1 Chronicles 4:35

“Joẹli, Jehu ọmọ Josibiah, ọmọ Seraiah, ọmọ Asieli,”

1 Chronicles 4:35 — Biblica® Open Yoruba Contemporary Bible

Verse 35 of 43 in 1 Chronicles chapter 4 — Biblica® Open Yoruba Contemporary Bible. Read it in context below, with maps, timelines and thematic connections beside the text.

1 Chronicles 4 — full chapter (Biblica® Open Yoruba Contemporary Bible)

Àwọn ọmọ : Peresi, Hesroni, Karmi, Huri àti Ṣobali. Reaiah ọmọ Ṣobali ni baba , àti baba àti . Àwọn wọ̀nyí ni ẹ̀yà ará . Àwọn wọ̀nyí ni àwọn ọmọ : Jesreeli, Iṣima, Idbaṣi, orúkọ arábìnrin wọn sì ni Penueli sì ni baba , àti baba Huṣa. Àwọn wọ̀nyí ni ọmọ , àkọ́bí àti baba Bẹtilẹhẹmu. Aṣihuri baba sì ní aya méjì, Hela àti . Naara sì bí , Heferi àti ṣtari. Àwọn wọ̀nyí sì ni àwọn ọmọ . Àwọn ọmọ : Sereti , Etani, àti ẹni tí ó jẹ́ baba àti àti ti àwọn ẹ̀yà ọmọ . Jabesi sì ní ọlá ju àwọn ẹ̀gbọ́n rẹ̀ ọkùnrin lọ. Ìyá rẹ̀ sì sọ ọ́ ní wí pé, “Mo bí i nínú ìpọ́njú.” Jabesi sì kígbe sókè sí Ọlọ́run ẹli wí pé, “Háà, Ìwọ yóò bùkún fún mi, ìwọ yóò sì mú agbègbè mi tóbi! Jẹ́ kí ọwọ́ rẹ kí ó wà pẹ̀lú mi kí o sì pa mi mọ́ kúrò nínú ibi; kí èmi kí ó le ní ìdáǹdè kúrò nínú ìrora.” Ọlọ́run sì gbọ́ ohùn ẹ̀bẹ̀ rẹ̀. Kelubu arákùnrin Ṣuha, sì jẹ́ baba , ẹni tí ó jẹ́ baba Eṣtoni. Eṣtoni sì jẹ́ baba -, Pasea àti ti baba ìlú ṣi. Àwọn wọ̀nyí ni ọkùnrin . Àwọn ọmọ : Otnieli àti . Àwọn ọmọ : Hatati àti . Meonotai sì ni baba . Seraiah sì jẹ́ baba , baba ṣinu. A pè báyìí nítorí àwọn ènìyàn àwọn íṣọ̀nà ní ìwọ̀n. Àwọn ọmọ ọmọ : Iru, Ela, àti . Àwọn ọmọ : Kenasi. Àwọn ọmọ : Sifi, àti , Tiria àti . Àwọn ọmọ : Jeteri, Meredi, Eferi àti . Ọ̀kan lára àwọn aya sì bí , Ṣammai àti Iṣba baba Eṣitemoa. Aya rẹ̀ láti ẹ̀yà sì bí baba , àti baba àti baba . Àwọn wọ̀nyí ni àwọn ọmọ ọmọbìnrin , ẹni ti ti fẹ́. Àwọn ọmọ aya arábìnrin , baba ará , àti Eṣitemoa àwọn ará . Àwọn ọmọ Ṣimoni: Amnoni, Rina, Beni- àti . Àwọn ọmọ Iṣi: Soheti àti -. Àwọn ọmọ Ṣela ọmọ : Eri baba , Lada baba ṣa àti àwọn ìdílé ilé àwọn tí ń hun aṣọ íṣẹ́ ní -Aṣibea. Jokimu, ọkùnrin , àti ṣi àti , olórí ní àti Jaṣubi . (Àkọsílẹ̀ yìí sì wà láti