1 Kings 12:5
“Rehoboamu sì wí fún wọn pé, “Ẹ lọ ná títí di ọjọ́ mẹ́ta, nígbà náà ni kí ẹ padà tọ̀ mí wá.” Àwọn ènìyàn náà sì lọ.”
1 Kings 12:5 — Biblica® Open Yoruba Contemporary Bible
Verse 5 of 33 in 1 Kings chapter 12 — Biblica® Open Yoruba Contemporary Bible. Read it in context below, with maps, timelines and thematic connections beside the text.
1 Kings 12 — full chapter (Biblica® Open Yoruba Contemporary Bible)
Rehoboamu sì lọ sí Ṣekemu, nítorí gbogbo ẹli ti lọ síbẹ̀ láti fi í jẹ ọba. Nígbà tí ọmọ , tí ó wà ní síbẹ̀ gbọ́, nítorí tí ó ti sá kúrò níwájú ọba, ó sì wà ní . Bẹ́ẹ̀ ni wọ́n ránṣẹ́ sí , òun àti gbogbo ìjọ ẹli sì lọ sọ́dọ̀ , wọ́n sì wí fún un pé, “Baba rẹ sọ àjàgà wa di wúwo, ṣùgbọ́n nísinsin yìí, mú kí ìsìn baba rẹ̀ tí ó le, àti àjàgà rẹ̀ tí ó wúwo, tí ó fi sí wa ní ọrùn kí ó fẹ́rẹ̀ díẹ̀, àwa yóò sì sìn ọ́.” Rehoboamu sì wí fún wọn pé, “Ẹ lọ ná títí di ọjọ́ mẹ́ta, nígbà náà ni kí ẹ padà tọ̀ mí wá.” Àwọn ènìyàn náà sì lọ. Nígbà náà ni ọba fi ọ̀rọ̀ lọ àwọn àgbàgbà tí ń dúró níwájú baba rẹ̀ nígbà tí ó wà láààyè. Ó sì béèrè pé, “Ìmọ̀ràn wo ni ẹ̀yin yóò gbà mí láti dá àwọn ènìyàn wọ̀nyí lóhùn?” Wọ́n sì dá a lóhùn pé, “Bí ìwọ yóò bá jẹ́ ìránṣẹ́ fún àwọn ènìyàn wọ̀nyí lónìí, kí o sì sìn wọ́n, àti kí o sì sọ ọ̀rọ̀ rere sí wọn nígbà tí ìwọ bá ń dá wọn lóhùn, wọn yóò máa ṣe ìránṣẹ́ rẹ títí láé.” Ṣùgbọ́n kọ ìmọ̀ràn tí àwọn àgbàgbà fún un, ó sì fi ọ̀rọ̀ náà lọ àwọn ọmọdé tí wọ́n dàgbà pẹ̀lú rẹ̀, tí wọ́n sì ń sìn ín. Ó sì bi wọ́n pé, “Kí ni ìmọ̀ràn yín? Báwo ni a ó ṣe dá àwọn ènìyàn yí lóhùn, tí wọ́n wí fún mi pé, ‘Ṣé kí àjàgà tí baba rẹ fi sí wa lọ́rùn kí ó fúyẹ́ díẹ̀’?” Àwọn ọmọdé tí ó dàgbà pẹ̀lú rẹ̀ dá a lóhùn pé, “Sọ fún àwọn ènìyàn tí wọ́n wí fún ọ pé, ‘Baba rẹ̀ mú kí àjàgà wa wúwo ṣùgbọ́n ìwọ mú kí ó fúyẹ́ díẹ̀ fún wa’; sọ fún wọn pé, ìka ọwọ́ mi kékeré nípọn ju ẹ̀gbẹ́ baba mi lọ. Baba mi ti gbé àjàgà wúwo lé e yín; Èmi yóò sì fi kún àjàgà yín. Baba mi ti fi pàṣán nà yín, Èmi yóò fi àkéekèe nà yín.” Jeroboamu àti gbogbo àwọn ènìyàn náà wá sọ́dọ̀ ní ọjọ́ kẹta, gẹ́gẹ́ bí ọba ti wí pé, “Ẹ padà tọ̀ mí wá ní ọjọ́ kẹta.” Ọba sì fi ohùn líle dá àwọn ènìyàn lóhùn, ó sì kọ ìmọ̀ràn tí àwọn àgbàgbà fún un, Ó sì tẹ̀lé ìmọ̀ràn àwọn ọmọdé, ó sì wí pé, “Baba mí sọ àjàgà yín di wúwo, èmi yóò sì jẹ́ kí ó wúwo sí i, baba mi fi pàṣán nà yín èmi yóò fi àkéekèe nà yín.” Bẹ́ẹ̀ ni ọba kò sì fi etí sí ti àwọn ènìyàn, nítorí tí ọ̀ràn náà ti ọwọ́ Olúwa wá láti mú ọ̀rọ̀ tí ó sọ fún ọmọ láti ẹnu ará Ṣilo ṣẹ. Nígbà tí gbogbo ẹli rí i pé ọba kọ̀ láti gbọ́ ti àwọn, wọ́n sì dá ọba lóhùn pé, “Ìpín wo ni àwa ní nínú , ìní wo ni àwa ní nínú ọmọ ? Padà sí àgọ́ rẹ, ìwọ ẹli! Bojútó ilé ara rẹ, ìwọ !” Bẹ́ẹ̀ ni àwọn ará ẹli padà sí ilé wọn. Ṣùgbọ́n fún ti àwọn ọmọ ẹli tí ń gbé nínú ìlú , Rehoboamu jẹ ọba lórí wọn síbẹ̀. Ọba rán jáde, ẹni tí ó wà ní ìkáwọ́ iṣẹ́ írúú, ṣùgbọ́n gbogbo ẹli sọ ọ́ ní òkúta pa. Ọba , gbìyànjú láti dé inú kẹ̀kẹ́ rẹ̀ ó sì sálọ sí ẹmu. Bẹ́ẹ̀ ni ẹli ṣọ̀tẹ̀ sí ilé títí di òní yìí. Nígbà tí gbogbo ẹli sì gbọ́ pé ti padà dé, wọ́n ránṣẹ́, wọ́n sì pè é wá sí àjọ, wọ́n sì fi jẹ ọba lórí gbogbo ẹli. Kò sí ẹnìkan tí ó tọ ilé lẹ́yìn bí kò ṣe kìkì ẹ̀yà nìkan. Nígbà tí sì dé sí ẹmu, ó kó gbogbo ilé jọ, àti ẹ̀yà ; ọ̀kẹ́ mẹ́sàn-án (180,000) ènìyàn tí a yàn, tí wọ́n ń ṣe ológun, láti bá ilé ẹli jà àti láti mú ìjọba náà padà bọ̀ sọ́dọ̀ , ọmọ . Ṣùgbọ́n ọ̀rọ̀ Ọlọ́run tọ Ṣemaiah ènìyàn Ọlọ́run wá wí pé, “Sọ fún , ọmọ , ọba àti fún gbogbo ilé àti ti , àti fún àwọn ènìyàn tókù wí pé, ‘Báyìí ni Olúwa wí, “Ẹ má ṣe gòkè lọ láti bá àwọn arákùnrin yín jà, àwọn ènìyàn ẹli. Kì olúkúlùkù yín padà sí ilé rẹ̀, nítorí nǹkan yìí láti ọ̀dọ̀ mi wá ni.” ’ ” Bẹ́ẹ̀ ni wọ́n sì gbọ́ ọ̀rọ̀ Olúwa, wọ́n sì tún padà sí ilé wọn, gẹ́gẹ́ bí ọ̀rọ̀ Olúwa. Nígbà náà ni kọ́ Ṣekemu ní òkè , ó sì ń gbé inú rẹ̀. Láti ibẹ̀ ó sì jáde lọ, ó sì kọ́ . Jeroboamu rò nínú ara rẹ̀ pé, “Ìjọba náà yóò padà nísinsin yìí sí ilé . Bí àwọn ènìyàn wọ̀nyí bá gòkè lọ láti ṣe ìrúbọ ní ilé Olúwa ní ẹmu, wọn yóò tún fi ọkàn wọn fún Olúwa wọn, Rehoboamu ọba . Wọn yóò sì pa mí, wọn yóò sì tún padà tọ ọba lọ.” Lẹ́yìn tí ó ti gba ìmọ̀ràn, ọba sì yá ẹgbọrọ màlúù wúrà méjì. Ó sì wí fún àwọn ènìyàn pé, “Ó ti pọ̀jù fún yín láti máa gòkè lọ sí ẹmu. Àwọn Ọlọ́run yín nìyìí, Israẹli, tí ó mú yín láti ilẹ̀ wá.” Ó sì gbé ọ̀kan kalẹ̀ ní , àti èkejì ní . Nǹkan yìí sì di ẹ̀ṣẹ̀; àwọn ènìyàn sì lọ títí dé láti sin èyí tí ó wà níbẹ̀. Jeroboamu sì kọ́ ojúbọ sórí ibi gíga, ó sì yan àwọn àlùfáà láti inú àwọn ènìyàn bí ó tilẹ̀ jẹ́ pé wọn kì í ṣe inú àwọn ọmọ . Jeroboamu sì dá àsè sílẹ̀ ní ọjọ́ kẹ́ẹ̀dógún oṣù kẹjọ gẹ́gẹ́ bí àsè tí ó wà ní , ó sì rú ẹbọ lórí pẹpẹ. Ó ṣe èyí ní , ó rú ẹbọ sí àwọn ọmọ màlúù tí ó ṣe. Ó sì fi àwọn àlùfáà sí ibi gíga tí ó ti ṣe sí . Ní ọjọ́ kẹ́ẹ̀dógún oṣù kẹjọ, oṣù tí ó rò ní ọkàn ara rẹ̀, ó sì rú ẹbọ lórí pẹpẹ tí ó kọ́ ní . Bẹ́ẹ̀ ni ó sì dá àsè sílẹ̀ fún àwọn ọmọ ẹli, ó sì gun orí pẹpẹ náà lọ láti rú ẹbọ.
Every verse in 1 Kings 12
Chapter navigation
Biblica® ní oore ọ̀fẹ́ láti lo Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní™ / Biblica® Open Yoruba Contemporary Bible™ Copyright © 2009, 2017 by Biblica, Inc. “Biblica” is a trademark registered in the United States Patent and Trademark Office by Biblica, Inc. Used with permission. Licensed under CC BY-SA 4.0.