1 Kings 1:49

“Nígbà náà ni gbogbo àwọn àlejò tí ó wà lọ́dọ̀ Adonijah dìde ní ìdágìrì, wọ́n sì túká.”

1 Kings 1:49 — Biblica® Open Yoruba Contemporary Bible

Verse 49 of 53 in 1 Kings chapter 1 — Biblica® Open Yoruba Contemporary Bible. Read it in context below, with maps, timelines and thematic connections beside the text.

1 Kings 1 — full chapter (Biblica® Open Yoruba Contemporary Bible)

Nígbà tí ọba di arúgbó, ọjọ́ rẹ̀ sì pọ̀, ara rẹ̀ kò le è móoru bí ó tilẹ̀ jẹ́ pé wọ́n da ọ̀pọ̀lọpọ̀ aṣọ bò ó. Nígbà náà ni àwọn ìránṣẹ́ rẹ̀ wí fún un pé, “Ẹ jẹ́ kí a wá ọ̀dọ́mọbìnrin wúńdíá kan kí ó dúró ti ọba, kì ó sì máa tọ́jú rẹ̀. Kí ó dùbúlẹ̀ ní àyà rẹ̀ kí ara ọba olúwa wa lè móoru.” Nígbà náà ni wọ́n lọ jákèjádò ilẹ̀ ẹli láti wá ọ̀dọ́mọbìnrin arẹwà, wọ́n sì rí ṣagi, ará Ṣunemu, wọ́n sì mú un wá sí ọ̀dọ̀ ọba. Ọmọbìnrin náà rẹwà gidigidi; ó sì ń ṣe ìtọ́jú ọba, ó sì ń ṣe ìránṣẹ́ fún un, ṣùgbọ́n ọba kò sì bá a lòpọ̀. ẹni tí ìyá rẹ̀ ń ṣe sì gbé ara rẹ̀ ga, ó sì wí pé, “Èmi yóò jẹ ọba.” Ó sì ṣètò kẹ̀kẹ́ ogun àti àwọn ẹlẹ́ṣin, pẹ̀lú àádọ́ta ọkùnrin láti máa sáré níwájú rẹ̀. (Baba rẹ̀ kò bà á nínú jẹ́ rí nípa bíbéèrè lọ́wọ́ rẹ̀ pé, “Èéṣe tí ìwọ fi hùwà báyìí?” Ó sì jẹ́ arẹwà ọkùnrin, òun ni a bí lé .) sì gbèrò pẹ̀lú , ọmọ àti àlùfáà, wọ́n sì ṣe ìrànlọ́wọ́ fún un. Ṣùgbọ́n àlùfáà, Benaiah ọmọ , Natani wòlíì, Ṣimei àti ọ̀rẹ́ rẹ̀ àti olórí ogun ni kò darapọ̀ mọ́ . Nígbà náà ni fi àgùntàn àti màlúù àti ẹran ọ̀sìn tí ó sanra rú ẹbọ níbi Òkúta tí ń bẹ lẹ́gbẹ̀ẹ́ En-. Ó sì pe gbogbo àwọn arákùnrin rẹ̀, àwọn ọmọ ọba, àti gbogbo àwọn ọkùnrin tí wọ́n jẹ́ ìránṣẹ́ ọba. Ṣùgbọ́n kò pe wòlíì tàbí tàbí àwọn olórí tàbí arákùnrin rẹ̀. Nígbà náà ni béèrè lọ́wọ́ ṣeba, ìyá pé, “Ǹjẹ́ ìwọ kò gbọ́ pé , ọmọ ti jẹ ọba láìjẹ́ pé olúwa wa mọ̀ sí i? Ǹjẹ́ nísinsin yìí, jẹ́ kí èmi gbà ọ́ ní ìmọ̀ràn bí ìwọ ṣe lè gba ẹ̀mí rẹ là àti ẹ̀mí ọmọ rẹ . Lọ sọ́dọ̀ ọba, kí o sì wí fún un pé, ‘Olúwa mi ọba, ǹjẹ́ ìwọ kò búra fún ìránṣẹ́ rẹ pé, “Dájúdájú ọmọ rẹ ni yóò jọba lẹ́yìn mi, yóò sì jókòó lórí ìtẹ́ mi?” Èéṣe nígbà náà tí fi jẹ ọba?’ Níwọ́n ìgbà tí ìwọ sì wà níbẹ̀, tí o sì ń bá ọba sọ̀rọ̀ èmi yóò wá, láti wádìí ohun tí o ti sọ.” Bẹ́ẹ̀ ni ṣeba lọ rí ọba ní inú yàrá rẹ̀, ọba sì gbó gidigidi níbi tí ṣagi ará Ṣunemu ti ń ṣe ìránṣẹ́ fún ọba. Batṣeba sì tẹríba, ó sì kúnlẹ̀ níwájú ọba. Ọba sì béèrè pé, “Kí ni ìwọ ń fẹ́?” Ó sì wí fún ọba pé, “Olúwa mi; ìwọ fúnra rẹ̀ fi Olúwa Ọlọ́run rẹ búra fún ìránṣẹ́ rẹ pé, ‘Solomoni ọmọ rẹ yóò jẹ ọba lẹ́yìn mi, yóò sì jókòó lórí ìtẹ́ mi.’ Ṣùgbọ́n nísinsin yìí, ti di ọba, ìwọ, ọba olúwa mi kò sì mọ̀ nípa rẹ̀. Òun sì ti fi ọ̀pọ̀lọpọ̀ màlúù, àti ẹran tí ó ní ọ̀rá, àti àgùntàn rú ẹbọ, ó sì pe gbogbo àwọn ọmọ ọba, àti àlùfáà àti balógun, ṣùgbọ́n kò sì pe ìránṣẹ́ rẹ. Olúwa mi ọba, ojú gbogbo ẹli ń bẹ lára rẹ, láti mọ ẹni tí yóò jókòó lórí ìtẹ́ olúwa mi ọba lẹ́yìn rẹ. Bí kò ṣe bẹ́ẹ̀ nígbà tí olúwa mi ọba bá sùn pẹ̀lú àwọn baba rẹ̀, wọn yóò sì ka èmi àti sí ẹlẹ́ṣẹ̀.” Bí ó sì ti ń bá ọba sọ̀rọ̀ lọ́wọ́, Natani wòlíì sì wọlé. Wọ́n sì sọ fún ọba pé, “Natani wòlíì wà níbí.” Ó sì lọ síwájú ọba, ó wólẹ̀, ó sì dojúbolẹ̀. Natani sì wí pé, “Ǹjẹ́ ìwọ, olúwa mi ọba, ti sọ pé ni yóò jẹ ọba lẹ́yìn rẹ àti pé òun ni yóò jókòó lórí ìtẹ́ rẹ? Ó sì ti sọ̀kalẹ̀ lọ ní òní, ó sì ti rú ẹbọ ọ̀pọ̀lọpọ̀ màlúù, àti ẹran ọlọ́ràá àti àgùntàn. Ó sì ti pe gbogbo àwọn ọmọ ọba, balógun àti àlùfáà. Nísìnsinyìí, wọ́n ń jẹ, wọ́n ń mu pẹ̀lú rẹ̀, wọ́n sì wí pé, ‘Kí ọba kí ó pẹ́!’ Ṣùgbọ́n èmi ìránṣẹ́ rẹ, àti àlùfáà, àti ọmọ , àti ìránṣẹ́ rẹ ni kò pè. Ṣé nǹkan yìí ni olúwa mi ọba ti ṣe láìjẹ́ kí àwọn ìránṣẹ́ rẹ mọ ẹni tí yóò jókòó lórí ìtẹ́ olúwa mi ọba lẹ́yìn rẹ?” Nígbà náà ni ọba wí pé, “Pe ṣeba wọlé wá.” Ó sì wá síwájú ọba, ó sì dúró níwájú rẹ̀. Ọba sì búra pé, “Dájúdájú bí Olúwa ti wà ẹni tí ó ti gbà mí kúrò nínú gbogbo wàhálà Lónìí dandan ni èmi yóò gbé ohun tí mo ti fi Olúwa Ọlọ́run ẹli búra fún yọ pé, Solomoni ọmọ rẹ ni yóò jẹ ọba lẹ́yìn mi, àti pé yóò jókòó lórí ìtẹ́ mi ní ipò mi.” Nígbà náà ni ṣeba tẹríba, ó sì kúnlẹ̀ níwájú ọba pé, “Kí olúwa mi ọba kí ó pẹ́!” Dafidi ọba sì wí pé, “Ẹ pe àlùfáà wọlé fún mi àti wòlíì àti ọmọ .” Nígbà tí wọ́n wá síwájú ọba, ọba sì wí fún wọn pé, “Ẹ mú àwọn ìránṣẹ́ olúwa yín pẹ̀lú yín kí ẹ sì mú kí ọmọ mi kí ó gun ìbáaka mi, kí ẹ sì mú un sọ̀kalẹ̀ wá sí . Níbẹ̀ ni àlùfáà àti wòlíì yóò ti fi òróró yàn án ní ọba lórí ẹli. Ẹ fọn fèrè, kí ẹ sì ké pé, ‘Kí ọba kí ó pẹ́!’ Nígbà náà ni kí ẹ sì gòkè pẹ̀lú rẹ̀, kí ó sì wá, kí ó sì jókòó sórí ìtẹ́ mi, kí ó sì jẹ ọba ní ipò mi. Èmi ti yàn án ní ọba lórí gbogbo ẹli àti .” Benaiah ọmọ sì dá ọba lóhùn pé, “Àmín! Kí Olúwa Ọlọ́run olúwa mi ọba, kéde rẹ̀ bẹ́ẹ̀. Bí Olúwa ti wà pẹ̀lú olúwa mi ọba, bẹ́ẹ̀ ni kí ó wà pẹ̀lú kí ó lè mú kí ìjọba rẹ̀ pẹ́ ju ìtẹ́ olúwa mi ọba lọ!” Nígbà náà ni àlùfáà, Natani wòlíì, Benaiah ọmọ , àwọn ará àti sì sọ̀kalẹ̀ wá wọ́n sì gbé gun ìbáaka ọba wá sí . Sadoku àlùfáà sì mú ìwo òróró láti inú àgọ́, ó sì dà á sí lórí. Nígbà náà ni wọ́n sì fọn fèrè, gbogbo àwọn ènìyàn sì ké pé, “Kí ọba kí ó pẹ́!” Gbogbo ènìyàn sì gòkè tọ̀ ọ́ lẹ́yìn wọ́n ń fọn ìpè, wọ́n sì ń yọ ayọ̀ ńlá, tó bẹ́ẹ̀ tí ilẹ̀ mì fún ìró wọn. àti gbogbo àwọn àlejò tí ó wà lọ́dọ̀ rẹ̀ gbọ́ ọ́ bí wọ́n ti ń jẹun tán, wọ́n ń gbọ́ ìpè, Joabu sì wí pé, “Kí ní ìtumọ̀ gbogbo ariwo nínú ìlú yìí?” Bí ó sì ti ń sọ̀rọ̀ lọ́wọ́, Jonatani ọmọ àlùfáà sì dé, sì wí pé, “Wọlé wá, ọkùnrin yíyẹ ìwọ gbọdọ̀ mú ìròyìn rere wá.” Jonatani sì dáhùn, ó sì wí fún pé, “Lóòótọ́ ni olúwa wa ọba, fi jẹ ọba. Ọba sì ti rán àlùfáà, Natani wòlíì, Benaiah ọmọ àti àwọn ará àti pẹ̀lú rẹ̀, wọ́n sì ti gbé e gun ìbáaka ọba, Sadoku àlùfáà àti wòlíì ti fi òróró yàn án ní ọba ní . Láti ibẹ̀ ni wọ́n ti gòkè wá pẹ̀lú ayọ̀, ìlú sì ń hó pẹ̀lú rẹ̀. Èyí ni ariwo tí ẹ̀yin ń gbọ́. Solomoni sì ti jókòó lórí ìtẹ́ ìjọba rẹ̀. Àwọn ìránṣẹ́ ọba sì ti tún wá láti bá olúwa wa ọba yọ̀, wí pé, ‘Kí Ọlọ́run rẹ̀ mú orúkọ lókìkí ju tirẹ̀ lọ àti kí ìtẹ́ rẹ̀ kí ó pọ̀ ju tirẹ̀ lọ!’ Ọba sì tẹ ara rẹ̀ ba lórí ibùsùn rẹ̀, ọba sì wí pé, ‘Ògo ni fún Olúwa Ọlọ́run ẹli, ẹni tí ó ti jẹ́ kí ojú mi rí ẹnìkan tí ó jókòó lórí ìtẹ́ mi lónìí.’ ” Nígbà náà ni gbogbo àwọn àlejò tí ó wà lọ́dọ̀ dìde ní ìdágìrì, wọ́n sì túká. Ṣùgbọ́n sì bẹ̀rù , ó lọ, ó sì di ìwo pẹpẹ mú. Nígbà náà ni a sì sọ fún pé, “ bẹ̀rù ọba, ó sì di ìwo pẹpẹ mú, Ó wí pé, ‘Jẹ́ kí ọba búra fún mi lónìí pé, òun kì yóò fi idà pa ìránṣẹ́ rẹ̀.’ ” Solomoni sì dáhùn pé, “Bí ó bá fi ara rẹ̀ hàn láti jẹ́ ẹni ọ̀wọ̀, irun orí rẹ̀ kan kì yóò sì bọ́ sílẹ̀; ṣùgbọ́n bí a bá rí búburú kan ní ọwọ́ rẹ̀ òun yóò kú.” Nígbà náà ni ọba rán àwọn ènìyàn, wọ́n sì mú un sọ̀kalẹ̀ láti ibi pẹpẹ wá. sì wá, ó sì foríbalẹ̀ fún ọba, Solomoni sì wí pé, “Lọ ilé rẹ.”

Every verse in 1 Kings 1

Chapter navigation

Biblica® ní oore ọ̀fẹ́ láti lo Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní™ / Biblica® Open Yoruba Contemporary Bible™ Copyright © 2009, 2017 by Biblica, Inc. “Biblica” is a trademark registered in the United States Patent and Trademark Office by Biblica, Inc. Used with permission. Licensed under CC BY-SA 4.0.

0:000:00