1 Chronicles 6:76

“Pẹ̀lú láti ẹ̀yà Naftali wọ́n gba Kedeṣi ní Galili, Hammoni àti Kiriataimu, lápapọ̀ pẹ̀lú pápá oko tútù ilẹ̀ wọn.”

1 Chronicles 6:76 — Biblica® Open Yoruba Contemporary Bible

Verse 76 of 81 in 1 Chronicles chapter 6 — Biblica® Open Yoruba Contemporary Bible. Read it in context below, with maps, timelines and thematic connections beside the text.

1 Chronicles 6 — full chapter (Biblica® Open Yoruba Contemporary Bible)

Àwọn ọmọ : Gerṣoni, Kohati àti . Àwọn ọmọ : Amramu, Isari, Hebroni, àti . Àwọn ọmọ : Aaroni, Mose àti . Àwọn ọmọkùnrin : Nadabu, , Eleasari àti . Eleasari jẹ́ baba , Finehasi baba ṣua Abiṣua baba , Bukki baba , Ussi baba , Serahiah baba , Meraioti baba , Amariah baba Ahitubu baba , Sadoku baba , Ahimasi baba , Asariah baba , Johanani baba . (Òhun ni ó sìn gẹ́gẹ́ bí àlùfáà nínú ilé Olúwa tí kọ́ sí ẹmu). Asariah baba baba Ahitubu baba . Sadoku baba Ṣallumu, Ṣallumu baba , Hilkiah baba , Asariah baba , pẹ̀lú baba . A kó lẹ́rú nígbà tí Olúwa lé àti ẹmu kúrò ní ìlú nípasẹ̀ . Àwọn ọmọ : Gerṣoni, Kohati àti . Wọ̀nyí ni àwọn orúkọ àwọn ọmọ ṣoni: Libni àti Ṣimei. Àwọn ọmọ : Amramu, Isari, Hebroni àti . Àwọn ọmọ : Mahili àti Muṣi. Wọ̀nyí ni àwọn ìdílé ará tí a kọ ní ṣísẹ̀-n-tẹ̀lé gẹ́gẹ́ bí baba wọn. Ti ṣoni: Libni ọmọkùnrin rẹ̀, Jahati. Ọmọkùnrin rẹ̀, Simma ọmọkùnrin rẹ̀, Joah ọmọkùnrin rẹ̀, Iddo ọmọkùnrin rẹ̀, Sera ọmọkùnrin rẹ̀ àti ọmọkùnrin rẹ̀. Àwọn ìran ọmọ : Amminadabu ọmọkùnrin rẹ̀, Kora ọmọkùnrin rẹ̀, Asiri ọmọkùnrin rẹ̀. Elkana ọmọkùnrin rẹ̀, Ebiasafi ọmọkùnrin rẹ̀, Asiri ọmọkùnrin rẹ̀. Tahati ọmọkùnrin rẹ̀, Urieli ọmọkùnrin rẹ̀, Ussiah ọmọkùnrin rẹ̀ àti ọmọkùnrin rẹ̀. Àwọn ìran ọmọ : Amasai, Ahimoti Elkana ọmọ rẹ̀, Sofai ọmọ rẹ̀ ọmọ rẹ̀, Eliabu ọmọ rẹ̀, Jerohamu ọmọ rẹ̀, Elkana ọmọ rẹ̀ àti ẹli ọmọ rẹ̀. Àwọn ọmọ ẹli: Joẹli àkọ́bí àti ọmọ ẹlẹ́ẹ̀kejì. Àwọn ìran ọmọ : Mahili, Libni ọmọ rẹ̀. Ṣimei ọmọ rẹ̀, Ussa ọmọ rẹ̀. Ṣimea ọmọ rẹ̀, Haggiah ọmọ rẹ̀ àti ọmọ rẹ̀. Èyí ní àwọn ọkùnrin tí a fi sí ìdí orin nínú ilé Olúwa lẹ́yìn tí àpótí ẹ̀rí ti wá láti sinmi níbẹ̀. Wọ́n jíṣẹ́ pẹ̀lú orin níwájú àgọ́ ìpàdé títí tí fi kọ́ ilé Olúwa ní ẹmu. Wọ́n ṣe iṣẹ́ ìsìn wọn ní ìbámu pẹ̀lú ìlànà tí a fi lélẹ̀ fún wọn. Wọ̀nyí ni àwọn ọkùnrin tí ó sìn pẹ̀lú ọmọ wọn. Láti ọ̀dọ̀ àwọn ará : Hemani olùkọrin, ọmọ Joẹli, ọmọ ẹli, ọmọ , ọmọ , ọmọ , ọmọ , ọmọ , ọmọ , ọmọ , ọmọ , ọmọ , ọmọ Joẹli, ọmọ , ọmọ , ọmọ , ọmọ , ọmọ , ọmọ , ọmọ , ọmọ , ọmọ , ọmọ ẹli; Hemani sì darapọ̀ mọ́ , ẹni tí o sìn ní ọwọ́ ọ̀tún rẹ̀: Asafu ọmọ , ọmọ Ṣimea, ọmọ , ọmọ , ọmọ ọmọ , ọmọ , ọmọ , ọmọ , ọmọ , ọmọ Ṣimei, ọmọ , ọmọ ṣoni, ọmọ ; láti ìbákẹ́gbẹ́ wọn, àwọn ará wà ní ọwọ́ òsì rẹ̀: Etani ọmọ Kiṣi, ọmọ , ọmọ , ọmọ Haṣabiah, ọmọ , ọmọ , ọmọ , ọmọ , ọmọ Ṣemeri, ọmọ , ọmọ Muṣi, ọmọ , ọmọ . Àwọn ẹgbẹ́ wọn ni wọn yan àwọn iṣẹ́ yòókù ti àgọ́ fún, èyí tí í ṣe ilé Ọlọ́run. Ṣùgbọ́n àti àwọn ìran ọmọ rẹ̀ jẹ́ àwọn tí ó gbé ọrẹ kalẹ̀ lórí pẹpẹ ẹbọ sísun àti lórí pẹpẹ tùràrí ní ìbátan pẹ̀lú gbogbo ohun tí a ṣe ní Mímọ́ Jùlọ. Ṣíṣe ètùtù fún ẹli, ní ìbámu pẹ̀lú gbogbo ohun tí ìránṣẹ́ Ọlọ́run ti pàṣẹ. Wọ̀nyí ni àwọn ìránṣẹ́ : Eleasari ọmọ rẹ̀, Finehasi ọmọ rẹ̀, Abiṣua ọmọ rẹ̀, Bukki ọmọ rẹ̀, Ussi ọmọ rẹ̀, Serahiah ọmọ rẹ̀, Meraioti ọmọ rẹ̀, Amariah ọmọ rẹ̀, Ahitubu ọmọ rẹ̀, Sadoku ọmọ rẹ̀ àti ọmọ rẹ̀. Wọ̀nyí ni ibùgbé wọn tí a pín fún wọn gẹ́gẹ́ bí agbègbè wọn (tí a fi lé àwọn ìran ọmọ lọ́wọ́ tí ó wá láti ẹ̀yà , nítorí kèké alákọ́kọ́ jẹ́ tiwọn). A fún wọn ní ní pẹ̀lú àyíká pápá oko tútù ilẹ̀ rẹ̀. Ṣùgbọ́n àwọn pápá àti ìletò tí ó yí ìlú ńlá náà ká ni a fi fún ọmọ . Bẹ́ẹ̀ ni àwọn ìran ọmọ ni a fún ní (ìlú ti ààbò), àti , Jattiri, Eṣitemoa, Hileni, Debiri, Aṣani, Jutta àti -Ṣemeṣi lápapọ̀ pẹ̀lú pápá oko tútù ilẹ̀ rẹ̀. Àti láti inú ẹ̀yà , a fún wọn ní , Geba, Alemeti àti lápapọ̀ pẹ̀lú pápá oko tútù ilẹ̀ wọn. Àwọn ìlú wọ̀nyí, tí