1 Chronicles 5:11
“Àti àwọn ọmọ Gadi ń gbé lékè wọn, ní ilẹ̀ Baṣani títí dé Saleka:”
1 Chronicles 5:11 — Biblica® Open Yoruba Contemporary Bible
Verse 11 of 26 in 1 Chronicles chapter 5 — Biblica® Open Yoruba Contemporary Bible. Read it in context below, with maps, timelines and thematic connections beside the text.
1 Chronicles 5 — full chapter (Biblica® Open Yoruba Contemporary Bible)
Ǹjẹ́ àwọn ọmọ , àkọ́bí ẹli. (Nítorí òun ni àkọ́bí; ṣùgbọ́n, bí ó ti ṣe pé ó ba ibùsùn baba rẹ̀ jẹ́, a fi ogún ìbí rẹ̀ fún àwọn ọmọ ẹfu ọmọ ẹli: a kì yóò sì ka ìtàn ìdílé náà gẹ́gẹ́ bí ipò ìbí. Nítorí borí àwọn arákùnrin rẹ̀, àti lọ́dọ̀ rẹ̀ ni aláṣẹ ti ń jáde wá; ṣùgbọ́n ogún ìbí jẹ́ ti ẹfu), àwọn ọmọ àkọ́bí ẹli ni: Hanoku àti , Hesroni àti . Àwọn ọmọ Joẹli: Ṣemaiah ọmọ rẹ̀, Gogu ọmọ rẹ̀, Ṣimei ọmọ rẹ̀. Mika ọmọ rẹ̀, Reaiah ọmọ rẹ̀, Baali ọmọ rẹ̀. Beera ọmọ rẹ̀, tí - ọba kó ní ìgbèkùn lọ. Ìjòyè àwọn ọmọ ni jẹ́. Àti àwọn arákùnrin rẹ̀ nípa ìdílé wọn, nígbà tí a ń ka ìtàn ìdílé ìran wọn: Jeieli àti ni olórí, àti ọmọ ọmọ Ṣema, ọmọ Joẹli. Wọ́n tí ń gbé àní títí dé àti -. Àti níhà àríwá, o tẹ̀dó lọ títí dé àtiwọ aginjù láti odò ; nítorí tí ẹran ọ̀sìn wọn pọ̀ sí i ní ilẹ̀ . Àti ní ọjọ́ , wọ́n bá àwọn ọmọ jagun, ẹni tí ó ṣubú nípa ọwọ́ wọn; wọ́n sì ń gbé inú àgọ́ wọn ní gbogbo ilẹ̀ àríwá . Àti àwọn ọmọ ń gbé lékè wọn, ní ilẹ̀ Baṣani títí dé : Joẹli jẹ́ olórí, Ṣafamu ìran ọmọ , àti Ṣafati ni Baṣani. Àti àwọn arákùnrin wọn ti ilẹ̀ àwọn baba wọn ní: Mikaeli, Meṣullamu Ṣeba, Jorai, Jaka, Sia àti méje. Wọ̀nyí ni àwọn ọmọ , ọmọ , ọmọ , ọmọ , ọmọ , ọmọ Jeṣiṣ, ọmọ , ọmọ . Ahi, ọmọ , ọmọ , olórí ilé àwọn baba wọn. Wọ́n sì ń gbé ní Baṣani àti nínú àwọn ìlú rẹ̀, àti nínú gbogbo ìgbèríko Ṣaroni, ní agbègbè wọn. Gbogbo wọ̀nyí ni a kà nípa ìtàn ìdílé, ní ọjọ́ ọba , àti ní ọjọ́ ọba ẹli. Àwọn ọmọ , àti àwọn ọmọ , àti ààbọ̀ ẹ̀yà , nínú àwọn ọkùnrin alágbára tí wọ́n ń gbé asà àti idà, tí wọ́n sì ń fi ọrun tafà, tí wọ́n sì mòye ogun, jẹ́ ọ̀kẹ́ méjì ó lé ẹgbẹ̀rìnlélógún dín ogójì (47,760) ènìyàn, tí ó jáde lọ sí ogún náà. Wọ́n sì bá àwọn ọmọ jagun, pẹ̀lú , àti ṣi àti . Nígbà tí wọ́n sì rí ìrànlọ́wọ́ gbà si, a sì fi àwọn ọmọ lé wọn lọ́wọ́, àti gbogbo àwọn tí ó wà pẹ̀lú wọn; nítorí tiwọn ké pe Ọlọ́run ní ogun náà, òun sì gbọ́ ẹ̀bẹ̀ wọn; nítorí tí wọ́n gbẹ́kẹ̀ wọn lé e. Wọ́n sì kó ẹran ọ̀sìn wọn lọ; ìbákasẹ ẹgbàá mẹ́ẹ̀ẹ́dọ́gbọ̀n (50,000) àti àgùntàn ọ̀kẹ́ méjìlá ó lé ẹgbàárùn-ún (250,000), àti kẹ́tẹ́kẹ́tẹ́ ẹgbẹ̀rún méjì (2,000), àti ènìyàn ọ̀kẹ́ márùn-ún (100,000). Nítorí ọ̀pọ̀lọpọ̀ ni ó ṣubú tí a pa, nítorí láti ọ̀dọ̀ Ọlọ́run ni ogun náà, wọ́n sì jókòó ní ipò wọn títí di ìgbà ìkólọ sí ìgbèkùn. Àwọn ọmọkùnrin ààbọ̀ ẹ̀yà ń gbé ní ilẹ̀ náà: wọ́n bí sí i láti Baṣani títí dé -, àti àti títí dé òkè . Wọ̀nyí sì ni àwọn olórí ilé àwọn baba wọn. Eferi, Iṣi, Elieli, Asrieli, , Hodafiah àti àwọn alágbára akọni ọkùnrin, ọkùnrin olókìkí, àti olórí ilé àwọn baba wọn. Wọ́n sì ṣẹ̀ sí Ọlọ́run àwọn baba wọn, wọ́n sì ṣe àgbèrè tọ àwọn ọlọ́run ènìyàn ilẹ̀ náà lẹ́yìn, tí Ọlọ́run ti parun ní iwájú wọn. Nítorí náà Ọlọ́run ẹli ru ẹ̀mí ọba sókè (èyí ni - ọba ), ó si kó wọn lọ, àní àwọn ọmọ àti àwọn ọmọ , àti ààbọ̀ ẹ̀yà lọ sí ìgbèkùn. Ó sì kó wọn wá sí , àti , àti , àti sí etí odò ; títí dí òní yìí.
Every verse in 1 Chronicles 5
Chapter navigation
Biblica® ní oore ọ̀fẹ́ láti lo Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní™ / Biblica® Open Yoruba Contemporary Bible™ Copyright © 2009, 2017 by Biblica, Inc. “Biblica” is a trademark registered in the United States Patent and Trademark Office by Biblica, Inc. Used with permission. Licensed under CC BY-SA 4.0.