ìgbà àtijọ́.) Àwọn sì ni amọ̀kòkò tí ń gbé ní àti ; wọ́n sì dúró níbẹ̀ wọ́n sì ń ṣiṣẹ́ fún ọba. Àwọn ọmọ : Nemueli, Jamini, Jaribi, Sera àti ; Ṣallumu sì jẹ́ ọmọ , Mibsamu ọmọ rẹ̀ Miṣima ọmọ rẹ̀. Àwọn ọmọ Miṣima: Hamueli ọmọ rẹ̀ ọmọ rẹ̀ àti Ṣimei ọmọ rẹ̀. Ṣimei sì ní ọmọkùnrin mẹ́rìndínlógún àti ọmọbìnrin mẹ́fà, ṣùgbọ́n àwọn ẹ̀gbọ́n rẹ̀ ọkùnrin kò ní ọmọ púpọ̀; bẹ́ẹ̀ ni àwọn ìdílé wọn kò sì pọ̀ gẹ́gẹ́ bí àwọn ènìyàn . Wọ́n sì ń gbé ní ṣeba, Molada, Hasari-Ṣuali, àti ní , àti ní , àti ní , Betueli, Horma, Siklagi, Beti- ; Hasari , Beti- àti Ṣaraimi. Àwọn wọ̀nyí ni ìlú wọn títí di ìgbà ọba , agbègbè ìlú wọn ni , Aini, Rimoni, Tokeni, Aṣani àwọn ìlú márùn-ún, àti gbogbo ìletò wọn, tí ó wà yí ìlú náà ká, dé . Àwọn wọ̀nyí ni ibùgbé wọn. Àti ìtàn ìdílé wọ́n. Meṣobabu àti , Josa ọmọ , Joẹli, ọmọ , ọmọ , ọmọ , àti pẹ̀lú , Jaakoba, Jeṣohaiah, Asaiah, Adieli, Jesimieli, Benaiah, àti ọmọ Ṣifi ọmọ , ọmọ , ọmọ Ṣimri ọmọ Ṣemaiah. Àwọn ọkùnrin tí a dárúkọ lókè yìí àwọn ni ìjòyè ìdílé wọn. Àwọn ìdílé sì pọ̀ sí i gidigidi, wọ́n sì lọ sí ojú ọ̀nà . Lọ títí dé ìlà-oòrùn àfonífojì láti wá koríko fún àwọn agbo ẹran wọn. Wọ́n sì rí koríko tútù tí ó dára ilẹ̀ náà gbòòrò ó sì ní àlàáfíà ó sì gbé jẹ́. Àwọn ọmọ ni ó ti ń gbé ibẹ̀ tẹ́lẹ̀tẹ́lẹ̀. Àwọn ọkùnrin tí a kọ orúkọ rẹ̀ sókè, dé ní ọjọ́ ọba . Wọ́n sì kọlu àwọn ará ní àgọ́ wọn àti pẹ̀lú àwọn ará tí a rí níbẹ̀ tí ó sì pa wọ́n run pátápátá títí di òní yìí. Wọ́n sì ń gbé ní ipò wọn, nítorí pé koríko ń bẹ níbẹ̀ fún agbo ẹran wọn. Ẹ̀ẹ́dẹ́gbẹ̀ta (500) nínú àwọn ará , lábẹ́ ìdarí pẹ̀lú , Neariah, Refaiah àti , àwọn ọmọ Iṣi, gbógun sí àwọn òkè ìlú ti . Wọ́n sì pa àwọn ará tí ó kù, àwọn tí ó ti sálà, wọ́n sì ti ń gbé ibẹ̀ títí di òní yìí.

Every verse in 1 Chronicles 4

Chapter navigation

Biblica® ní oore ọ̀fẹ́ láti lo Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní™ / Biblica® Open Yoruba Contemporary Bible™ Copyright © 2009, 2017 by Biblica, Inc. “Biblica” is a trademark registered in the United States Patent and Trademark Office by Biblica, Inc. Used with permission. Licensed under CC BY-SA 4.0.

0:000:00