1 Kings 11:2

“Wọ́n wá láti orílẹ̀-èdè tí Olúwa ti wí fún àwọn ọmọ Israẹli pé, “Ẹ̀yin kò gbọdọ̀ fẹ́ wọn níyàwó tàbí ní ọkọ, nítorí wọn yóò yí ọkàn yín padà sí òrìṣà wọn.” Síbẹ̀síbẹ̀ Solomoni fàmọ́ wọn ní ìfẹ́.”

1 Kings 11:2 — Biblica® Open Yoruba Contemporary Bible

Verse 2 of 43 in 1 Kings chapter 11 — Biblica® Open Yoruba Contemporary Bible. Read it in context below, with maps, timelines and thematic connections beside the text.

1 Kings 11 — full chapter (Biblica® Open Yoruba Contemporary Bible)

Solomoni ọba fẹ́ ọ̀pọ̀ àjèjì obìnrin yàtọ̀ sí ọmọbìnrin , àwọn ọmọbìnrin , àti ti , ti , ti àti ti àwọn ọmọ . Wọ́n wá láti orílẹ̀-èdè tí Olúwa ti wí fún àwọn ọmọ ẹli pé, “Ẹ̀yin kò gbọdọ̀ fẹ́ wọn níyàwó tàbí ní ọkọ, nítorí wọn yóò yí ọkàn yín padà sí òrìṣà wọn.” Síbẹ̀síbẹ̀ fàmọ́ wọn ní ìfẹ́. Ó sì ní ẹ̀ẹ́dẹ́gbẹ̀rin (700) obìnrin, àwọn ọmọ ọba àti ọ̀ọ́dúnrún (300) àlè, àwọn ìyàwó rẹ̀ sì yí i ní ọkàn padà. Bí sì ti di arúgbó, àwọn ìyàwó rẹ̀ sì yí i ní ọkàn padà sí ọlọ́run mìíràn, ọkàn rẹ̀ kò sì ṣe déédé pẹ̀lú Olúwa Ọlọ́run rẹ̀, gẹ́gẹ́ bí ọkàn baba rẹ̀ ti ṣe. Solomoni tọ Aṣtoreti òrìṣà àwọn ará lẹ́yìn, àti òrìṣà ìríra àwọn ọmọ . Bẹ́ẹ̀ ni ṣe búburú níwájú Olúwa; kò sì tọ Olúwa lẹ́yìn ní pípé, bí baba rẹ̀ ti ṣe. Lórí òkè tí ń bẹ níwájú ẹmu, Solomoni kọ́ ibi gíga kan fún ṣi, òrìṣà ìríra , àti fún , òrìṣà ìríra àwọn ọmọ . Bẹ́ẹ̀ ni ó sì ṣe bẹ́ẹ̀ fún gbogbo àwọn àjèjì obìnrin rẹ̀, ẹni tí ń sun tùràrí, tí wọ́n sì ń rú ẹbọ fún òrìṣà wọn. Olúwa bínú sí nítorí ọkàn rẹ̀ ti yípadà kúrò lọ́dọ̀ Olúwa Ọlọ́run ẹli, tí ó ti fi ara hàn án lẹ́ẹ̀méjì. Bí o tilẹ̀ jẹ́ pé ó ti kìlọ̀ fún kí ó má ṣe tọ àwọn ọlọ́run mìíràn lẹ́yìn, ṣùgbọ́n kò pa àṣẹ Olúwa mọ́. Nítorí náà Olúwa wí fún pé, “Nítorí bí ìwọ ti ṣe nǹkan yìí, tí ìwọ kò sì pa májẹ̀mú mi àti àṣẹ mi mọ́, tí mo ti pàṣẹ fún ọ, dájúdájú èmi yóò fa ìjọba ya kúrò lọ́wọ́ rẹ, èmi yóò sì fi fún ẹlòmíràn. Ṣùgbọ́n, nítorí baba rẹ, Èmi kì yóò ṣe é ní ọjọ́ rẹ. Èmi yóò fà á ya kúrò lọ́wọ́ ọmọ rẹ. Síbẹ̀ èmi kì yóò fa gbogbo ìjọba náà ya, ṣùgbọ́n èmi yóò fi ẹ̀yà kan fún ọmọ rẹ nítorí ìránṣẹ́ mi, àti nítorí ẹmu tí èmi ti yàn.” Nígbà náà ni Olúwa gbé ọ̀tá kan dìde sí , Hadadi ará ìdílé ọba ni ó ti wá ní . Ó sì ṣe, nígbà tí wà ní , Joabu olórí ogun sì gòkè lọ láti sin àwọn ọmọ-ogun ẹli ti a pa lójú ogun, ó sì pa gbogbo ọkùnrin . Nítorí àti gbogbo ẹli sì dúró níbẹ̀ fún oṣù mẹ́fà, títí wọ́n fi pa gbogbo ọkùnrin run. Ṣùgbọ́n sálọ sí pẹ̀lú àwọn ará tí wọ́n jẹ́ ìránṣẹ́ baba rẹ̀. Hadadi sì wà ní ọmọdé nígbà náà. Wọ́n sì dìde kúrò ní , wọ́n sì lọ sí . Nígbà náà ni wọ́n mú ènìyàn pẹ̀lú wọn láti wá, wọ́n sì lọ sí , sọ́dọ̀ ọba ẹni tí ó fún ní ilé àti ilẹ̀, ó sì fún un ní oúnjẹ. Inú sì dùn sí púpọ̀ tí ó fi fún un ní arábìnrin aya rẹ̀ ní aya, arábìnrin , ayaba. Arábìnrin bí ọmọkùnrin kan fún un tí à ń pe orúkọ rẹ̀ ní , ẹni tí tọ́ dàgbà ní ààfin ọba. Níbẹ̀ ni ń gbé pẹ̀lú àwọn ọmọ fúnra rẹ̀. Nígbà tí ó sì wà ní , Hadadi sì gbọ́ pé ti sùn pẹ̀lú àwọn baba rẹ̀, àti pé olórí ogun sì ti kú pẹ̀lú. Nígbà náà ni wí fún pé, “Jẹ́ kí n lọ, kí èmi kí ó le padà sí ìlú mi.” Farao sì wí fún un pé, “Kí ni ìwọ ṣe aláìní níbí, tí ìwọ fi fẹ́ padà lọ sí ìlú rẹ?” sì wí pé, “Kò sí nǹkan, ṣùgbọ́n sá à jẹ́ kí èmi kí ó lọ!” Ọlọ́run sì gbé ọ̀tá mìíràn dìde sí , Resoni ọmọ , ẹni tí ó ti sá kúrò lọ́dọ̀ olúwa rẹ̀, ọba . Ó sì kó ènìyàn jọ sọ́dọ̀ ara rẹ̀, ó sì di olórí ogun ẹgbẹ́ kan, nígbà tí fi pa ogun run; wọ́n sì lọ sí , wọ́n ń gbé ibẹ̀, wọ́n sì jẹ ọba ní . Resoni sì jẹ́ ọ̀tá ẹli ní gbogbo ọjọ́ , ó ń pa kún ibi ti ṣe. Bẹ́ẹ̀ ni jẹ ọba ní , ó sì ṣòdì sí ẹli. Bákan náà ọmọ sì ṣọ̀tẹ̀ sí ọba. Ó sì jẹ́ ọ̀kan lára àwọn ìránṣẹ́ , ará ti , ìyá rẹ̀ sì jẹ́ opó, orúkọ rẹ̀ ni . Èyí sì ni ìdí tí ó fi ṣọ̀tẹ̀ sí ọba: Solomoni kọ́ , ó sì di ẹ̀yà ìlú baba rẹ̀. Jeroboamu jẹ́ ọkùnrin alágbára, nígbà tí sì rí bí ọ̀dọ́mọkùnrin náà ti ṣe iṣẹ́ rẹ̀ dáradára, ó fi í ṣe olórí iṣẹ́ ìrú ilé ẹfu. Ó sì ṣe, ní àkókò náà ń jáde kúrò ní ẹmu. Wòlíì ti Ṣilo sì pàdé rẹ̀ lójú ọ̀nà, ó sì wọ agbádá tuntun. Àwọn méjèèjì nìkan ni ó sì ń bẹ ní oko, Ahijah sì gbá agbádá tuntun tí ó wọ̀ mú, ó sì fà á ya sí ọ̀nà méjìlá. Nígbà náà ni ó sọ fún