1 Chronicles 27:28

“Baali-Hanani ará Gederi wà ní ìdí olifi àti àwọn igi sikamore ní apá ìhà ìwọ̀-oòrùn àwọn ní ẹ̀ṣẹ̀ pẹ̀tẹ́lẹ̀. Joaṣi wà ní ìdí fífún ni ní òróró olifi.”

1 Chronicles 27:28 — Biblica® Open Yoruba Contemporary Bible

Verse 28 of 34 in 1 Chronicles chapter 27 — Biblica® Open Yoruba Contemporary Bible. Read it in context below, with maps, timelines and thematic connections beside the text.

1 Chronicles 27 — full chapter (Biblica® Open Yoruba Contemporary Bible)

Wọ̀nyí ni ìwé àkójọ orúkọ àwọn ọmọ ẹli, àwọn olórí àwọn ìdílé, àwọn balógun ẹgbẹẹgbẹ̀rún àti àwọn balógun ọ̀rọ̀ọ̀rún àti àwọn ìjòyè wọn. Tí ó n sin ọba nínú gbogbo ohun tí ó kan ìpín àwọn ọmọ-ogun tí ó wà lẹ́nu iṣẹ́ ìsìn ní oṣooṣù ní gbogbo ọdún. Ìpín kọ̀ọ̀kan jẹ́ ẹgbàá méjìlá (24,000) ọkùnrin. Ní ti alákòóso lórí ìpín kìn-ín-ní fún oṣù kìn-ín-ní jẹ́ Jaṣobeamu ọmọ àwọn ọkùnrin ẹgbàá méjìlá (24,000) ní ó wà ní abẹ́ ìpín tirẹ̀. Ó jẹ́ ìran ọmọ àti olóyè fún gbogbo àwọn ìjòyè ológun fún oṣù kìn-ín-ní. Alákòóso fún ìpín àwọn ọmọ-ogun fún oṣù kejì jẹ́ ará ; Mikloti jẹ́ olórí ìpín tirẹ̀. Ọkùnrin ẹgbàá méjìlá (24,000) ni ó wà ní ìpín tirẹ̀. Olórí àwọn ọmọ-ogun ẹlẹ́ẹ̀kẹta fún oṣù kẹta jẹ́ ọmọ àlùfáà. Ó jẹ́ olóyè, àwọn ọkùnrin ẹgbàá méjìlá (24,000) ní ó wà ní ìpín tirẹ̀. Èyí ni náà tí ó jẹ́ ọkùnrin ńlá láàrín àwọn ọgbọ̀n àti lórí àwọn ọgbọ̀n. Ọmọ rẹ̀ jẹ́ alákòóso lórí ìpín tirẹ̀. Ẹlẹ́ẹ̀kẹrin fún oṣù kẹrin, jẹ́ arákùnrin : ọmọ rẹ̀ jẹ́ arọ́pò rẹ̀. Ẹgbàá méjìlá (24,000) ọkùnrin ni ó wà ní ìpín rẹ̀. Ẹ̀karùnún fún oṣù karùn-ún, jẹ́ olórí Ṣamhuti ará . Ẹgbàá méjìlá (24,000) ọkùnrin ní ó wà ní ìpín tirẹ̀. Ẹ̀kẹfà fún oṣù kẹfà jẹ́ ọmọ Ikẹsi, ará . Ọkùnrin ẹgbàá méjìlá (24,000) ni ó wà ní ìpín rẹ̀. Èkeje fún oṣù keje jẹ́ ará , ará . Ọkùnrin ẹgbàá méjìlá (24,000) ni o wà ní ìpín rẹ̀. Ẹ̀kẹjọ fún oṣù kẹjọ jẹ́ ará Huṣati, ará ọkùnrin ẹgbàá méjìlá (24,000) ni ó wà ní ìpín rẹ̀. Ẹ̀kẹsànán fún oṣù kẹsànán jẹ́. Abieseri ará , ará ọkùnrin ẹgbàá méjìlá (24,000) ni ó wà ní ìpín rẹ̀. Ẹ̀kẹwàá fún oṣù kẹwàá jẹ́ ará , ará ọkùnrin ẹgbàá méjìlá (24,000) ni ó wà ní ìpín rẹ̀. Ìkọkànlá fún oṣù kọkànlá jẹ́ ará ará ọkùnrin ẹgbàá méjìlá (24,000) ni ó wà ní ìpín