1 Chronicles 7:14

“Àwọn ìran ọmọ Manase: Asrieli jẹ́ ìran ọmọ rẹ̀ ní ipasẹ̀ àlè rẹ̀ ará Aramu ó bí Makiri baba Gileadi.”

1 Chronicles 7:14 — Biblica® Open Yoruba Contemporary Bible

Verse 14 of 40 in 1 Chronicles chapter 7 — Biblica® Open Yoruba Contemporary Bible. Read it in context below, with maps, timelines and thematic connections beside the text.

1 Chronicles 7 — full chapter (Biblica® Open Yoruba Contemporary Bible)

Àwọn ọmọ : Tola, Pua, Jaṣubu àti Ṣimroni, mẹ́rin ni gbogbo rẹ̀. Àwọn ọmọ : Ussi, Refaiah, Jehieli, Jamai, Ibsamu àti ẹli olórí àwọn ìdílé wọn. Ní àkókò ìjọba, Dafidi, àwọn ìran ọmọ tò lẹ́sẹẹsẹ gẹ́gẹ́ bí àwọn ọkùnrin alágbára ní ìtàn ìdílé láti ọ̀dọ̀ baba ńlá wọn, tí iye wọn sì jẹ́ ẹgbẹ̀rún méjìlélógún ó lé ẹgbẹ̀ta (22,600). Àwọn ọmọ, Ussi: Israhiah. Àwọn ọmọ : Mikaeli, , Joẹli àti Iṣiah. Gbogbo àwọn márààrún sì jẹ́ olóyè. Gẹ́gẹ́ bí ìtàn ìdílé wọn láti ọ̀dọ̀ baba ńlá wọn, wọ́n ní ọkùnrin ẹgbàá mẹ́rìndínlógójì (36,000) tí ó ti ṣe tan fún ogun, nítorí wọ́n ní ọ̀pọ̀ àwọn ọmọ àti ìyàwó. Àwọn ìbátan tí ó jẹ́ alágbára akọni àwọn ọkùnrin tí ó jẹ́ ti àwọn ìdílé , bí a ti tò ó lẹ́sẹẹsẹ nínú ìtàn ìdílé láti ọ̀dọ̀ baba ńlá wọn jẹ́ ẹgbàá mẹ́tàdínláàádọ́rin (87,000) ni gbogbo rẹ̀. Àwọn ọmọ mẹ́ta : Bela, Bekeri àti . Àwọn ọmọ : Esboni, Ussi, Usieli, Jerimoti àti , àwọn márààrún. Àwọn ni olórí ilé baba ńlá wọn, akọni alágbára ènìyàn. A sì ka iye wọn nípa ìran wọn sí ẹgbẹ̀rún méjìlélógún ó lé mẹ́rìnlélọ́gbọ̀n (22,034) ènìyàn. Àwọn ọmọ : Semirahi, Joaṣi, Elieseri, Elioenai, Omri, Jeremoti, Abijah, Anatoti àti . Gbogbo wọ̀nyí jẹ́ ọmọ . Ìtàn ìdílé wọn láti ọ̀dọ̀ baba ńlá wọn tí a kọ lẹ́sẹẹsẹ jẹ́ ti àwọn olórí ìdílé àti ẹgbẹ̀rún ní ọ̀nà ogún ó lé nígba (20,200) ọkùnrin alágbára. Ọmọ : Bilhani. Àwọn ọmọ : Jeuṣi , Ehudu, Kenaana, Setamu, Tarṣiṣi àti ṣahari. Gbogbo àwọn ọmọ jẹ́ olórí. Àwọn ẹgbẹ̀rún mẹ́tàdínlógún ó lé nígba (17,200) akọni ọkùnrin ni ó ti ṣetán láti jáde lọ sí ogun. Àti Ṣuppimu, àti , àwọn ọmọ , àti Huṣimu, àwọn ọmọ . Àwọn ọmọ : Jasieli, Guni, Jeseri àti Ṣallumu—ọmọ rẹ̀ nípa . Àwọn ìran ọmọ : Asrieli jẹ́ ìran ọmọ rẹ̀ ní ipasẹ̀ àlè rẹ̀ ará ó bí baba . Makiri sì mú ìyàwó láti àárín àwọn ará àti Ṣuppimu. Orúkọ arábìnrin rẹ̀ a máa jẹ́ . Orúkọ ìran ọmọ mìíràn a máa jẹ́ , tí ó ní àwọn ọmọbìnrin nìkan ṣoṣo. Maaka, ìyàwó bí ọmọkùnrin