1 Chronicles 3:17
“Àwọn ọmọ Jekoniah tí a mú ní ìgbèkùn: Ṣealitieli ọmọ rẹ̀ ọkùnrin,”
1 Chronicles 3:17 — Biblica® Open Yoruba Contemporary Bible
Verse 17 of 24 in 1 Chronicles chapter 3 — Biblica® Open Yoruba Contemporary Bible. Read it in context below, with maps, timelines and thematic connections beside the text.
1 Chronicles 3 — full chapter (Biblica® Open Yoruba Contemporary Bible)
Àwọn wọ̀nyí sì ni ọmọ tí a bí fún un ní . Àkọ́bí sì ni ọmọ ti ; èkejì sì ni ẹli ọmọ ará ; ẹ̀kẹta sì ni ọmọ ọmọbìnrin ọba Geṣuri bí fún un; ẹ̀kẹrin sì ni ọmọ ; ẹ̀karùnún ni Ṣefatia láti ọ̀dọ̀ ; àti ẹ̀kẹfà, Itreamu, láti ọ̀dọ̀ aya rẹ̀. Àwọn mẹ́fà wọ̀nyí ni a bí fún ni , níbi tí ó ti jẹ ọba fún ọdún méje àti oṣù mẹ́fà. Dafidi sì jẹ ọba ní ẹmu fún ọdún mẹ́tàlélọ́gbọ̀n. Wọ̀nyí ni ọmọ wẹ́wẹ́ tí a bí fún un ní ẹmu: Ṣimea, Ṣobabu, Natani àti . Àwọn mẹ́rin wọ̀nyí sì ni a bí láti ọ̀dọ̀ -Ṣua ọmọbìnrin . Ibhari sì wà pẹ̀lú, ṣama, Elifeleti, Noga, Nefegi, Jafia, ṣama, Eliada àti mẹ́sàn-án ni wọ́n. Àwọn wọ̀nyí ni àwọn ọmọ yàtọ̀ sí àwọn ọmọ tí àlè bí fún un. Tamari sì ni arábìnrin wọn. Ọmọ ni , Abijah ọmọ rẹ̀, ọmọ rẹ̀, Jehoṣafati ọmọ rẹ̀, Jehoramu ọmọ rẹ̀, Ahasiah ọmọ rẹ̀, Joaṣi ọmọ rẹ̀, Amasiah ọmọ rẹ̀, Asariah ọmọ rẹ̀, Jotamu ọmọ rẹ̀, Ahasi ọmọ rẹ̀, Hesekiah ọmọ rẹ̀, Manase ọmọ rẹ̀, Amoni ọmọ rẹ̀, ọmọ rẹ̀. Àwọn ọmọ : àkọ́bí ọmọ rẹ̀ ni , èkejì ọmọ rẹ̀ ni , ẹ̀kẹta ọmọ rẹ̀ ni , ẹ̀kẹrin ọmọ rẹ̀ ni Ṣallumu. Àwọn ìran ọmọ : Jekoniah ọmọ rẹ̀, àti . Àwọn ọmọ tí a mú ní ìgbèkùn: Ṣealitieli ọmọ rẹ̀ ọkùnrin, Malkiramu, Pedaiah, Ṣenasari, Jekamiah, Hoṣama àti . Àwọn ọmọ : Serubbabeli àti Ṣimei. Àwọn ọmọ : Meṣullamu àti . Ṣelomiti ni arábìnrin wọn. Àwọn márùn-ún mìíràn sì tún wà: Haṣuba, Oheli, Berekiah, Hasadiah àti . Àwọn ọmọ : Pelatiah àti Jeṣaiah, àti àwọn ọmọ , ti , ti àti ti Ṣekaniah. Àwọn ọmọ Ṣekaniah: Ṣemaiah àti àwọn ọmọ rẹ̀: Hattusi, Igali, Bariah, Neariah àti Ṣafati, mẹ́fà ni gbogbo wọn. Àwọn ọmọ : Elioenai; Hesekiah, àti , mẹ́ta ni gbogbo wọn. Àwọn ọmọ : Hodafiah, Eliaṣibu, Pelaiah, Akkubu, Johanani, Delaiah àti , méje sì ni gbogbo wọn.
Every verse in 1 Chronicles 3
Chapter navigation
Biblica® ní oore ọ̀fẹ́ láti lo Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní™ / Biblica® Open Yoruba Contemporary Bible™ Copyright © 2009, 2017 by Biblica, Inc. “Biblica” is a trademark registered in the United States Patent and Trademark Office by Biblica, Inc. Used with permission. Licensed under CC BY-SA 4.0.