Saamu

Saamu 76

Psalm 76 in Yoruba and English (KJV) · Orin Dafidi 76Tap any highlighted word for context

About this Psalm

The Psalm heading names Asaph as its author. This is a praise Psalm that celebrates God's victorious majesty and the fear due to him.

Saamu 76 — Scripture text (Biblica® Open Yoruba Contemporary Bible)

Ní ni a mọ Ọlọ́run; orúkọ rẹ̀ sì lágbára ní ẹli

KJV verse 1: In Judah is God known: his name is great in Israel.

Àgọ́ rẹ̀ wà ní ẹmu, ibùgbé rẹ̀ ni .

KJV verse 2: In Salem also is his tabernacle, and his dwelling place in Zion.

Níbẹ̀ ni ó ṣẹ́ ọfà, asà àti àwọn idà, ohun ìjà ogun. .

KJV verse 3: There brake he the arrows of the bow, the shield, and the sword, and the battle. Selah.

Ìwọ ni ògo àti ọlá, ju òkè ńlá ìkógun wọ̀nyí lọ.

KJV verse 4: Thou art more glorious and excellent than the mountains of prey.

A kó àwọn alágídí ọkàn ní ìkógun wọ́n sun oorun ìgbẹ̀yìn wọn; kò sí ọ̀kan nínú àwọn akọni tó lè gbé ọwọ́ rẹ̀ sókè.

KJV verse 5: The stouthearted are spoiled, they have slept their sleep: and none of the men of might have found their hands.

Ní ìfibú rẹ, Ọlọ́run ọbu, àwọn ẹṣin àti kẹ̀kẹ́ ogun sì dùbúlẹ̀ síbẹ̀.

KJV verse 6: At thy rebuke, O God of Jacob, both the chariot and horse are cast into a dead sleep.

Ìwọ nìkan ni ó yẹ kí a bẹ̀rù. Ta ló lé dúró níwájú rẹ, nígbà tí ìwọ bá ń bínú?

KJV verse 7: Thou, even thou, art to be feared: and who may stand in thy sight when once thou art angry?

Ìwọ ń ṣe ìdájọ́ láti ọ̀run, ilé ayé bẹ̀rù, ó sì dúró jẹ́ẹ́,

KJV verse 8: Thou didst cause judgment to be heard from heaven; the earth feared, and was still,

nígbà tí, ìwọ Ọlọ́run, bá dìde láti ṣe ìdájọ́, láti gba àwọn ẹni ìnilára ilẹ̀ náà. .

KJV verse 9: When God arose to judgment, to save all the meek of the earth. Selah.

Lóòótọ́, ìbínú rẹ sí àwọn ènìyàn ń mú ìyìn wá fún ọ, ẹni tí ó yọ nínú ìbínú rẹ ní a dá nígbà tí ìwọ bá fi ìbínú ìyókù di ara rẹ ni àmùrè.

KJV verse 10: Surely the wrath of man shall praise thee: the remainder of wrath shalt thou restrain.

Jẹ́ ẹ̀jẹ́ sí Olúwa Ọlọ́run rẹ kí o sì mú un ṣẹ; kí gbogbo àwọn tí ó yí i ká mú ẹ̀bùn wá fún ẹni tí ó tọ́ láti bẹ̀rù.

KJV verse 11: Vow, and pay unto the LORD your God: let all that be round about him bring presents unto him that ought to be feared.

Ó ké ẹ̀mí àwọn aládé kúrò; àwọn ọba ayé sì ń bẹ̀rù rẹ̀.

KJV verse 12: He shall cut off the spirit of princes: he is terrible to the kings of the earth.

Every verse in Saamu 76

Chapter navigation

Biblica® ní oore ọ̀fẹ́ láti lo Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní™ / Biblica® Open Yoruba Contemporary Bible™ Copyright © 2009, 2017 by Biblica, Inc. “Biblica” is a trademark registered in the United States Patent and Trademark Office by Biblica, Inc. Used with permission. Licensed under CC BY-SA 4.0.

KJV: public domain

Most-read Psalms in Yoruba

Saamu 760:00 / 0:00