pé, “Mú ọ̀nà mẹ́wàá fún ara rẹ, nítorí báyìí ni Olúwa Ọlọ́run ẹli wí pé, ‘Wò ó, èmi yóò fa ìjọba náà ya kúrò ní ọwọ́ , èmi yóò sì fi ẹ̀yà mẹ́wàá fún ọ. Ṣùgbọ́n nítorí ti ìránṣẹ́ mi àti nítorí ẹmu, ìlú tí mo ti yàn nínú gbogbo ẹ̀yà ẹli, òun yóò ní ẹ̀yà kan. Èmi yóò ṣe èyí nítorí tí wọ́n ti kọ̀ mí sílẹ̀, wọ́n sì ti sin Aṣtoreti òrìṣà àwọn ará , Kemoṣi òrìṣà àwọn ará , àti òrìṣà àwọn ọmọ , wọn kò sì rìn ní ọ̀nà mi, tàbí ṣe èyí tí ó dára lójú mi, tàbí pa àṣẹ àti òfin mi mọ́ bí baba ti ṣe. “ ‘Ṣùgbọ́n èmi kì yóò gba gbogbo ìjọba náà lọ́wọ́ ; èmi ti mú un jẹ́ olórí ní gbogbo ọjọ́ ayé rẹ̀ nítorí ti ìránṣẹ́ mi, ẹni tí mo yàn, tí ó sì ti pa òfin mi àti àṣẹ mi mọ́. Èmi yóò gba ìjọba náà ní ọwọ́ ọmọ rẹ̀, èmi yóò sì fi ẹ̀yà mẹ́wàá fún ọ. Èmi yóò fi ẹ̀yà kan fún ọmọ rẹ kí ìránṣẹ́ mi lè máa ní ìmọ́lẹ̀ níwájú mi nígbà gbogbo ní ẹmu, ìlú tí mo ti yàn láti fi orúkọ mi síbẹ̀. Ṣùgbọ́n ní ti ìwọ, Èmi yóò mú ọ, ìwọ yóò sì jẹ ọba lórí ohun gbogbo tí ọkàn rẹ ń fẹ́; ìwọ yóò jẹ ọba lórí ẹli. Bí ìwọ bá ṣe gbogbo èyí tí mo pàṣẹ fún ọ, tí o sì rìn ní ọ̀nà mi, tí o sì ṣe èyí tí ó tọ́ lójú mi nípa pípa òfin àti àṣẹ mi mọ́, bí i ìránṣẹ́ mi ti ṣe, Èmi yóò wà pẹ̀lú rẹ. Èmi yóò kọ́ ilé òtítọ́ fún ọ bí èyí tí mo kọ́ fún , èmi yóò sì fi ẹli fún ọ. Èmi yóò sì rẹ irú-ọmọ sílẹ̀ nítorí èyí, ṣùgbọ́n kì í ṣe títí láé.’ ” Solomoni wá ọ̀nà láti pa , ṣùgbọ́n sálọ sí , sọ́dọ̀ Ṣiṣaki ọba , ó sì wà níbẹ̀ títí fi kú. Ìyókù iṣẹ́ àti gbogbo èyí tí ó ṣe, àti ọgbọ́n rẹ̀, a kò ha kọ wọ́n sínú ìwé ìṣe bí? Solomoni sì jẹ ọba ní ẹmu lórí gbogbo ẹli ní ogójì ọdún. Nígbà náà ni sì sùn pẹ̀lú àwọn baba rẹ̀, a sì sin ín ní ìlú baba rẹ̀. Rehoboamu ọmọ rẹ̀ sì jẹ ọba ní ipò rẹ̀.

Every verse in 1 Kings 11

Chapter navigation

Biblica® ní oore ọ̀fẹ́ láti lo Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní™ / Biblica® Open Yoruba Contemporary Bible™ Copyright © 2009, 2017 by Biblica, Inc. “Biblica” is a trademark registered in the United States Patent and Trademark Office by Biblica, Inc. Used with permission. Licensed under CC BY-SA 4.0.

0:000:00