a pín láàrín àwọn ẹ̀yà jẹ́ mẹ́tàlá ní gbogbo rẹ̀. Ìyókù àwọn ìran ọmọ ní a pín ìlú mẹ́wàá fún láti àwọn ìdílé ní ti ààbọ̀ ẹ̀yà . Àwọn ìran ọmọ ṣoni, sí ìdílé ni a pín ìlú mẹ́tàlá fún láti ẹ̀yà àwọn ẹ̀yà , Aṣeri àti , àti láti apá ẹ̀yà tí ó wà ní Baṣani. Sebuluni àwọn ìran ọmọ , ìdílé sí ìdílé, ní a pín ìlú méjìlá fún láti ẹ̀yà , Gadi àti . Bẹ́ẹ̀ ni àwọn ọmọ ẹli fún àwọn ará ní ìlú wọ̀nyí pẹ̀lú pápá oko tútù ilẹ̀ wọn. Láti ẹ̀yà , Simeoni àti ni a pín ìlú tí a ti dárúkọ wọn sẹ́yìn fún. Lára àwọn ìdílé ni a fún ní ìlú láti ẹ̀yà gẹ́gẹ́ bí ìlú agbègbè wọn. Ní òkè orílẹ̀-èdè , a fún wọn ní Ṣekemu (ìlú ńlá ti ààbò), àti Jokimeamu, Beti-. Aijaloni àti - lápapọ̀ pẹ̀lú pápá oko tútù ilẹ̀ wọn. Pẹ̀lú láti apá ààbọ̀ ẹ̀yà àwọn ọmọ ẹli fún àti lápapọ̀ pẹ̀lú pápá oko tútù ilẹ̀ wọn, fún ìyókù àwọn ìdílé . Àwọn ará ṣoni gbà nǹkan wọ̀nyí. Láti ààbọ̀ ẹ̀yà ti wọ́n gba ní Baṣani àti pẹ̀lú Aṣtarotu, lápapọ̀ pẹ̀lú pápá oko tútù wọn. Láti ẹ̀yà wọ́n gba ṣi, Daberati Ramoti àti , lápapọ̀ pẹ̀lú pápá oko tútù ilẹ̀ wọn. Láti ẹ̀yà Aṣeri wọ́n gba Maṣali, Abdoni, Hukoki àti lápapọ̀ pẹ̀lú pápá oko tútù ilẹ̀ wọn. Pẹ̀lú láti ẹ̀yà wọ́n gba ṣi ní , Hammoni àti , lápapọ̀ pẹ̀lú pápá oko tútù ilẹ̀ wọn. Àwọn ará (ìyókù àwọn ará ) gbà nǹkan wọ̀nyí. Láti ẹ̀yà wọ́n gba , Karta, Rimoni àti , lápapọ̀ pẹ̀lú ilẹ̀ pápá oko tútù wọn. Láti ẹ̀yà rékọjá ìlà-oòrùn wọ́n gba nínú aginjù , Kedemoti àti , lápapọ̀ pẹ̀lú ilẹ̀ pápá oko tútù wọn. Pẹ̀lú láti ẹ̀yà wọ́n gba ní , Heṣboni àti lápapọ̀ pẹ̀lú àwọn ilẹ̀ pápá oko tútù wọn.

Every verse in 1 Chronicles 6

Chapter navigation

Biblica® ní oore ọ̀fẹ́ láti lo Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní™ / Biblica® Open Yoruba Contemporary Bible™ Copyright © 2009, 2017 by Biblica, Inc. “Biblica” is a trademark registered in the United States Patent and Trademark Office by Biblica, Inc. Used with permission. Licensed under CC BY-SA 4.0.

0:000:00