1 Chronicles 2:6
“Àwọn ọmọ Sera: Simri, Etani, Hemani, Kalkoli àti Dara, gbogbo wọn jẹ́ márùn-ún.”
1 Chronicles 2:6 — Biblica® Open Yoruba Contemporary Bible
Verse 6 of 55 in 1 Chronicles chapter 2 — Biblica® Open Yoruba Contemporary Bible. Read it in context below, with maps, timelines and thematic connections beside the text.
1 Chronicles 2 — full chapter (Biblica® Open Yoruba Contemporary Bible)
Àwọn wọ̀nyí ni àwọn ọmọ ẹli. Reubeni, Simeoni, Lefi, Juda, Isakari, Sebuluni, Dani, Josẹfu, Benjamini; Naftali, Gadi: àti Aṣeri. Àwọn ọmọ : Eri, Onani àti Ṣela, àwọn mẹ́tẹ̀ẹ̀ta wọ̀nyí ni wọ́n bí fún un láti ọ̀dọ̀ arábìnrin , ọmọbìnrin Ṣua. Eri àkọ́bí , ó sì burú ní ojú Olúwa, bẹ́ẹ̀ ni Olúwa sì pa á. Tamari, aya ọmọbìnrin , ó sì bí àti sì ní ọmọ márùn-ún ní àpapọ̀. Àwọn ọmọ : Hesroni àti . Àwọn ọmọ : Simri, Etani, Hemani, Kalkoli àti , gbogbo wọn jẹ́ márùn-ún. Àwọn ọmọ : Akani, ẹni tí ó mú ìyọnu wá sórí ẹli nípa ẹ̀ṣẹ̀ ìfibú lórí mímú ohun ìyàsọ́tọ̀. Àwọn ọmọ : Asariah. Àwọn ọmọ tí a bí fún ni: Jerahmeeli, Ramu àti . Ramu sì ni baba , àti baba ṣoni olórí àwọn ènìyàn . Nahiṣoni sì ni baba , Salmoni ni baba , Boasi baba àti baba . Jese sì ni baba àkọ́bí rẹ̀; ọmọ ẹlẹ́ẹ̀kejì sì ni , ẹlẹ́ẹ̀kẹta ni Ṣimea, ẹlẹ́ẹ̀kẹrin , ẹlẹ́ẹ̀karùnún , ẹlẹ́ẹ̀kẹfà àti ẹlẹ́ẹ̀keje . Àwọn arábìnrin wọn ni àti . Àwọn ọmọ mẹ́ta ni ṣ, Joabu àti . Abigaili ni ìyá , ẹni tí baba rẹ̀ sì jẹ́ ará Iṣmaeli. Kalebu ọmọ ní ọmọ láti ọ̀dọ̀ ìyàwó rẹ̀ (láti ọ̀dọ̀ ). Àwọn wọ̀nyí ni àwọn ọmọ rẹ̀: Jeṣeri, Ṣobabu àti . Nígbà tí sì kú, Kalebu sì fẹ́ ní aya, ẹni tí ó bí fún un. Huri ni baba , Uri sì jẹ́ baba . Nígbà tí ó yá, Hesroni sì dùbúlẹ̀ pẹ̀lú ọmọbìnrin baba (ó sì ti fẹ́ ní aya láti ìgbà tí ó ti wà ní ẹni ọgọ́ta ọdún) ó sì bí . Segubu sì jẹ́ baba , ẹni tí ó jẹ́ olùdarí ìlú mẹ́tàlélógún ní ilẹ̀ . (Ṣùgbọ́n Geṣuri àti sì fi agbára gba -, àti pẹ̀lú gbogbo agbègbè rẹ̀ tí wọn tẹ̀dó sí jẹ́ ọgọ́ta ìlú.) wọ̀nyí ni àwọn ọmọ baba . Lẹ́yìn tí sì kú ni , Abijah ìyàwó rẹ̀ ti sì bí Aṣihuri baba fún un. Ọmọ àkọ́bí : Ramu ọmọ àkọ́bí rẹ̀ , Oreni, Osemu àti . Jerahmeeli ní ìyàwó mìíràn, ẹni tí orúkọ rẹ̀ ń jẹ́ ; ó sì jẹ́ ìyá fún . Àwọn ọmọ àkọ́bí : Maasi, Jamini àti . Àwọn ọmọ : Ṣammai àti . Àwọn ọmọ Ṣammai: Nadabu àti ṣuri. Orúkọ ìyàwó ṣuri ni ẹni tí ó bí àti . Àwọn ọmọ àti . Seledi sì kú láìsí ọmọ. Àwọn ọmọ : Iṣi, ẹni tí ó jẹ́ baba fún Ṣeṣani. Ṣeṣani sì jẹ́ baba fún . Àwọn ọmọ , arákùnrin Ṣammai: Jeteri àti . Jeteri sì kú láìní ọmọ. Àwọn ọmọ : Peleti àti . Àwọn wọ̀nyí ni ọmọ . Ṣeṣani kò sì ní ọmọkùnrin àwọn ọmọbìnrin nìkan ni ó ní. Ó sì ní ìránṣẹ́ ará tí orúkọ rẹ̀ ń jẹ́ . Ṣeṣani sì fi ọmọ obìnrin rẹ̀ ní aya fún ìránṣẹ́ rẹ̀ , ó sì bí ọmọ fún tí orúkọ rẹ̀ jẹ́ . Attai sì jẹ́ baba fún , Natani sì jẹ́ baba fún , Sabadi ni baba , Eflali jẹ́ baba , Obedi sì ni baba , ni baba , Asariah sì ni baba , Helesi ni baba , Eleasa ni baba , Sismai ni baba Ṣallumu, Ṣallumu sì ni baba , Jekamiah sì ni baba ṣama. Àwọn ọmọ arákùnrin : Meṣa àkọ́bí rẹ̀, ẹni tí ó jẹ́ baba fún , àti àwọn ọmọ rẹ̀ ṣa, ẹni tí ó jẹ́ baba fún . Àwọn ọmọ : Kora, Tapua, Rekemu, àti Ṣema. Ṣema ni baba , Rahamu sì jẹ́ baba fún . Rekemu sì ni baba Ṣammai. Àwọn ọmọ Ṣammai ni , Maoni sì ni baba -. Efani obìnrin sì ni ìyá , Mosa àti , Harani sì ni baba . Àwọn ọmọ : Regemu, Jotamu, Geṣani, Peleti, Efani àti Ṣaafu. Maaka obìnrin sì ni ìyá àti . Ó sì bí Ṣaafu baba , Ṣefa baba àti baba , ọmọbìnrin sì ni . Àwọn wọ̀nyí ni ọmọ . Àwọn ọmọ , àkọ́bí : Ṣobali baba -. Salma baba Bẹtilẹhẹmu àti baba -. Àwọn ọmọ Ṣobali baba - ni: Haroe, ìdajì àwọn ará . Àti ìdílé -: àti àwọn ara , àti àwọn ará , àti àwọn ará Ṣumati àti àwọn ará Miṣraiti: láti ọ̀dọ̀ wọn ni àwọn ọmọ ará àti àwọn ará Eṣtaoli ti wá. Àwọn ọmọ : Bẹtilẹhẹmu, àti àwọn ará , Atrotu -, ìdajì àwọn ará , àti ará , àti àwọn ìdílé àwọn akọ̀wé, ẹni tí ń gbé ní : àti àwọn ọmọ àti àwọn ará Ṣimeati àti àwọn ará . Àwọn wọ̀nyí ni àwọn ará , ẹni tí ó wá láti ọ̀dọ̀ , baba ilé .
Every verse in 1 Chronicles 2
Chapter navigation
Biblica® ní oore ọ̀fẹ́ láti lo Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní™ / Biblica® Open Yoruba Contemporary Bible™ Copyright © 2009, 2017 by Biblica, Inc. “Biblica” is a trademark registered in the United States Patent and Trademark Office by Biblica, Inc. Used with permission. Licensed under CC BY-SA 4.0.