Saamu

Saamu 99

Psalm 99 in Yoruba and English (KJV) · Orin Dafidi 99Tap any highlighted word for context

About this Psalm

The Psalm heading does not name an author. This is a royal Psalm that exalts the holy King who loves justice and answers his people.

Saamu 99 — Scripture text (Biblica® Open Yoruba Contemporary Bible)

Olúwa jẹ ọba; jẹ́ kí ayé kí ó wárìrì Ó jókòó lórí ìtẹ́ kérúbù jẹ́ kí ayé kí ó wárìrì.

KJV verse 1: The LORD reigneth; let the people tremble: he sitteth between the cherubims; let the earth be moved.

Olúwa tóbi ní ; Ó sì ga jù gbogbo orílẹ̀-èdè lọ.

KJV verse 2: The LORD is great in Zion; and he is high above all the people.

Kí wọ́n sì yin orúkọ rẹ̀ tí ó tóbi tí ó ni ẹ̀rù, Mímọ́ ni Òun.

KJV verse 3: Let them praise thy great and terrible name; for it is holy.

Ọba náà ní agbára, ó sì fẹ́ òdodo, ìwọ fi ìdí àìṣègbè múlẹ̀; ìwọ ṣe ohun tí ó tọ́ àti ohun tí ó yẹ nínú ọbu.

KJV verse 4: The king’s strength also loveth judgment; thou dost establish equity, thou executest judgment and righteousness in Jacob.

Gbígbéga ni Olúwa Ọlọ́run wa ẹ foríbalẹ̀ níbi ẹsẹ̀ rẹ̀; ó jẹ́ mímọ́.

KJV verse 5: Exalt ye the LORD our God, and worship at his footstool; for he is holy.

Mose àti wà nínú àwọn àlùfáà rẹ̀ ẹli wà nínú àwọn tí ó ń ké pe orúkọ rẹ̀ wọ́n ké pe Olúwa, ó sì dá wọn lóhùn.

KJV verse 6: Moses and Aaron among his priests, and Samuel among them that call upon his name; they called upon the LORD, and he answered them.

Ó sọ̀rọ̀ sí wọn nínú ọ̀wọ́n àwọsánmọ̀, wọ́n pa ẹ̀rí rẹ̀ mọ́ àti ìlànà tí ó fún wọn.

KJV verse 7: He spake unto them in the cloudy pillar: they kept his testimonies, and the ordinance that he gave them.

Olúwa Ọlọ́run wa, ó dá wọn lóhùn; ó jẹ́ Ọlọ́run tí ó ń dáríjì àwọn ọmọ ẹli ìwọ tí ó ń fi ìyà àìṣedéédéé wọn jẹ wọ́n.

KJV verse 8: Thou answeredst them, O LORD our God: thou wast a God that forgavest them, though thou tookest vengeance of their inventions.

Gbígbéga ni Olúwa Ọlọ́run wa kí a sìn ín ní òkè mímọ́ rẹ̀ nítorí Olúwa Ọlọ́run wa jẹ́ mímọ́.

KJV verse 9: Exalt the LORD our God, and worship at his holy hill; for the LORD our God is holy.

Every verse in Saamu 99

Chapter navigation

Biblica® ní oore ọ̀fẹ́ láti lo Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní™ / Biblica® Open Yoruba Contemporary Bible™ Copyright © 2009, 2017 by Biblica, Inc. “Biblica” is a trademark registered in the United States Patent and Trademark Office by Biblica, Inc. Used with permission. Licensed under CC BY-SA 4.0.

KJV: public domain

Most-read Psalms in Yoruba

Saamu 990:00 / 0:00