1 Kings 15:19

“Ó sì wí pé, “Jẹ́ kí májẹ̀mú kí ó wà láàrín èmi àti ìwọ, bí ó sì ti wà láàrín baba mi àti baba rẹ. Wò ó, Èmi rán ọrẹ fàdákà àti wúrà sí ọ. Ǹjẹ́ nísinsin yìí, da májẹ̀mú rẹ pẹ̀lú Baaṣa, ọba Israẹli, kí ó lè lọ kúrò lọ́dọ̀ mi.””

1 Kings 15:19 — Biblica® Open Yoruba Contemporary Bible

Verse 19 of 34 in 1 Kings chapter 15 — Biblica® Open Yoruba Contemporary Bible. Read it in context below, with maps, timelines and thematic connections beside the text.

1 Kings 15 — full chapter (Biblica® Open Yoruba Contemporary Bible)

Ní ọdún kejìdínlógún ìjọba ọmọ , Abijah jẹ ọba lórí , ó sì jẹ ọba ní ọdún mẹ́ta ní ẹmu. Orúkọ ìyá rẹ̀ sì ni , ọmọbìnrin . Ó sì rìn nínú gbogbo ẹ̀ṣẹ̀ tí baba rẹ̀ ti dá ṣáájú rẹ̀; ọkàn rẹ̀ kò sì pé pẹ̀lú Olúwa Ọlọ́run rẹ̀, gẹ́gẹ́ bí ọkàn baba ńlá rẹ̀ ti ṣe. Ṣùgbọ́n, nítorí i Olúwa Ọlọ́run rẹ̀ fún un ní ìmọ́lẹ̀ kan ní ẹmu nípa gbígbé ọmọ rẹ̀ ró láti jẹ ọba ní ipò rẹ̀ àti láti fi ìdí ẹmu múlẹ̀. Nítorí tí ṣe èyí tí ó dára ní ojú Olúwa, tí kò sì kùnà láti pa gbogbo èyí tí Olúwa pàṣẹ fún un mọ́ ní ọjọ́ ayé rẹ̀ gbogbo; bí kò ṣe ní kìkì ọ̀ràn ará . Ogun sì wà láàrín àti ní gbogbo ọjọ́ ayé . Ní ti ìyókù ìṣe , àti gbogbo èyí tí ó ṣe, a kò ha kọ wọ́n sínú ìwé ọ̀rọ̀ ọjọ́ àwọn ọba ? Ogun sì wà láàrín àti . Abijah sì sùn pẹ̀lú àwọn baba rẹ̀, a sì sin ín ní ìlú . ọmọ rẹ̀ sì jẹ ọba ní ipò rẹ̀. Ní ogún ọdún ọba ẹli, jẹ ọba lórí , Ó sì jẹ ọba ní ẹmu ní ọdún mọ́kànlélógójì. Orúkọ ìyá ńlá rẹ̀ sì ni , ọmọbìnrin . sì ṣe èyí tí ó dára lójú Olúwa, bí baba rẹ̀ ti ṣe. Ó sì mú àwọn ọkùnrin alágbèrè ojúbọ òrìṣà kúrò ní ilẹ̀ náà, ó sì kó gbogbo ère tí àwọn baba rẹ̀ ti ṣe kúrò. Ó sì mú ìyá ńlá rẹ̀ kúrò láti máa ṣe ayaba, nítorí tí ó yá ère kan fún Aṣerah òrìṣà rẹ̀. sì ké ère náà lulẹ̀, ó sì jó o ní àfonífojì . Ṣùgbọ́n kò mú àwọn ibi gíga kúrò, síbẹ̀ ọkàn pé pẹ̀lú Olúwa ní ọjọ́ ayé rẹ̀ gbogbo. Ó sì mú wúrà àti fàdákà àti àwọn ohun èlò tí òun àti baba rẹ̀ ti yà sí mímọ́ wọ ilé Olúwa. Ogun sì wà láàrín àti ṣa ọba ẹli ní gbogbo ọjọ́ ayé wọn. Baaṣa, ọba ẹli sì gòkè lọ sí , ó sì kọ́ láti má jẹ́ kí ẹnikẹ́ni jáde tàbí wọlé tọ ọba lọ. Nígbà náà ni mú gbogbo fàdákà àti wúrà tí ó kù nínú ìṣúra ilé Olúwa àti ìṣúra ilé ọba. Ó sì fi lé àwọn ìránṣẹ́ rẹ̀ lọ́wọ́, ó sì rán wọn lọ sí