tirẹ̀. Èkejìlá fún oṣù kejìlá jẹ́ ará láti ìdílé . Ẹgbàá méjìlá (24,000) ọkùnrin ni ó wà ní ìpín tirẹ̀. Àwọn ìjòyè lórí àwọn ẹ̀yà tí ẹli: lórí àwọn ará : Elieseri ọmọ ; lórí àwọn ọmọ : Ṣefatia ọmọ ; lórí : Haṣabiah ọmọ ; lórí : Sadoku; lórí : Elihu arákùnrin ; lórí : Omri ọmọ ; lórí : Iṣmaiah ọmọ ; lórí : Jerimoti ọmọ ; lórí àwọn ará : ọmọ ; lórí ààbọ̀ ẹ̀yà : Joẹli ọmọ ; lórí ààbọ̀ ẹ̀yà ní : Iddo ọmọ ; lórí : Jaasieli ọmọ ; lórí : Asareeli ọmọ . Wọ̀nyí ni àwọn ìjòyè lórí ẹ̀yà ẹli. Dafidi kò kọ iye àwọn ọkùnrin náà ní ogún ọdún sẹ́yìn tàbí dín nítorí Olúwa ti ṣe ìlérí láti ṣe ẹli gẹ́gẹ́ bí iye ìràwọ̀ ojú ọ̀run. Joabu ọmọ bẹ̀rẹ̀ sí ní kà wọ́n, ṣùgbọ́n kò parí kíkà wọ́n nítorí, ìbínú dé sórí àwọn ẹli nípasẹ̀ kíka iye àti iye náà, a kò kọ ọ́ sínú ìwé ìtàn ayé ti ọba . Asmafeti ọmọ wà ní ìdí ilé ìṣúra ti ọba. Jonatani ọmọ wà ní ìdí ilé ìṣúra ní iwájú agbègbè nínú àwọn ìlú, àwọn ìletò àti àwọn ilé ìṣọ́. Esri ọmọ wà ní ìdí àwọn òṣìṣẹ́ lórí pápá, tí wọ́n ń ko ilẹ̀ náà. Ṣimei ará wà ní ìdí àwọn ọgbà àjàrà. Sabdi ará wà ní ìdí mímú jáde ti èso àjàrà fún ọpọ́n ńlá tí a ń fi ọ̀tún èso àjàrà sí. Baali- ará wà ní ìdí olifi àti àwọn igi sikamore ní apá ìhà ìwọ̀-oòrùn àwọn ní ẹ̀ṣẹ̀ pẹ̀tẹ́lẹ̀. Joaṣi wà ní ìdí fífún ni ní òróró olifi. Ṣitrai ará Ṣaroni wà ní ìdí fífi ọwọ́ ẹran jẹ oko ní Ṣaroni. Ṣafati ọmọ wà ní ìdí àwọn ọ̀wọ́ ẹran ní àwọn pẹ̀tẹ́lẹ̀. Obili ará Iṣmaeli wà ní ìdí àwọn ìbákasẹ. Jehdeiah ará wà ní ìdí àwọn kẹ́tẹ́kẹ́tẹ́. Jasisi ará wà ní ìdí àwọn agbo ẹran. Gbogbo wọ̀nyí ni àwọn íṣẹ́ tí wọ́n wà ní ìdí ẹrù ọba . Jonatani, arákùnrin jẹ́ olùdámọ̀ràn, ọkùnrin ímọ̀ àti akọ̀wé. Jehieli ọmọ bojútó àwọn ọmọ ọba. Ahitofeli jẹ́ olùdámọ̀ràn ọba. Huṣ ará jẹ́ ọ̀rẹ́ ọba. (Jehoiada ọmọ àti nípasẹ̀ jẹ ọba rọ́pò .) jẹ́ olórí ọmọ-ogun ọba.

Every verse in 1 Chronicles 27

Chapter navigation

Biblica® ní oore ọ̀fẹ́ láti lo Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní™ / Biblica® Open Yoruba Contemporary Bible™ Copyright © 2009, 2017 by Biblica, Inc. “Biblica” is a trademark registered in the United States Patent and Trademark Office by Biblica, Inc. Used with permission. Licensed under CC BY-SA 4.0.

0:000:00