1 Chronicles 8:29

“Jeieli, baba Gibeoni ń gbé ní Gibeoni. Ìyàwó o rẹ̀ a má jẹ́ Maaka,”

1 Chronicles 8:29 — Biblica® Open Yoruba Contemporary Bible

Verse 29 of 40 in 1 Chronicles chapter 8 — Biblica® Open Yoruba Contemporary Bible. Read it in context below, with maps, timelines and thematic connections beside the text.

1 Chronicles 8 — full chapter (Biblica® Open Yoruba Contemporary Bible)

Benjamini jẹ́ baba: Bela àkọ́bí rẹ̀, Aṣbeli ọmọkùnrin ni ẹ̀ẹ̀kejì, Ahara ẹ̀ẹ̀kẹ́ta, Noha ẹ̀ẹ̀kẹrin àti ẹ̀karùnún. Àwọn ọmọ ni, Adari, Gera, Abihudi, Abiṣua, Naamani, Ahoa, Gera, Ṣefufani àti . Wọ̀nyí ni àwọn ìran ọmọ , tí wọ́n jẹ́ olórí àwọn ìdílé tí ó ń gbé ní tí a sì lé kúrò lọ sí : Naamani àti , tí ó lé wọn kúrò ní ìlú, àti tí ó sì jẹ́ baba àti . A bí àwọn ọmọkùnrin fún Ṣaharaimu ní lẹ́yìn tí ó ti kọ àwọn ìyàwó rẹ̀ sílẹ̀, Huṣimu àti . Nípasẹ̀ ìyàwó rẹ̀ ṣi ó ní , Meṣa, Malkamu, Jeusi, Sakia àti . Wọ̀nyí ni àwọn ọmọkùnrin rẹ̀, olórí àwọn ìdílé. Nípasẹ̀ Huṣimu ó ní àti . Àwọn ọmọ : Eberi, Miṣamu, Ṣemedu (ẹni tí ó kọ́ àti pẹ̀lú àwọn ìletò àyíká rẹ̀.) Pẹ̀lú àti Ṣema, tí wọ́n jẹ́ olórí àwọn ìdílé ti àwọn tí ó ń gbé ní àti àwọn tí ó lé àwọn olùgbé kúrò. Ahio, Ṣasaki, Jeremoti, Sebadiah, Aradi, Ederi Mikaeli, Iṣifa àti jẹ́ àwọn ọmọ . Sebadiah, Meṣullamu, Hiski, Heberi Iṣimerai, Isiliahi àti jẹ́ àwọn ọmọ . Jakimu, Sikri, Sabdi, Elienai, Siletai, Elieli, Adaiah, Beraiah àti Ṣimrati jẹ́ àwọn ọmọ, Ṣimei. Iṣipani , Elieli, Abdoni, Sikri, Hanani, Hananiah, Elamu, Anitotijah, Ifediah àti jẹ́ àwọn ọmọ Ṣasaki. Ṣamṣerai, Ṣeharaiah, Ataliah Jareṣiah, àti jẹ́ àwọn ọmọ . Gbogbo àwọn wọ̀nyí jẹ́ olórí àwọn ìdílé, olóyè gẹ́gẹ́ bí a ti kọ ọ́ lẹ́sẹẹsẹ nínú ìtàn ìran wọn, wọ́n sì ń gbé ní ẹmu. Jeieli, baba ń gbé ní . Ìyàwó o rẹ̀ a má jẹ́ , àkọ́bí rẹ̀ a sì máa jẹ́ wọ̀nyí sì ń tẹ̀lé , Kiṣi, Baali, Neri, Nadabu, Gedori , Sekeri pẹ̀lú , tí ó jẹ́ baba Ṣimea. Wọ́n ń gbé ní ẹ̀bá ìbátan wọn ní ẹmu. Neri jẹ́ baba Kiṣi, Kiṣi baba àti baba , Malikiṣua, Abinadabu àti Eṣi-. Ọmọ : Meribu- tí ó jẹ́ baba . Àwọn ọmọ : Pitoni, Meleki, Tarea, àti . Ahasi jẹ́ baba a , Jeheada jẹ́ baba a , Asmafeti àti , Simri sì jẹ́ baba . Mosa jẹ́ baba ; Rafa sì jẹ́ ọmọ rẹ̀, Eleasa ọmọ rẹ̀ àti ọmọ rẹ̀. Aseli ní ọmọ mẹ́fà pẹ̀lú wọ̀nyí ni orúkọ wọn: Asrikamu, Bokeru, Iṣmaeli, Ṣeariah, àti . Gbogbo wọ̀nyí ni ọmọ . Àwọn ọmọ arákùnrin rẹ̀ : Ulamu àkọ́bí rẹ̀, Jeuṣi ọmọkùnrin ẹ̀ẹ̀kejì àti ẹ̀ẹ̀kẹ́ta. Àwọn ọmọ jẹ́ ògboyà jagunjagun tí ó lè gbá orin mú. Wọ́n ní ọ̀pọ̀ ọmọkùnrin àti ọmọ ọmọkùnrin áàdọ́jọ ní gbogbo rẹ̀. Gbogbo wọ̀nyí ni àwọn ìdílé ìran ọmọ .

Every verse in 1 Chronicles 8

Chapter navigation

Biblica® ní oore ọ̀fẹ́ láti lo Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní™ / Biblica® Open Yoruba Contemporary Bible™ Copyright © 2009, 2017 by Biblica, Inc. “Biblica” is a trademark registered in the United States Patent and Trademark Office by Biblica, Inc. Used with permission. Licensed under CC BY-SA 4.0.

0:000:00