kan. Ó sì sọ orúkọ rẹ̀ ní . Ó sì pe arákùnrin rẹ̀ ní Ṣereṣi, àwọn ọmọ rẹ̀ sì ní àti . Ọmọ : Bedani. Wọ̀nyí ni àwọn ọmọ ọmọ , ọmọ . Arábìnrin rẹ̀. Hamoleketi bí Iṣhodi, Abieseri àti . Àwọn ọmọ Ṣemida sì jẹ́: Ahiani, Ṣekemu, Likki àti . Àwọn ìran ọmọ : Ṣutelahi, Beredi ọmọkùnrin rẹ̀, Tahati ọmọ rẹ̀, Eleadah ọmọ rẹ̀. Tahati ọmọ rẹ̀ Sabadi ọmọ, rẹ̀, àti Ṣutelahi ọmọ rẹ̀. Eseri àti ni a pa nípasẹ̀ àwọn ọkùnrin bíbí ìbílẹ̀ nígbà tí wọ́n sọ̀kalẹ̀ lọ láti lọ fi agbára mú ohun ọ̀sìn wọn Efraimu baba wọn ṣọ̀fọ̀ fún wọn ní ọjọ́ púpọ̀, àwọn ìbátan rẹ̀ wá láti tù ú nínú. Nígbà náà, ó sùn pẹ̀lú, ìyàwó rẹ̀, ó sì lóyún ó sì bí ọmọkùnrin kan. Ó sì sọ ọ́ ní nítorí òfò ti wà nínú ìdílé náà. Ọmọbìnrin rẹ̀ sì jẹ́ Ṣerah, ẹni tí ó kọ́ ìsàlẹ̀ àti òkè - àti -Ṣerah pẹ̀lú. Refa jẹ́ ọmọ rẹ̀, Resefi ọmọ rẹ̀, Tela ọmọ rẹ̀, Tahani ọmọ rẹ̀, Laadani ọmọ rẹ̀ ọmọ rẹ̀, ṣama ọmọ rẹ̀, Nuni ọmọ rẹ̀ àti Joṣua ọmọ rẹ̀. Ilẹ̀ wọn àti ìfìdíkalẹ̀ wọn ni àti àwọn ìletò tí ó yíká, Narani lọ sí ìhà ìlà-oòrùn, Geseri àti àwọn ìletò rẹ̀ lọ sí ìhà ìwọ̀-oòrùn àti Ṣekemu àti àwọn ìletò rẹ̀ ní ọ̀nà lọ sí àti àwọn ìletò. Lẹ́gbẹ̀ ìpínlẹ̀ ti ni -Ṣeani, Taanaki, Megido àti lápapọ̀ pẹ̀lú àwọn ìletò rẹ̀. Àwọn ìran ọmọ ẹfu ọmọ ẹli ń gbé nínú ìlú wọ̀nyí. Àwọn ọmọ Aṣeri: Imina, Iṣifa, Iṣfi àti . Arábìnrin wọn sì jẹ́ . Àwọn ọmọ : Heberi àti , tí ó jẹ́ baba . Heberi jẹ́ baba , Ṣomeri àti àti ti arábìnrin wọn Ṣua. Àwọn ọmọ : Pasaki, Bimhali àti . Wọ̀nyí ni àwọn ọmọ . Àwọn ọmọ Ṣomeri: Ahi, Roga, Jahuba àti . Àwọn ọmọ arákùnrin rẹ̀ , Imina, Ṣeleṣi àti . Àwọn ọmọ : Sua, Haniferi, Ṣuali, Beri, Imra. Beseri, Hodi, Ṣamma, Ṣilisa, Itrani àti . Àwọn ọmọ : Jefunne, Pisifa àti . Àwọn ọmọ : Arah, Hannieli àti . Gbogbo wọ̀nyí jẹ́ ìran ọmọ Aṣeri—olórí ìdílé, àṣàyàn ọkùnrin, alágbára jagunjagun àti olórí nínú àwọn ìjòyè. Iye àwọn tí a kà yẹ fún ogun, gẹ́gẹ́ bí à ti ṣe kọ ọ́ lẹ́sẹẹsẹ nínú ìtàn ìdílé wọn jẹ́ ẹgbàá mẹ́tàlá (26,000) ọkùnrin.

Every verse in 1 Chronicles 7

Chapter navigation

Biblica® ní oore ọ̀fẹ́ láti lo Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní™ / Biblica® Open Yoruba Contemporary Bible™ Copyright © 2009, 2017 by Biblica, Inc. “Biblica” is a trademark registered in the United States Patent and Trademark Office by Biblica, Inc. Used with permission. Licensed under CC BY-SA 4.0.

0:000:00