1 Chronicles 11:30
“Maharai ará Netofa, Heledi ọmọ Baanah ará Netofa,”
1 Chronicles 11:30 — Biblica® Open Yoruba Contemporary Bible
Verse 30 of 47 in 1 Chronicles chapter 11 — Biblica® Open Yoruba Contemporary Bible. Read it in context below, with maps, timelines and thematic connections beside the text.
1 Chronicles 11 — full chapter (Biblica® Open Yoruba Contemporary Bible)
Gbogbo àwọn ẹli kó ara wọn jọ pọ̀ sí ọ̀dọ̀ ní , wọ́n sì wí pé, “Ẹran-ara rẹ àti ẹ̀jẹ̀ rẹ ni àwa í ṣe. Ní àtijọ́, kódà nígbà tí jẹ ọba, ìwọ ni ẹni tí ó darí ẹli ní ojú ogun wọn. Olúwa Ọlọ́run rẹ sì wí fún ọ pé, ‘Ìwọ yóò sì jẹ́ olùṣọ́ ẹli ènìyàn mi, ìwọ yóò sì jẹ́ olórí fún wọn.’ ” Nígbà tí gbogbo àwọn ìjòyè ẹli tí wọ́n ti wá sọ́dọ̀ ọba ni . Ó sì ṣe májẹ̀mú pẹ̀lú wọn ní níwájú Olúwa, wọ́n sì fi òróró yan ní ọba lórí ẹli, gẹ́gẹ́ bí ọ̀rọ̀ Olúwa láti ọwọ́ ẹli. Dafidi àti gbogbo àwọn ọmọ ẹli jáde lọ sí ẹmu (tí ṣe ). Àwọn ara ilẹ̀ náà ń gbé níbẹ̀. Àwọn ará ìlú sì wí fún pé, “Ìwọ kò sì gbọdọ̀ wọ ìhín yìí wá.” Ṣùgbọ́n kó ìlú odi —èyí tí í ṣe ìlú . Dafidi ti wí pé, “Ẹnikẹ́ni tí ó bá tètè kọlu àwọn ará ni yóò di olórí àti balógun.” ọmọ sì kọ́kọ́ gòkè lọ, bẹ́ẹ̀ ni ó sì gba olórí. Dafidi sì ń gbé inú ìlú odi, nítorí náà ni wọ́n fi ń pè é ni ìlú . Ó sì kọ́ àwọn ìlú náà yíkákiri; láti yíkákiri; Joabu sì tún ìyókù àwọn ìlú náà ṣe. Bẹ́ẹ̀ ni ń ga, ó sì pọ̀ sí i, nítorí pé Olúwa àwọn ọmọ-ogun wà pẹ̀lú rẹ̀. Àwọn wọ̀nyí sì ni ìjòyè alágbára ọkùnrin , àwọn pẹ̀lú gbogbo àwọn ọmọ ẹli, wọ́n sì fún ìjọba rẹ̀ ní àtìlẹ́yìn tó lágbára láti mú un tàn káàkiri gbogbo ilẹ̀, gẹ́gẹ́ bí Olúwa ti ṣèlérí. Èyí sì ni iye àwọn akọni ọkùnrin : Jaṣobeamu ọmọ , òun sì ni olórí nínú àwọn ìjòyè, ó sì gbé ọ̀kọ̀ rẹ̀ sókè lórí àwọn ọ̀ọ́dúnrún (300) ènìyàn, àwọn ẹni tí ó pa ní ogun ẹ̀ẹ̀kan. Lẹ́yìn rẹ̀ sì ni ọmọ àwọn ará , ọ̀kan lára àwọn mẹ́ta ọkùnrin alágbára. Ó sì wà pẹ̀lú ní - nígbà tí àwọn ará kó ara wọn jọ láti jagun, níbi tí ilẹ̀ kan wà tí ó kún fún ọkà barle. Àwọn ènìyàn sì sálọ kúrò níwájú . Ṣùgbọ́n wọ́n mú ìdúró wọn ní àárín pápá náà. Wọ́n sì gbà a wọ́n sì gún àwọn ará mọ́lẹ̀, Olúwa sì mú ìgbàlà ńlá fún wọn. Mẹ́ta nínú àwọn ọgbọ̀n ìjòyè sọ̀kalẹ̀ tọ́ wá lọ sí orí àpáta nínú ihò , nígbà tí àwọn ẹgbẹ́ sì dúró ní àfonífojì ní orí òkè . Ní àsìkò náà sì ń bẹ nínú ìlú odi, ẹgbẹ́ ogun àwọn ará sì ń bẹ ní Bẹtilẹhẹmu. Dafidi sí pòǹgbẹ fún omi ó sì wí pé, “Háà, ẹnìkan yóò ha bu omi láti inú kànga ní ẹ̀gbẹ́ ẹnu-bodè Bẹtilẹhẹmu fún un mu?” Bẹ́ẹ̀ ni àwọn mẹ́ta náà