Ọlọ́run!

KJV verse 35: O God, thou art terrible out of thy holy places: the God of Israel is he that giveth strength and power unto his people. Blessed be God.

Every verse in Saamu 68

Chapter navigation

Biblica® ní oore ọ̀fẹ́ láti lo Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní™ / Biblica® Open Yoruba Contemporary Bible™ Copyright © 2009, 2017 by Biblica, Inc. “Biblica” is a trademark registered in the United States Patent and Trademark Office by Biblica, Inc. Used with permission. Licensed under CC BY-SA 4.0.

KJV: public domain

Most-read Psalms in Yoruba

Saamu 680:00 / 0:00