1 Kings 16:29
“Ní ọdún kejìdínlógójì Asa ọba Juda, Ahabu ọmọ Omri jẹ ọba ní Israẹli, o si jẹ ọba lórí Israẹli ní Samaria ní ọdún méjìlélógún.”
1 Kings 16:29 — Biblica® Open Yoruba Contemporary Bible
Verse 29 of 34 in 1 Kings chapter 16 — Biblica® Open Yoruba Contemporary Bible. Read it in context below, with maps, timelines and thematic connections beside the text.
1 Kings 16 — full chapter (Biblica® Open Yoruba Contemporary Bible)
Ó sì ṣe, ọ̀rọ̀ Olúwa sì tọ ọmọ wá sí ṣa pé, “Èmi ti gbé ọ ga láti inú erùpẹ̀ wá, mo sì fi ọ́ ṣe olórí ẹli ènìyàn mi, ṣùgbọ́n ìwọ sì rìn ní ọ̀nà , ó sì mú kí ẹli ènìyàn mi dẹ́ṣẹ̀, láti mú mi bínú nípa ẹ̀ṣẹ̀ wọn. Nítorí náà, èmi yóò mú ṣa àti ilé rẹ̀ kúrò, èmi yóò sì ṣe ilé rẹ̀ bí ilé ọmọ . Àwọn ajá yóò jẹ ẹni ṣa tí ó bá kú ní ìlú, ẹyẹ ojú ọ̀run yóò sì jẹ àwọn tí ó kú ní oko.” Àti ìyókù ìṣe ṣa, ohun tí ó ṣe àti agbára rẹ̀, a kò ha kọ wọ́n sínú ìwé ọ̀rọ̀ ọjọ́ àwọn ọba ẹli? Baaṣa sì sùn pẹ̀lú àwọn baba rẹ̀, a sì sin ín ní . Ela ọmọ rẹ̀ sì jẹ ọba ní ipò rẹ̀. Ọ̀rọ̀ Olúwa sì wá nípa ọwọ́ wòlíì ọmọ pẹ̀lú sí ṣa àti ilé rẹ̀, nítorí gbogbo búburú tí ó ti ṣe níwájú Olúwa, ní mímú un bínú nípa ohun tó ti ṣe àti wíwà bí ilé , àti nítorí tí ó pa á run pẹ̀lú. Ní ọdún kẹrìndínlọ́gbọ̀n ọba , Ela ọmọ ṣa bẹ̀rẹ̀ sí ní jẹ ọba ní ẹli, ó sì jẹ ọba ní ní ọdún méjì. Simri, ọ̀kan nínú àwọn ìránṣẹ́ rẹ̀, olórí ìdajì kẹ̀kẹ́ rẹ̀, dìtẹ̀ sí i. Ela sì wà ní nígbà náà, ó sì mu àmupara ní ilé , ìríjú ilé rẹ̀ ni . Simri sì wọlé, ó sì kọlù ú, ó sì pa á ní ọdún kẹtàdínlọ́gbọ̀n , ọba , ó sì jẹ ọba ní ipò rẹ̀. Bí ó sì ti bẹ̀rẹ̀ sí ní jẹ ọba, bí ó sì ti jókòó lórí ìtẹ́, ó lu gbogbo ilé ṣa pa, kò ku ọkùnrin kan sílẹ̀, bóyá ìbátan tàbí ọ̀rẹ́. Bẹ́ẹ̀ ni pa gbogbo ilé ṣa run, gẹ́gẹ́ bí ọ̀rọ̀ Olúwa tí ó sọ sí ṣa nípa ọwọ́ wòlíì: nítorí gbogbo ẹ̀ṣẹ̀ tí ṣa àti ọmọ rẹ̀ ti ṣẹ̀ àti tí wọ́n ti mú ẹli ṣẹ̀, tí wọ́n fi mú Olúwa Ọlọ́run ẹli bínú, wọ́n mú u bínú nípa òrìṣà asán wọn. Ìyókù ìṣe àti gbogbo ohun tí ó ṣe, a kò ha kọ wọ́n sínú ìwé ọ̀rọ̀ ọjọ́ àwọn ọba ẹli? Ní ọdún kẹtàdínlọ́gbọ̀n ọba , ni jẹ ọba ọjọ́ méje ní . Àwọn ọmọ-ogun sì dó ti , ìlú àwọn ará . Nígbà tí àwọn ọmọ ẹli tí ó dó tì gbọ́ wí pé ti dìtẹ̀ sí ọba, ó sì ti pa á, wọ́n kéde , olórí ogun, bí ọba lórí ẹli ní ọjọ́ náà ní ibùdó. Nígbà náà ni àti gbogbo ẹli pẹ̀lú rẹ̀ kúrò ní , wọ́n sì dó ti . Nígbà tí sì ri pé a ti gba ìlú, ó sì wọ inú ààfin ilé ọba lọ, ó sì tẹ iná bọ ilé ọba lórí ara rẹ̀, ó sì kú, nítorí àwọn ẹ̀ṣẹ̀ rẹ̀ tí ó ti ṣẹ̀, ní ṣíṣe búburú níwájú Olúwa àti ní rírìn ní ọ̀nà àti nínú ẹ̀ṣẹ̀ rẹ̀ tí ó ti ṣe àti tí ó ti mú ẹli ṣẹ̀. Ní ti ìyókù ìṣe , àti ọ̀tẹ̀ rẹ̀ tí ó dì, a kò ha kọ wọ́n sínú ìwé ọ̀rọ̀ ọjọ́ àwọn ọba ẹli? Nígbà náà ní àwọn ènìyàn ẹli dá sí méjì; apá kan wọn ń tọ ọmọ lẹ́yìn, láti fi í jẹ ọba, apá kan tókù sì ń tọ lẹ́yìn. Ṣùgbọ́n àwọn ènìyàn tí ń tọ lẹ́yìn borí àwọn tí ń tọ ọmọ lẹ́yìn. Bẹ́ẹ̀ ni kú, Omri sì jẹ ọba. Ní ọdún kọkànlélọ́gbọ̀n ọba , Omri bẹ̀rẹ̀ sí ń jẹ ọba lórí ẹli, ó sì jẹ ọba ní ọdún méjìlá, ọdún mẹ́fà ní . Ó sì ra òkè lọ́wọ́ Ṣemeri ní tálẹ́ǹtì méjì fàdákà, ó sì kọ́ ìlú sórí rẹ̀, ó sì pe ìlú náà ní , nípa orúkọ Ṣemeri, orúkọ ẹni tí ó kọ́kọ́ ni òkè náà. Ṣùgbọ́n sì ṣe búburú níwájú Olúwa, Ó sì ṣe búburú ju gbogbo àwọn tí ó wà ṣáájú rẹ̀ lọ. Ó rìn ní gbogbo ọ̀nà ọmọ àti nínú ẹ̀ṣẹ̀ rẹ̀, èyí tí ó ti mú ẹli ṣẹ̀, láti fi ohun asán wọn mú Olúwa, Ọlọ́run ẹli bínú. Ìyókù ìṣe àti ohun tí ṣe, àti agbára rẹ tí ó fihàn, a kò ha kọ, wọ́n sínú ìwé ọ̀rọ̀ ọjọ́ àwọn ọba ẹli? Omri sì sùn pẹ̀lú àwọn baba rẹ̀ a sì sin ín ní . Ahabu ọmọ rẹ̀ sì jẹ ọba ní ipò rẹ̀. Ní ọdún kejìdínlógójì ọba , Ahabu ọmọ jẹ ọba ní ẹli, o si jẹ ọba lórí ẹli ní ní ọdún méjìlélógún. Ahabu ọmọ sì ṣe búburú ní ojú Olúwa ju gbogbo àwọn tí ó wà ṣáájú rẹ̀ lọ. Ó sì ṣe bí ẹni pé ó ṣe ohun kékeré fún un láti máa rìn nínú ẹ̀ṣẹ̀ ọmọ , ó sì mú , ọmọbìnrin , ọba àwọn ará ní aya, ó sì bẹ̀rẹ̀ sí ń sin , ó sì bọ ọ́. Ó sì tẹ́ pẹpẹ kan fún nínú ilé tí ó kọ́ sí . Ahabu sì túnṣe ère òrìṣà Aṣerah, ó sì ṣe púpọ̀ láti mú Olúwa Ọlọ́run ẹli bínú ju èyí tí gbogbo ọba ẹli tí ó ti wà ṣáájú rẹ̀ ti ṣe lọ. Ní ìgbà ayé , Hieli ará kọ́ . Ó fi ìpìlẹ̀ rẹ̀ lé ilẹ̀ ní , àkọ́bí rẹ, ó sì gbé àwọn ìlẹ̀kùn ibodè rẹ̀ kọ́ ní àbíkẹ́yìn rẹ̀, gẹ́gẹ́ bí ọ̀rọ̀ Olúwa tí ó ti ipa Joṣua ọmọ sọ.
Every verse in 1 Kings 16
Chapter navigation
Biblica® ní oore ọ̀fẹ́ láti lo Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní™ / Biblica® Open Yoruba Contemporary Bible™ Copyright © 2009, 2017 by Biblica, Inc. “Biblica” is a trademark registered in the United States Patent and Trademark Office by Biblica, Inc. Used with permission. Licensed under CC BY-SA 4.0.