1 Chronicles 23:10

“Àti ọmọ Ṣimei: Jahati, Sina, Jeuṣi àti Beriah. Àwọn wọ̀nyí ni ọmọ Ṣimei mẹ́rin ni gbogbo wọn.”

1 Chronicles 23:10 — Biblica® Open Yoruba Contemporary Bible

Verse 10 of 32 in 1 Chronicles chapter 23 — Biblica® Open Yoruba Contemporary Bible. Read it in context below, with maps, timelines and thematic connections beside the text.

1 Chronicles 23 — full chapter (Biblica® Open Yoruba Contemporary Bible)

Nígbà tí sì dàgbà, tí ó sì di arúgbó, ó sì fi ọmọ rẹ̀ jẹ ọba lórí ẹli. Ó sì kó gbogbo àgbàgbà ẹli jọ, àti gẹ́gẹ́ bí àwọn àlùfáà àti àwọn ará . Àwọn ọmọ láti ọgbọ̀n ọdún tàbí jù bẹ́ẹ̀ lọ ni wọ́n kà àpapọ̀ iye àwọn ọkùnrin wọn sì jẹ́ ẹgbàá mọ́kàndínlógún (38,000). Dafidi sì wí pe, ní ti èyí, ẹgbàá méjìlá (24,000) ni kí wọn jẹ́ alábojútó iṣẹ́ ilé fún Olúwa àti ẹgbẹ̀rún mẹ́fà (6,000) ni kí ó ṣe olórí àti ídàájọ́. Ẹgbàajì (4,000) ni kí ó jẹ́ olùtọ́jú ẹnu-ọ̀nà àti ẹgbàajì (4,000) ni kí o sì jẹ́ ẹni ti yóò máa yin Olúwa pẹ̀lú ohun èlò orin, mo ti ṣe èyí fún ìdí pàtàkì yìí. Dafidi sì pín àwọn ọmọ sí ẹgbẹgbẹ́ láàrín àwọn ọmọ : Gerṣoni, Kohati àti . Àwọn tí ó jẹ́ ọmọ ṣoni: Laadani àti Ṣimei. Àwọn ọmọ ẹni àkọ́kọ́, Setamu àti Joẹli, mẹ́ta ní gbogbo wọn. Àwọn ọmọ Ṣimei: Ṣelomiti, Hasieli àti mẹ́ta ní gbogbo wọn. Àwọn wọ̀nyí sì ni olórí àwọn ìdílé . Àti ọmọ Ṣimei: Jahati, Sina, Jeuṣi àti . Àwọn wọ̀nyí ni ọmọ Ṣimei mẹ́rin ni gbogbo wọn. Jahati sì ni alákọ́kọ́ sì ni ẹlẹ́ẹ̀kejì, ṣùgbọ́n ṣi àti kò ní àwọn ọmọ púpọ̀; bẹ́ẹ̀ ni wọ́n sì ka ara wọn sí ìdílé kan pẹ̀lú ìfilé lọ́wọ́ kan. Àwọn ọmọ : Amramu, Isari, Hebroni àti mẹ́rin ni gbogbo wọn. Àwọn ọmọ . Aaroni àti . A sì ya sọ́tọ̀ òun àti àwọn ọmọ rẹ̀ títí láéláé, láti kọjú sí ohun mímọ́ jùlọ, láti fi rú ẹbọ sísun níwájú Olúwa, láti máa ṣe òjíṣẹ́ níwájú rẹ̀ àti láti kéde ìbùkún ní orúkọ rẹ̀ títí láéláé. Àwọn ọmọ ènìyàn Ọlọ́run ni wọ́n kà gẹ́gẹ́ bí apá kan ẹ̀yà . Àwọn ọmọ : Gerṣomu àti . Àwọn ọmọ ṣomu: Ṣubaeli sì ni alákọ́kọ́. Àwọn ọmọ : Rehabiah sì ni ẹni àkọ́kọ́. Elieseri kò sì tún ní ọmọ mìíràn, ṣùgbọ́n àwọn ọmọ wọ́n sì pọ̀ níye. Àwọn ọmọ : Ṣelomiti sì ni ẹni àkọ́kọ́. Àwọn ọmọ : Jeriah sì ni