1 Chronicles 15:3

“Dafidi kó gbogbo àwọn ọmọ Israẹli jọ ní Jerusalẹmu láti gbé àpótí ẹ̀rí Olúwa wá sí ibi tí ó ti pèsè sílẹ̀ fún un.”

1 Chronicles 15:3 — Biblica® Open Yoruba Contemporary Bible

Verse 3 of 29 in 1 Chronicles chapter 15 — Biblica® Open Yoruba Contemporary Bible. Read it in context below, with maps, timelines and thematic connections beside the text.

1 Chronicles 15 — full chapter (Biblica® Open Yoruba Contemporary Bible)

Lẹ́yìn ìgbà tí ti kọ́ ilé fún ara rẹ̀ ní ìlú . Ó sì fi ààyè sílẹ̀ fún àpótí ẹ̀rí Ọlọ́run ó sì pàgọ́ fún un. Nígbà náà wí pé, kò sí ẹnìkan àyàfi àwọn ọmọ ni ó lè gbé àpótí ẹ̀rí Ọlọ́run, nítorí Olúwa yàn wọ́n láti gbé àpótí ẹ̀rí Olúwa àti láti máa ṣe ìránṣẹ́ níwájú rẹ̀ títí láé. Dafidi kó gbogbo àwọn ọmọ ẹli jọ ní ẹmu láti gbé àpótí ẹ̀rí Olúwa wá sí ibi tí ó ti pèsè sílẹ̀ fún un. Wọ̀nyí ni àwọn ọmọ àti àwọn ọmọ tí péjọ papọ̀. Ọgọ́fà nínú àwọn ọmọ ; Urieli olórí àti àwọn ẹbí rẹ̀. Igba ó lé ogún nínú àwọn ọmọ ; Asaiah olórí àti àwọn ẹbí rẹ̀. Àádóje nínú àwọn ọmọ ṣoni; Joẹli olórí àti àwọn ẹbí rẹ̀. Igba nínú àwọn ọmọ ; Ṣemaiah olórí àti àwọn ẹbí rẹ̀. Ọgọ́rin nínú àwọn ọmọ ; Elieli olórí àti àwọn ẹbí rẹ̀. Méjìléláàádọ́fà nínú àwọn ọmọ ; Amminadabu olórí àti àwọn ẹbí rẹ̀. Dafidi sì ránṣẹ́ pe , Abiatari tí wọ́n jẹ́ àlùfáà, àti , Asaiah. Joẹli, Ṣemaiah, Elieli àti tí wọ́n jẹ́ . Ó sì fi fún wọn pé, “Ẹ̀yin ni olórí àwọn ìdílé ; ẹ̀yin àti àwọn ènìyàn yín, ẹ ya ara yín sí mímọ́ kí ẹ lè gbé àpótí ẹ̀rí Olúwa, Ọlọ́run ẹli, lọ sí ibi tí mó ti pèsè sílẹ̀ fún un. Nítorí tí ẹ̀yin ọmọ kò gbe gòkè wá ní ìgbà àkọ́kọ́ ti Olúwa Ọlọ́run fi ìbínú rẹ̀ ko lù wá. Àwa kò sì ṣe ìwádìí lọ́wọ́ rẹ̀ nípa bí a ti ń ṣe é gẹ́gẹ́ bí ọ́nà tí a là sílẹ̀.” Bẹ́ẹ̀ ni àwọn àlùfáà àti àwọn ya ara wọn sí mímọ́ láti gbé àpótí ẹ̀rí Olúwa gòkè wá, Ọlọ́run ẹli. Nígbà náà ni àwọn gbé àpótí ẹ̀rí Ọlọ́run pẹ̀lú ọ̀pá ní èjìká wọn gẹ́gẹ́ bí ti pa á láṣẹ gẹ́gẹ́ bí ọ̀rọ̀ Olúwa. Dafidi sọ fún àwọn olórí àwọn láti yan àwọn arákùnrin wọn gẹ́gẹ́ bí akọrin láti kọ orin ayọ̀, pẹ̀lú àwọn ohun èlò orin olókùn, dùùrù, àti símbálì. Bẹ́ẹ̀ ni àwọn yan ọmọ Joẹli; àti nínú