1 Chronicles 25:23
“ẹlẹ́ẹ̀kẹrìndínlógún sí Hananiah, àwọn ọmọ rẹ̀ àti ìdílé rẹ̀ sì jẹ́, méjìlá”
1 Chronicles 25:23 — Biblica® Open Yoruba Contemporary Bible
Verse 23 of 31 in 1 Chronicles chapter 25 — Biblica® Open Yoruba Contemporary Bible. Read it in context below, with maps, timelines and thematic connections beside the text.
1 Chronicles 25 — full chapter (Biblica® Open Yoruba Contemporary Bible)
Pẹ̀lúpẹ̀lú àti àwọn olórí àwọn ọmọ-ogun, ó sì yà díẹ̀ sọ́tọ̀ lára àwọn ọmọ , Hemani àti fún ìsìn àsọtẹ́lẹ̀, pẹ̀lú dùùrù, ohun èlò orin olókùn àti kimbali. Èyí sì ní àwọn iye àwọn ọkùnrin ẹni tí ó ṣe íṣẹ́ ìsìn yìí. Nínú àwọn ọmọ : Sakkuri, Josẹfu, Netaniah àti , àwọn ọmọ ni wọ́n wà lábẹ́ ìbojútó , ẹni tí ó sọtẹ́lẹ̀ lábẹ́ ìbojútó ọba. Gẹ́gẹ́ bí ti , nínú àwọn ọmọkùnrin rẹ̀: Gedaliah, Seri, Jeṣaiah, Ṣimei, Haṣabiah àti , mẹ́fà nínú gbogbo wọn, lábẹ́ ìbojútó baba wọn , ẹni tí ó sọtẹ́lẹ̀, ẹni tí ó lo dùùrù láti dúpẹ́ àti láti yin Olúwa. Gẹ́gẹ́ bí ti , nínú àwọn ọmọ rẹ̀: Bukkiah, Mattaniah, Usieli, Ṣubaeli àti ; Hananiah, Hanani, Eliata, Giddalti, àti , Joṣbekaṣa, Malloti, Hotiri, Mahasiotu. Gbogbo àwọn wọ̀nyí sì ni ọmọ àti wòlíì ọba. Wọ́n sì fi wọ́n fún nípa ìlérí Ọlọ́run láti máa gbé ìwo sókè. Ọlọ́run sì fún ní ọmọkùnrin mẹ́rìnlá àti àwọn ọmọbìnrin mẹ́ta. Gbogbo àwọn ọkùnrin yìí ni wọ́n wà lábẹ́ ìbojútó àwọn baba wọn fún ohun èlò orin ilé Olúwa, pẹ̀lú kimbali, ohun èlò orin olókùn àti dùùrù, fún ìsìn ilé Olúwa. Asafu, Jedutuni àti sì wà lábẹ́ ọba. Àwọn ìdílé wọn pẹ̀lú gbogbo àwọn tí ó mòye àti àwọn tí a kọ́ ní ohun èlò orin fún Olúwa, iye wọn sì jẹ́ ọ̀rìnlélúgba ó lé mẹ́jọ (288). Kékeré àti àgbà bákan náà, olùkọ́ àti gẹ́gẹ́ bí ti akẹ́kọ̀ọ́, ṣẹ́ kèké fún iṣẹ́ wọn. Kèké èkínní èyí tí ó jẹ́ ti , jáde sí ẹfu, àwọn ọmọ rẹ̀ àti ìdílé rẹ̀ jẹ́, méjìlá èkejì sì ni , òun àti àwọn ìdílé rẹ̀ àti àwọn ọmọ rẹ̀, méjìlá ẹlẹ́ẹ̀kẹta sí , àwọn ọmọ rẹ̀ àti àwọn ìdílé, méjìlá ẹlẹ́ẹ̀kẹrin sí , àwọn ọmọ rẹ̀ àti àwọn ìdílé rẹ̀ jẹ́, méjìlá ẹlẹ́ẹ̀karùnún sí , àwọn ọmọ rẹ̀ àti àwọn ìdílé rẹ̀ jẹ́, méjìlá ẹlẹ́ẹ̀kẹfà sí , àwọn ọmọ rẹ̀ àti àwọn ìdílé rẹ̀ jẹ́, méjìlá ẹlẹ́ẹ̀keje sí , àwọn ọmọ rẹ̀ àti àwọn ìdílé rẹ̀ jẹ́, méjìlá ẹlẹ́ẹ̀kẹjọ sí Jeṣaiah, àwọn ọmọ rẹ̀ àti àwọn ìdílé rẹ̀ jẹ́, méjìlá ẹlẹ́ẹ̀kẹsàn-án sí , àwọn ọmọ rẹ̀ àti àwọn ìdílé rẹ̀ jẹ́, méjìlá ẹlẹ́ẹ̀kẹwàá sí Ṣimei, àwọn ọmọ rẹ̀ àti àwọn ìdílé rẹ̀ jẹ́, méjìlá ẹlẹ́ẹ̀kọkànlá sí , àwọn ọmọ rẹ̀ àti àwọn ìdílé rẹ̀ sì jẹ́, méjìlá ẹlẹ́ẹ̀kẹjìlá sí Haṣabiah, àwọn ọmọ rẹ̀ àti ìdílé rẹ̀ sì jẹ́, méjìlá ẹlẹ́ẹ̀kẹtàlá sí Ṣubaeli, àwọn ọmọ rẹ̀ àti ìdílé rẹ̀ sì jẹ́, méjìlá ẹlẹ́ẹ̀kẹrìnlá sí , àwọn ọmọ rẹ̀ àti ìdílé rẹ̀ sì jẹ́, méjìlá ẹlẹ́ẹ̀kẹẹ̀dógún sí , àwọn ọmọ rẹ̀ àti ìdílé rẹ̀ sì jẹ́, méjìlá ẹlẹ́ẹ̀kẹrìndínlógún sí , àwọn ọmọ rẹ̀ àti ìdílé rẹ̀ sì jẹ́, méjìlá ẹlẹ́ẹ̀kẹtàdínlógún sí Joṣbekaṣa, àwọn ọmọ rẹ̀ sì jẹ́, méjìlá ẹlẹ́ẹ̀kejìdínlógún sí , àwọn ọmọ rẹ̀ àti ìdílé rẹ̀ sì jẹ́, méjìlá ẹlẹ́ẹ̀kọkàndínlógún sí , àwọn ọmọ rẹ̀ àti ìdílé rẹ̀ sì jẹ́, méjìlá ogún sí , àwọn ọmọ rẹ̀ àti ìdílé rẹ̀ sì jẹ́, méjìlá ẹlẹ́ẹ̀kọkànlélógún sí , àwọn ọmọ rẹ̀ àti àwọn ìdílé rẹ̀ sì jẹ́, méjìlá ẹlẹ́ẹ̀kejìlélógún sí , àwọn ọmọ rẹ̀ àti àwọn ìdílé rẹ̀ sì jẹ́, méjìlá ẹlẹ́ẹ̀kẹtàlélógún sí , àwọn ọmọ rẹ àti ìdílé rẹ̀ sì jẹ́, méjìlá ẹlẹ́ẹ̀kẹrìnlélógún sí àwọn ọmọ rẹ̀, àti àwọn ìdílé rẹ̀ sì jẹ́, méjìlá.
Every verse in 1 Chronicles 25
Chapter navigation
Biblica® ní oore ọ̀fẹ́ láti lo Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní™ / Biblica® Open Yoruba Contemporary Bible™ Copyright © 2009, 2017 by Biblica, Inc. “Biblica” is a trademark registered in the United States Patent and Trademark Office by Biblica, Inc. Used with permission. Licensed under CC BY-SA 4.0.