ọ̀dọ̀ - ọmọ , ọmọ ọba tí ó ń gbé ní . Ó sì wí pé, “Jẹ́ kí májẹ̀mú kí ó wà láàrín èmi àti ìwọ, bí ó sì ti wà láàrín baba mi àti baba rẹ. Wò ó, Èmi rán ọrẹ fàdákà àti wúrà sí ọ. Ǹjẹ́ nísinsin yìí, da májẹ̀mú rẹ pẹ̀lú ṣa, ọba ẹli, kí ó lè lọ kúrò lọ́dọ̀ mi.” Beni- gba ti ọba, ó sì rán àwọn alágbára olórí ogun rẹ̀ sí àwọn ìlú ẹli. Ó sì ṣẹ́gun , Dani àti --, àti gbogbo pẹ̀lú gbogbo ilẹ̀ . Nígbà tí ṣa sì gbọ́ èyí, ó sì ṣíwọ́ kíkọ́ , ó sì lọ kúrò sí . Nígbà náà ni ọba kéde ká gbogbo , kò dá ẹnìkan sí, wọ́n sì kó òkúta kúrò àti igi rẹ̀, tí ṣa fi kọ́lé. ọba sì fi wọ́n kọ́ ti àti . Ní ti ìyókù gbogbo ìṣe , àti gbogbo agbára rẹ̀, àti gbogbo ohun tí ó ṣe, àti àwọn ìlú tí ó kọ́, a kò ha kọ wọ́n sínú ìwé ọ̀rọ̀ ọjọ́ àwọn ọba ? Ṣùgbọ́n, ní ìgbà ogbó rẹ̀, ààrùn ṣe é ní ẹsẹ̀ rẹ̀. sì sùn pẹ̀lú àwọn baba rẹ̀, a sì sin ín pẹ̀lú àwọn baba rẹ̀ ní ìlú baba rẹ̀. Jehoṣafati ọmọ rẹ̀ sì jẹ ọba ní ipò rẹ̀. Nadabu ọmọ sì jẹ ọba lórí ẹli ní ọdún kejì ọba , ó sì jẹ ọba lórí ẹli ní ọdún méjì. Ó sì ṣe búburú níwájú Olúwa, ó sì rìn ní ọ̀nà baba rẹ̀ àti nínú ẹ̀ṣẹ̀ rẹ̀, èyí tí ó mú ẹli dá. Baaṣa ọmọ ti ilé sì dìtẹ̀ sí i, Baaṣa sì kọlù ú ní , ìlú àwọn ará , nígbà tí àti gbogbo ẹli dó ti . Baaṣa sì pa ní ọdún kẹta ọba , ó sì jẹ ọba ní ipò rẹ̀. Ó sì ṣe, bí ó sì ti bẹ̀rẹ̀ sí ní jẹ ọba ó pa gbogbo ilé , kò sì ku ẹnìkan tí ń mí fún , ṣùgbọ́n ó run gbogbo wọn, gẹ́gẹ́ bí ọ̀rọ̀ Olúwa, tí ó sọ nípa ọwọ́ ìránṣẹ́ rẹ̀ ará Ṣilo. Nítorí ẹ̀ṣẹ̀ tí ti ṣẹ̀ àti tí ó mú ẹli ṣẹ̀, àti nítorí tí ó ti mú Olúwa Ọlọ́run ẹli bínú. Ní ti ìyókù ìṣe àti gbogbo ohun tí ó ṣe, a kò ha kọ wọ́n sínú ìwé ọ̀rọ̀ ọjọ́ àwọn ọba ẹli? Ogun sì wà láàrín àti ṣa ọba ẹli ní gbogbo ọjọ́ wọn. Ní ọdún kẹta ọba , Baaṣa ọmọ sì jẹ ọba lórí gbogbo ẹli ní , ó sì jẹ ọba ní ọdún mẹ́rìnlélógún. Ó sì ṣe búburú níwájú Olúwa, ó sì rìn ní ọ̀nà àti nínú ẹ̀ṣẹ̀ rẹ̀, èyí tí ó ti mú ẹli ṣẹ̀.

Every verse in 1 Kings 15

Chapter navigation

Biblica® ní oore ọ̀fẹ́ láti lo Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní™ / Biblica® Open Yoruba Contemporary Bible™ Copyright © 2009, 2017 by Biblica, Inc. “Biblica” is a trademark registered in the United States Patent and Trademark Office by Biblica, Inc. Used with permission. Licensed under CC BY-SA 4.0.

0:000:00