1 Chronicles 1:46
“Nígbà tí Huṣamu kú, Hadadi ọmọ Bedadi tí ó kọlu Midiani ní ìgbẹ́ Moabu, ó sì jẹ ọba ní ipò rẹ̀. Orúkọ ìlú rẹ̀ ni Afiti.”
1 Chronicles 1:46 — Biblica® Open Yoruba Contemporary Bible
Verse 46 of 54 in 1 Chronicles chapter 1 — Biblica® Open Yoruba Contemporary Bible. Read it in context below, with maps, timelines and thematic connections beside the text.
1 Chronicles 1 — full chapter (Biblica® Open Yoruba Contemporary Bible)
Adamu, Seti, Enoṣi, Kenani, Mahalaleli, Jaredi, Enoku, Metusela, Lameki, Noa. Àwọn ọmọ : Ṣemu, Hamu àti . Àwọn ọmọ ni: Gomeri, Magogu, Madai; Jafani, Tubali, Meṣeki àti . Àwọn ọmọ ni: Aṣkenasi, Rifati àti . Àwọn ọmọ ni: ṣa, Tarṣiṣi, Kittimu, àti . Àwọn ọmọ ni: Kuṣi, Ejibiti, Puti, àti . Àwọn ọmọ Kuṣi ni: Seba, Hafila, Sabta, Raama, àti . Àwọn ọmọ : Ṣeba àti . Kuṣi sì bí ẹni tí ó di alágbára jagunjagun ní ayé. Ejibiti sì bí , Anamimu, Lehabimu, Naftuhimu, Patrusimu, Kasluhimu (láti ọ̀dọ̀ ẹni tí àwọn ará ti wá) àti àwọn ará . Kenaani sì bí àkọ́bí rẹ̀, àti , àti àwọn ará , àti àwọn ará , àti àwọn ará ṣi, àti àwọn ará , àti àwọn ará , àti àwọn ará , àti àwọn ará , àti àwọn ará , àti àwọn ará . Àwọn ọmọ Ṣemu ni: Elamu, Aṣuri, Arfakṣadi, Ludi àti . Àwọn ọmọ : Usi, Huli, Geteri, àti Meṣeki. Arfakṣadi sì bí Ṣela, Ṣela sì bí . Eberi sì bí ọmọ méjì: ọ̀kan ń jẹ́ , nítorí ní ìgbà ọjọ́ rẹ̀ ni ilẹ̀ ya; orúkọ arákùnrin rẹ̀ ni . Joktani sì bí , Ṣelefi, Hasarmafeti, Jera. Hadoramu, Usali, Dikla, Ebali, Abimaeli, Ṣeba. Ofiri, Hafila, àti . Gbogbo àwọn wọ̀nyí ni ọmọ . Ṣemu, Arfakṣadi, Ṣela, Eberi, Pelegi. Reu, Serugu, Nahori, Tẹra, àti (tí ń ṣe ). Àwọn ọmọ : Isaaki àti Iṣmaeli. Èyí ni àwọn ọmọ náà: Nebaioti àkọ́bí Iṣmaeli: Kedari, Adbeeli, Mibsamu, Miṣima, Duma, Massa, Hadadi, Tema, Jeturi, Nafiṣi, àti . Àwọn wọ̀nyí ni ọmọ Iṣmaeli. Àwọn ọmọ , obìnrin : Simrani, Jokṣani , Midiani Iṣbaki àti Ṣua. Àwọn ọmọ ṣani: Ṣeba àti . Àwọn ọmọ : Efani, Eferi, Hanoku, Abida àti . Gbogbo àwọn wọ̀nyí ni ìran . Abrahamu sì jẹ́ baba . Àwọn ọmọ : àti ẹli. Àwọn ọmọ : Elifasi, Reueli, Jeuṣi, Jalamu, àti . Àwọn ọmọ : Temani, Omari, Sefi, Gatamu àti ; láti : Amaleki. Àwọn ọmọ : Nahati, Sera, Ṣamma àti . Àwọn ọmọ : Lotani, Ṣobali, Sibeoni, Ana, Diṣoni, Eseri àti Diṣani. Àwọn ọmọ : Hori àti : Timna sì ni arábìnrin . Àwọn ọmọ Ṣobali: Afiani, Manahati, Ebali, Ṣefo àti . Àwọn ọmọ : Aiah àti . Àwọn ọmọ : Diṣoni. Àwọn ọmọ Diṣoni: Hemdani, Eṣbani, Itrani, àti . Àwọn ọmọ : Bilhani, Saafani àti . Àwọn ọmọ Diṣani: Usi àti . Àwọn wọ̀nyí ni ọba tí ó jẹ ní , kí ó tó di pé ọba kankan jẹ lórí ẹli: Bela ọmọ , orúkọ ìlú rẹ̀ ni . Nígbà tí kú, Jobabu ọmọ ti sì jẹ ọba ní ipò rẹ̀. Nígbà tí kú, Huṣamu láti ilẹ̀ sì jẹ ọba ní ipò rẹ̀. Nígbà tí Huṣamu kú, Hadadi ọmọ tí ó kọlu ní ìgbẹ́ , ó sì jẹ ọba ní ipò rẹ̀. Orúkọ ìlú rẹ̀ ni . Nígbà tí sì kú, Samla láti , ó sì jẹ ọba ní ipò rẹ̀. Samla sì kú, Saulu ti létí odò sì jẹ ọba ní ipò rẹ̀. Nígbà tí kú, Baali-, ọmọ jẹ ọba ní ipò rẹ̀. Nígbà tí - kú, Hadadi ni ó jẹ ọba ní ipò rẹ̀. Orúkọ ìlú rẹ̀ ni ; orúkọ ìyàwó sì ni ọmọbìnrin , ọmọbìnrin . Hadadi sì kú pẹ̀lú. Àwọn baálẹ̀ ni: baálẹ̀ , baálẹ̀ , baálẹ̀ baálẹ̀ , baálẹ̀ , baálẹ̀ . Baálẹ̀ , baálẹ̀ , baálẹ̀ , Magdieli àti . Àwọn wọ̀nyí ni baálẹ̀ .
Every verse in 1 Chronicles 1
Chapter navigation
Biblica® ní oore ọ̀fẹ́ láti lo Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní™ / Biblica® Open Yoruba Contemporary Bible™ Copyright © 2009, 2017 by Biblica, Inc. “Biblica” is a trademark registered in the United States Patent and Trademark Office by Biblica, Inc. Used with permission. Licensed under CC BY-SA 4.0.