1 Chronicles 24:9
“ẹ̀karùnún sì ni Malkiah, ẹlẹ́ẹ̀kẹfà sì ni Mijamini,”
1 Chronicles 24:9 — Biblica® Open Yoruba Contemporary Bible
Verse 9 of 31 in 1 Chronicles chapter 24 — Biblica® Open Yoruba Contemporary Bible. Read it in context below, with maps, timelines and thematic connections beside the text.
1 Chronicles 24 — full chapter (Biblica® Open Yoruba Contemporary Bible)
Àwọn wọ̀nyí sì ni pínpín àwọn ọmọ . Àwọn ọmọ ni , , Eleasari àti . Ṣùgbọ́n àti kú kí ó tó di wí pé baba wọn kú, wọn kò sì ní àwọn ọmọ; bẹ́ẹ̀ ni àti sì ṣe gẹ́gẹ́ bí àlùfáà. Pẹ̀lú ìrànlọ́wọ́ ọmọ àti ọmọ , Dafidi sì yà wọ́n nípa nínú ìpín fún ìyàsọ́tọ̀ àwọn iṣẹ́ ìsìn wọn. A rí ọ̀pọ̀ àwọn olórí lára àwọn ọmọ ju lára àwọn ọmọ lọ, wọ́n sì pín wọn lẹ́sẹ lẹ́sẹ: mẹ́rìndínlógún olórí láti ìdílé ọmọ ìran wọn àti olórí méjọ ìdílé láti ara àwọn ọmọ . Wọ́n sì pín wọn láìṣègbè nípa yíya ìpín, nítorí àwọn olórí ibi mímọ́ àti àwọn olórí ilé Ọlọ́run wà láàrín àwọn ọmọ méjèèjì àti . Ṣemaiah ọmọ , akọ̀wé ọ̀kan lára àwọn ọmọ sì kọ orúkọ wọn níwájú ọba àti àwọn ìjòyè: Sadoku àlùfáà, Ahimeleki ọmọ àti olórí ìdílé àwọn àlùfáà tí a mú láti ọ̀dọ̀ àti ọ̀kan láti ọ̀dọ̀ . Ìpín èkínní jáde sí , èkejì sí , ẹlẹ́ẹ̀kẹta sì ni , ẹ̀kẹrin sì ní , ẹ̀karùnún sì ni , ẹlẹ́ẹ̀kẹfà sì ni , èkeje sì ni , ẹlẹ́ẹ̀kẹjọ sí ni , ẹ̀kẹsànán sì ni Jeṣua, ẹ̀kẹwàá sì ni Ṣekaniah, ẹ̀kọkànlá sì ni ṣibu, ẹlẹ́ẹ̀kẹjìlá sì ni , ẹ̀kẹtàlá sì ni , ẹlẹ́ẹ̀kẹrìnlá sì ni Jeṣebeabu, ẹ̀kẹdógún sì ni , ẹ̀kẹrìndínlógún sì ni , ẹ̀kẹtàdínlógún sì ni , èkejìdínlógún sì ni , ẹ̀kọkàndínlógún sì ni , ogún sì ni , ẹ̀kọkànlélógún sì ni , ẹ̀kẹrìnlélógún sì ni , ẹ̀kẹtàlélógún sì ni , ẹ̀kẹrìnlélógún sì ni . Àwọn wọ̀nyí ni a yàn fún iṣẹ́ ìsìn nígbà tí wọ́n wọ ilé Olúwa, gẹ́gẹ́ bí ìlànà àti àṣẹ tí a ti fi fún wọn láti ọwọ́ baba ńlá wọn gẹ́gẹ́ bí Olúwa, Ọlọ́run ẹli, tí pàṣẹ fun un. Ìyókù àwọn ọmọ . Láti ọ̀dọ̀ àwọn ọmọ : Ṣubaeli láti ọ̀dọ̀ àwọn ọmọ Ṣubaeli; Jehdeiah. Àti gẹ́gẹ́ bí , láti ọ̀dọ̀ àwọn ọmọ , Iṣiah sì ni alákọ́kọ́. Láti ọ̀dọ̀ àwọn ọmọ : Ṣelomiti; láti ọ̀dọ̀ àwọn ọmọ Ṣelomoti: Jahati. Àwọn ọmọ : Jeriah alákọ́kọ́, Amariah ẹlẹ́ẹ̀kejì, Jahasieli ẹlẹ́ẹ̀kẹta àti ẹlẹ́ẹ̀kẹrin. Àwọn ọmọ : Mika; nínú àwọn ọmọ : Ṣamiri. Àwọn arákùnrin : Iṣi; nínú àwọn ọmọ Iṣiah: Sekariah. Àwọn ọmọ : Mahili àti Muṣi. Àwọn ọmọ : Beno. Àwọn ọmọ . Láti : Beno, Ṣohamu, Sakkuri àti . Láti : Eleasari, ẹni tí kò ni àwọn ọmọ. Láti Kiṣi. Àwọn ọmọ Kiṣi: Jerahmeeli. Àti àwọn ọmọ Muṣi: Mahili, Ederi àti . Èyí ni àwọn ọmọ , gẹ́gẹ́ bí ìdílé wọn. Wọ́n sì ṣé kèké gẹ́gẹ́ bí àwọn arákùnrin wọn àwọn ọmọ ṣe ṣẹ́, níwájú ọba àti , Ahimeleki, àti olórí ìdílé àwọn àlùfáà àti àwọn ọmọ . Àwọn ìdílé àgbàgbà arákùnrin wọ́n sì ṣe bẹ́ẹ̀ lórí àwọn arákùnrin wọn kéékèèké.
Every verse in 1 Chronicles 24
Chapter navigation
Biblica® ní oore ọ̀fẹ́ láti lo Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní™ / Biblica® Open Yoruba Contemporary Bible™ Copyright © 2009, 2017 by Biblica, Inc. “Biblica” is a trademark registered in the United States Patent and Trademark Office by Biblica, Inc. Used with permission. Licensed under CC BY-SA 4.0.