àwọn arákùnrin rẹ̀, Asafu ọmọ , àti nínú àwọn ọmọ arákùnrin wọn, Etani ọmọ Kuṣaiah; àti pẹ̀lú wọn àwọn arákùnrin wọn tí a yàn bí olùrànlọ́wọ́ wọn: Sekariah, Jaasieli, Ṣemiramotu, Jehieli, Unni, Eliabu, Benaiah, Maaseiah, Mattitiah, Elifelehu, Mikimeiah, àti - àti , àwọn aṣọ́bodè. Àwọn akọrin sì ni , Asafu, àti ti àwọn ti kimbali idẹ tí ń dún kíkan; Sekariah, Asieli, Ṣemiramotu, Jehieli, àti , Eliabu, Maaseiah àti àwọn tí ó gbọdọ̀ ta ohun èlò orin olókùn gẹ́gẹ́ bí alamoti, àti , Elifelehu, Mikneiah, Obedi-, Jeieli àti ni ó ní láti ta ohun èlò olóhùn gooro, láti darí gẹ́gẹ́ bí ṣeminiti. Kenaniah olórí àwọn ará ni ó wà ní ìkáwọ́ orin èyí sì ni ojúṣe nítorí ó mòye nípa rẹ̀. Berekiah àti ni kí ó wà gẹ́gẹ́ bí olùṣọ́nà fún àpótí ẹ̀rí. Ṣebaniah, Jehoṣafati, Netaneli, Amasai, Sekariah, Benaiah àti ní àwọn àlùfáà, tí o ń fún ìpè níwájú àpótí ẹ̀rí Ọlọ́run. Obedi- àti ni ó sì gbọdọ̀ jẹ́ olùṣọ́nà fún àpótí ẹ̀rí. Bẹ́ẹ̀ ni àti àwọn àgbàgbà ẹli àti àwọn olórí ẹgbẹẹgbẹ̀rún lọ láti gbé àpótí ẹ̀rí ti májẹ̀mú Olúwa láti ilé -, pẹ̀lú inú dídùn. Nítorí Ọlọ́run tì ràn wọ́n lọ́wọ́ àwọn ará ẹni tí ó gbé àpótí ẹ̀rí ti májẹ̀mú Olúwa, akọ màlúù méje pẹ̀lú àgbò méje láti fi ṣé ìrúbọ. Dafidi sì wọ efodu; aṣọ ìgúnwà ọ̀gbọ̀ dáradára, àti gbogbo àwọn ọmọ tí ń ru àpótí ẹ̀rí náà, àti àwọn akọrin, àti olórí pẹ̀lú àwọn akọrin. Dafidi sì wọ aṣọ ìgúnwà funfun. Bẹ́ẹ̀ ni gbogbo ẹli gbé àpótí ẹ̀rí àti májẹ̀mú Olúwa gòkè wá pẹ̀lú ariwo, pẹ̀lú àyíká ìhó ayọ̀ àti láti fọn fèrè ti ìpè, àti kimbali, àti láti ta ohun èlò orin olókùn àti dùùrù olóhùn gooro. Bí àpótí ẹ̀rí Olúwa ti ń wọ ìlú ńlá , Mikali ọmọbìnrin ń wò láti ojú fèrèsé nígbà tí ó sì rí ọba ń jó, ó sì ń ṣe àjọyọ̀, ó sì kẹ́gàn rẹ̀ ní ọkàn rẹ̀.

Every verse in 1 Chronicles 15

Chapter navigation

Biblica® ní oore ọ̀fẹ́ láti lo Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní™ / Biblica® Open Yoruba Contemporary Bible™ Copyright © 2009, 2017 by Biblica, Inc. “Biblica” is a trademark registered in the United States Patent and Trademark Office by Biblica, Inc. Used with permission. Licensed under CC BY-SA 4.0.

0:000:00