sì là láti ogun ará , ó sì fa omi jáde láti inú kànga ní ẹ̀gbẹ́ ẹnu-bodè Bẹtilẹhẹmu ó sì gbé padà tọ wá. Ṣùgbọ́n ó kọ̀ láti mu ú: dípò, ó sì tú jáde níwájú Olúwa. “Kí Ọlọ́run má jẹ́ kí èmi ó má ṣe ṣe èyí!” ó wí pé. “Ṣé kí èmi kí ó mú ẹ̀jẹ̀ ọkùnrin yí ẹni tí ó fi ẹ̀mí rẹ̀ wéwu?” Nítorí wọ́n fi ẹ̀mí wọn wéwu láti mú padà wá, Dafidi kò ní mu ú. Nǹkan wọ̀nyí ni àwọn akọni mẹ́ta ọkùnrin náà ṣe ohun ìyanu ńlá. Abiṣ arákùnrin ìjòyè àwọn mẹ́ta. Ó sì gbé ọ̀kọ̀ rẹ̀ sókè lórí àwọn ọ̀ọ́dúnrún (300) àwọn ènìyàn, àwọn ẹni tí ó pa, bẹ́ẹ̀ ni ó sì di olókìkí gẹ́gẹ́ bí àwọn mẹ́ta. Ó sì gba ìlọ́po ọlá lórí àwọn mẹ́tẹ̀ẹ̀ta ó sì di olórí wọn, bí ó tilẹ̀ jẹ́ pé a kò ka kún ara wọn. Benaiah ọmọ ó sì jẹ́ akọni íjà láti ṣeeli, ẹni tí ó ṣe iṣẹ́ agbára ńlá. Ó sì pa àwọn ọmọ méjì ti , ó sì tún sọ̀kalẹ̀ lọ sí inú ihò lákokò yìnyín dídì, ó sì pa kìnnìún kan Ó sì pa ara ẹni tí ó ga ní ìwọ̀n ẹsẹ̀ méje àti ààbọ̀ ṣùgbọ́n àwọn ará wọn ní ọ̀kọ̀ gẹ́gẹ́ bí ìdábùú igi ahunṣọ àti ọ̀pá ní ọwọ́ rẹ̀, Benaiah sọ̀kalẹ̀ lórí rẹ̀ pẹ̀lú kùmọ̀. Ó sì gba ọ̀kọ̀ náà láti ọwọ́ ará ó sì pa á pẹ̀lú ọ̀kọ̀ rẹ̀. Nǹkan wọ̀nyí sì ní ìwà akin ọmọ ; ohun náà pẹ̀lú sì di olókìkí gẹ́gẹ́ bí àwọn akọni ọkùnrin mẹ́ta. Ó sì ní ọlá púpọ̀ ju àwọn ọgbọ̀n lọ, ṣùgbọ́n a kò kà á láàrín àwọn mẹ́tẹ̀ẹ̀ta. Dafidi sì fi sí ìkáwọ́ àwọn ẹ̀ṣọ́. Àwọn akọni ọkùnrin náà nìyí: Asaheli arákùnrin , Elhanani ọmọ láti Bẹtilẹhẹmu, Ṣamotu ará , Helesi ará Ira ọmọ Ikẹsi láti , Abieseri láti , Sibekai ará Huṣati, láti ará Maharai ará , Heledi ọmọ ará , Itai ọmọ láti ní , Benaiah ará , Hurai láti àfonífojì ṣi, Abieli ará , Asmafeti ará ará Ṣaalboni. Àwọn ọmọ Haṣemu ará ọmọ Ṣage ará . Ahiamu ọmọ ará , Elifali ọmọ Heferi ará , Ahijah ará , Hesro ará ọmọ , Joẹli arákùnrin ọmọ , Seleki ará , Naharai ará ẹni tí ó jẹ́ ẹni tí n ru ìhámọ́ra ọmọ . Ira ará , Garebu ará , ará ọmọ . Adina ọmọ Ṣisa ará , ẹni tí ó jẹ́ ìjòyè ará , àti pẹ̀lú ọgbọ́n rẹ̀. Hanani ọmọ . Jehoṣafati ará . Ussia ará , Ṣama àti àwọn ọmọ ará , Jediaeli ọmọ Ṣimri, àti arákùnrin ará Elieli ará àti Joṣafia àwọn ọmọ , Itimah ará , Elieli, Obedi àti ará .
Every verse in 1 Chronicles 11
Chapter navigation
Biblica® ní oore ọ̀fẹ́ láti lo Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní™ / Biblica® Open Yoruba Contemporary Bible™ Copyright © 2009, 2017 by Biblica, Inc. “Biblica” is a trademark registered in the United States Patent and Trademark Office by Biblica, Inc. Used with permission. Licensed under CC BY-SA 4.0.