ẹni àkọ́kọ́, Amariah sì ni ẹni ẹ̀ẹ̀kejì, Jahasieli sì ni ẹ̀ẹ̀kẹ́ta àti ẹ̀ẹ̀kẹrin. Àwọn ọmọ : Mika ni àkọ́kọ́ àti Iṣiah ẹ̀ẹ̀kejì. Àwọn ọmọ : Mahili àti Muṣi. Àwọn ọmọ : Eleasari àti Kiṣi. Eleasari sì kú pẹ̀lú àìní àwọn ọmọkùnrin: Ó ní ọmọbìnrin nìkan. Àwọn ọmọ ẹ̀gbọ́n, àwọn ọmọ Kiṣi, sì fẹ́ wọn. Àwọn ọmọ Muṣi: Mahili, Ederi àti mẹ́ta ni gbogbo wọn. Àwọn wọ̀nyí sì ni ọmọ bí ìdílé wọn. Olórí ìdílé gẹ́gẹ́ bí wọ́n ti fi orúkọ sílẹ̀ lábẹ́ orúkọ wọn, ó sì kà wọn ní ẹyọ kọ̀ọ̀kan, wí pé, àwọn òṣìṣẹ́ tí ó jẹ́ ogún ọdún tàbí jù bẹ́ẹ̀ lọ tí ń ṣiṣẹ́ ìsìn nínú ilé Olúwa. Nítorí pé ti sọ pé, “Níwọ̀n ìgbà tí Olúwa Ọlọ́run ẹli, ti fi ìsinmi fún àwọn ènìyàn tí ó kù tí sì ń gbé ẹmu títí láéláé, àwọn ọmọ kò sì tún ru àgọ́ tàbí ọ̀kankan lára àwọn ohun èlò tí wọ́n ń lò níbi ìsìn rẹ̀.” Gẹ́gẹ́ bí ọ̀rọ̀ ìkẹyìn sí, àwọn ọmọ , wọ́n sì kà wọ́n, bẹ̀rẹ̀ láti orí àwọn ọmọ ogún ọdún tàbí jù bẹ́ẹ̀ lọ. Iṣẹ́ àwọn ọmọ ni láti ran àwọn ọmọ lọ́wọ́ nínú iṣẹ́ wọn fún ti ilé Olúwa: láti wà lábẹ́ ìkáwọ́ agbára ìlú, àti ẹ̀gbẹ́ ilé, àti ìwẹ̀nùmọ́ ti gbogbo ohun ìyàsọ́tọ̀ àti ṣíṣe ohun tí í ṣe iṣẹ́ ìsìn nínú ilé Olúwa. Wọ́n sì wà ní ìkáwọ́ àkàrà tí wọ́n mú jáde láti orí tábìlì, àti ìyẹ̀fun fún ẹbọ, àti àkàrà aláìwú, àti fún púpọ̀ àti èyí tí a pòpọ̀, àti gbogbo írúú ìwọ̀n àti wíwọ̀n àti òsùwọ̀n. Wọ́n sì gbọdọ̀ dúró ní gbogbo òwúrọ̀ láti dúpẹ́ àti láti yin Olúwa. Wọ́n sì gbọdọ̀ ṣe irú kan náà ní àṣálẹ́. Àti láti rú ẹbọ sísun fún Olúwa ní ọjọ́ ìsinmi àti ní àsìkò oṣù tuntun àti ní àjọ̀dún tí a yàn. Wọ́n gbọdọ̀ sìn níwájú Olúwa lójoojúmọ́ ní iye tó yẹ àti ní ọ̀nà tí a ti pàṣẹ fún wọn. Bẹ́ẹ̀ ni nígbà náà, àwọn ọmọ gbé ìgbékalẹ̀ jáde fún ìpàdé àgọ́, fún Mímọ́ àti, lábẹ́ àwọn arákùnrin àwọn ọmọ fún ìsìn ilé Olúwa.

Every verse in 1 Chronicles 23

Chapter navigation

Biblica® ní oore ọ̀fẹ́ láti lo Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní™ / Biblica® Open Yoruba Contemporary Bible™ Copyright © 2009, 2017 by Biblica, Inc. “Biblica” is a trademark registered in the United States Patent and Trademark Office by Biblica, Inc. Used with permission. Licensed under CC BY-SA 4.0.

0:000:00