1 Chronicles 9:44

“Aseli ní ọmọ mẹ́fà, pẹ̀lú wọ̀nyí ni orúkọ wọn: Asrikamu, Bokeru, Iṣmaeli Ṣeariah, Obadiah àti Hanani, gbogbo wọ̀nyí ni ọmọ Aseli.”

1 Chronicles 9:44 — Biblica® Open Yoruba Contemporary Bible

Verse 44 of 44 in 1 Chronicles chapter 9 — Biblica® Open Yoruba Contemporary Bible. Read it in context below, with maps, timelines and thematic connections beside the text.

1 Chronicles 9 — full chapter (Biblica® Open Yoruba Contemporary Bible)

Gbogbo ẹli ni a kọ lẹ́sẹẹsẹ nínú ìtàn ìdílé láti ọ̀dọ̀ àwọn baba ńlá nínú ìwé àwọn ọba ẹli. Àwọn ènìyàn ni a kó ní ìgbèkùn lọ sí nítorí àìṣòótọ́ wọn. Nísinsin yìí, àwọn tí ó kọ́kọ́ tún tẹ̀dó lórí ohun ìní wọn ní ìlú wọn ni díẹ̀ nínú àwọn ọmọ ẹli, àwọn àlùfáà, àwọn ará àti àwọn ìránṣẹ́ ilé Olúwa. Àwọn tí ó wá láti láti àti láti àti tí ó ń gbé ní ẹmu jẹ́: Uttai ọmọ , ọmọ , ọmọ , ọmọ , ìran ọmọ ọmọ . Àti nínú ará Ṣilo: Asaiah àkọ́bí àti àwọn ọmọ rẹ̀. Ní ti ará : Jeueli. Àwọn ènìyàn láti sì jẹ́ ẹ̀ẹ́dẹ́gbẹ̀rin ó dín mẹ́wàá (690). Àti nínú àwọn ọmọ ni: Sallu ọmọ Meṣullamu, ọmọ ; ọmọ ; Ibinaiah ọmọ ; Ela ọmọ , ọmọ ; àti Meṣullamu ọmọ Ṣefatia; ọmọ , ọmọ . Àwọn ènìyàn láti gẹ́gẹ́ bí a ti ṣe kọ ọ́ nínú ìran wọn nínú ìtàn ìdílé láti ọ̀dọ̀ baba ńlá wọn, tí ó jẹ́ ẹgbẹ̀rún ó dín mẹ́rìnlélógójì (956). Gbogbo àwọn ọkùnrin yí jẹ́ àwọn olórí àwọn ìdílé. Ní ti àwọn àlùfáà: Jedaiah; Jehoiaribi; Jakini; Asariah ọmọ , ọmọ Meṣullamu, ọmọ , ọmọ , ọmọ , olórí tí ó ń bojútó ilé Ọlọ́run; Adaiah ọmọ , ọmọ Paṣuri, ọmọ ; àti ọmọ , ọmọ , ọmọ Meṣullamu ọmọ Meṣilemiti, ọmọ . Àwọn àlùfáà, tí wọ́n jẹ́ àwọn olórí àwọn ìdílé, tí ó jẹ́ ẹgbẹ̀sán ó dín méjì (1,760). Wọ́n jẹ́ alágbára ọkùnrin, tí wọ́n lè dúró fún iṣẹ́ ìránṣẹ́ nínú ilé Ọlọ́run. Ní ti àwọn ará : Ṣemaiah ọmọ Haṣubu, ọmọ , ọmọ Haṣabiah ará ; Bakibakari, Hereṣi, Galali àti , ọmọ , ọmọ , ọmọ ; ọmọ Ṣemaiah, ọmọ , ọmọ ; àti ọmọ , ọmọ , tí ó ń gbé nínú àwọn ìlú àwọn ará . Àwọn olùtọ́jú ẹnu-ọ̀nà: Ṣallumu, Akkubu, Talmoni, Ahimani àti arákùnrin wọn, Ṣalumu olóyè wọn, ti wà ní ipò ìdúró ní ẹnu-ọ̀nà ọba ní apá ìhà ìlà-oòrùn títí di àkókò yí. Wọ̀nyí ni àwọn olùtọ́jú ẹnu-ọ̀nà tí ó jẹ́ ti ìpàgọ́ àwọn ará . Ṣallumu ọmọ ọmọ , ọmọ , àti àwọn olùtọ́jú ẹnu-ọ̀nà ẹlẹgbẹ́ rẹ̀. Láti ìdílé rẹ̀ (àwọn ará ) ni ó dúró fún ṣíṣọ́ ìloro ẹnu-ọ̀nà àgọ́ gẹ́gẹ́ bí baba wọn ti ń dúró fún ṣíṣọ́ àbáwọlé ibùgbé Olúwa. Ní ìgbà àkọ́kọ́ ọmọ jẹ́ olórí fún àwọn olùtọ́jú ẹnu-ọ̀nà, Olúwa sì wà pẹ̀lú rẹ̀. Sekariah, ọmọ Meṣelemiah jẹ́ olùtọ́jú ẹnu-ọ̀nà ní àbáwọlé sí àgọ́ ibi ìpàdé. Gbogbo rẹ̀ lápapọ̀, àwọn tí a yàn láti jẹ́ olùtọ́jú ẹnu-ọ̀nà ní àwọn ìloro jẹ́ igba ó lé méjìlá (212). A ka àwọn wọ̀nyí nípa ìdílé ní ìletò wọn. Àwọn olùtọ́jú ẹnu-ọ̀nà ni a ti yàn sí ipò láti ọ̀dọ̀ àti ẹli, aríran, nítorí òtítọ́ wọn. Àwọn àti àwọn ọmọ wọn ni ó wà fún ṣíṣọ́ ẹnu-ọ̀nà ilé Olúwa ilé tí a pè ní àgọ́. Àwọn olùtọ́jú ẹnu-ọ̀nà wà ní igun mẹ́rẹ̀ẹ̀rin: ìlà-oòrùn, ìwọ̀-oòrùn àríwá àti gúúsù. Àwọn arákùnrin wọn ní àwọn ìletò wọn ní láti wá ní àkókò dé àkókò láti pín iṣẹ́ ìsìn wọn fún àkókò ọjọ́ méje. Ṣùgbọ́n àwọn olórí alábojútó ẹnu-ọ̀nà mẹ́rẹ̀ẹ̀rin tí wọ́n jẹ́ ará ni a yàn fún àwọn iyàrá àti àwọn àpótí ìṣúra ní ilé Ọlọ́run. Wọ́n á lo gbogbo òru ní dídúró yí ilé Ọlọ́run ká, nítorí wọ́n ní láti ṣọ́ ọ, wọ́n sì ní àṣẹ sí kọ́kọ́rọ́ fún ṣíṣí i ní àràárọ̀. Díẹ̀ wà ní ìdí ohun èlò tí à ń lò fún ìsìn ilé Ọlọ́run; wọn a máa kà á nígbà tí wọ́n gbé e wọlé àti nígbà tí a kó wọn jáde. Àwọn mìíràn ni a yàn láti bojútó ohun èlò àti gbogbo ohun èlò ilé tí a yà sọ́tọ̀ fún Ọlọ́run, àti ìyẹ̀fun àti ọtí èso àjàrà àti òróró náà, tùràrí àti tùràrí olóòórùn dídùn. Ṣùgbọ́n díẹ̀ nínú àwọn àlùfáà ni ó ń bojútó pípò tùràrí olóòórùn dídùn papọ̀. Ará tí a sọ ní àkọ́bí ọmọkùnrin Ṣallumu ará ni a yàn, tí ń ṣe alábojútó ohun tí a dín. Àti nínú àwọn arákùnrin wọn, nínú àwọn ọmọ tó ń ṣe ìtọ́jú àkàrà ìfihàn, láti máa pèsè rẹ̀ ní ọjọọjọ́ ìsinmi. Àwọn tí wọ́n jẹ́ ọkùnrin, olórí àwọn ìdílé dúró nínú àgọ́ ilé Olúwa, wọn kò sì ṣe lára iṣẹ́ ìsìn yòókù nítorí wọ́n ń ṣe iṣẹ́ náà lọ́sàn, lóru. Gbogbo wọ̀nyí jẹ́ olórí àwọn , olóyè gẹ́gẹ́ bí a ti ṣe kọ lẹ́sẹẹsẹ sínú ìtàn ìdílé láti ọ̀dọ̀ baba ńlá wọn, wọ́n sì ń gbé ní ẹmu. Jeieli baba ń gbé ní . Orúkọ ìyàwó rẹ̀ a máa jẹ́ , pẹ̀lú àkọ́bí ọmọkùnrin rẹ̀ jẹ́ , tí wọ̀nyí sì ń tẹ̀lé , Kiṣi, Baali, Neri, Nadabu. Gedori, Ahio, Sekariah àti . Mikiloti jẹ́ baba Ṣimeamu, àwọn náà ń gbé ní ẹ̀bá ìbátan wọn ní ẹmu. Neri jẹ́ baba Kiṣi, Kiṣi baba a , àti baba a , àti ṣua, Abinadabu àti Eṣi-. Ọmọ : Meribu-, tí ó jẹ́ baba . Àwọn ọmọ : Pitoni. Meleki, Tarea àti . Ahasi jẹ́ baba , Jada jẹ́ baba , Asmafeti, Simri, sì jẹ́ baba . Mosa jẹ́ baba ; Refaiah jẹ́ ọmọ rẹ̀, Eleasa ọmọ rẹ̀ àti ọmọ rẹ̀. Aseli ní ọmọ mẹ́fà, pẹ̀lú wọ̀nyí ni orúkọ wọn: Asrikamu, Bokeru, Iṣmaeli Ṣeariah, àti , gbogbo wọ̀nyí ni ọmọ .

Every verse in 1 Chronicles 9

Chapter navigation

Biblica® ní oore ọ̀fẹ́ láti lo Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní™ / Biblica® Open Yoruba Contemporary Bible™ Copyright © 2009, 2017 by Biblica, Inc. “Biblica” is a trademark registered in the United States Patent and Trademark Office by Biblica, Inc. Used with permission. Licensed under CC BY-SA 4.0.

0:000:00