1 Kings 4:26
“Solomoni sì ní ẹgbàajì (4,000) ilé ẹṣin fún kẹ̀kẹ́ rẹ̀, àti ẹgbàá mẹ́fà (12,000) ẹlẹ́ṣin.”
1 Kings 4:26 — Biblica® Open Yoruba Contemporary Bible
Verse 26 of 34 in 1 Kings chapter 4 — Biblica® Open Yoruba Contemporary Bible. Read it in context below, with maps, timelines and thematic connections beside the text.
1 Kings 4 — full chapter (Biblica® Open Yoruba Contemporary Bible)
Solomoni ọba sì jẹ ọba lórí gbogbo ẹli. Àwọn wọ̀nyí sì ni ìjòyè rẹ̀: Asariah ọmọ àlùfáà: Elihorefu àti àwọn ọmọ Ṣisa akọ̀wé; Jehoṣafati ọmọ ni akọ̀wé ìlú; Benaiah ọmọ ni olórí ogun; Sadoku àti ni àwọn àlùfáà; Asariah ọmọ ni olórí àwọn agbègbè; Sabudu ọmọ , àlùfáà àti olùgba ọba ní ìmọ̀ràn; Ahiṣari ni olùtọ́jú ààfin; Adoniramu ọmọ ni ó ń ṣe olórí iṣẹ́-ìlú. Solomoni sì tún ní ìjòyè méjìlá lórí gbogbo agbègbè ẹli, tí wọ́n ń pèsè oúnjẹ fún ọba àti agbo ilé rẹ̀. Olúkúlùkù ní láti pèsè fún oṣù kan ní ọdún. Orúkọ wọn ni wọ̀nyí: Bene- ní ìlú olókè . Bene- ní , Ṣaalbimu, Beti-Ṣemeṣi, àti -; Bene-, ní (tirẹ̀ ni àti gbogbo ilẹ̀ ń ṣe); Bene-, ní (; òun ni ó fẹ́ ọmọbìnrin ní aya). Baana ọmọ , ní àti , àti ní gbogbo -Ṣeani tí ń bẹ níhà ní ìsàlẹ̀ , láti -Ṣeani dé - títí dé ibi tí ń bẹ ní ìkọjá . Ọmọ ní (tirẹ̀ ni àwọn ìletò ọmọ tí ń bẹ ní , tirẹ̀ sì ni agbègbè , tí ń bẹ ní Baṣani, ọgọ́ta ìlú tí ó tóbi pẹ̀lú odi tí ẹnu-ọ̀nà rẹ̀ jẹ́ irin). Ahinadabu ọmọ ní Ahimasi ní (ó fẹ́ ọmọbìnrin ní aya). Baana ọmọ Huṣ ní Aṣeri àti ní ; Jehoṣafati ọmọ ni ó wà ní ; Ṣimei ọmọ ni ; Geberi ọmọ ní (orílẹ̀-èdè ọba àwọn ará àti orílẹ̀-èdè ọba Baṣani). Òun nìkan ni ìjòyè lórí ilẹ̀ náà. Àwọn ènìyàn àti ti ẹli pọ̀ gẹ́gẹ́ bí iyanrìn tí ń bẹ ní etí Òkun; wọ́n ń jẹ, wọ́n sì ń mu, wọ́n sì ń yọ ayọ̀. Solomoni sì ń ṣàkóso lórí gbogbo àwọn ìjọba láti odò títí dé ilẹ̀ àwọn ará , àti títí dé etí ilẹ̀ . Àwọn orílẹ̀-èdè yìí ń mú owó òde wá, wọ́n sì ń sin ní gbogbo ọjọ́ ayé rẹ̀. Oúnjẹ fún ọjọ́ kan jásí ọgbọ̀n ìyẹ̀fun kíkúnná àti ọgọ́ta òsùwọ̀n ìyẹ̀fun, Màlúù mẹ́wàá tí ó sanra, àti ogún màlúù láti inú pápá wá, àti ọgọ́rùn-ún àgùntàn àti ewúrẹ́, láìka àgbọ̀nrín àti èsúró, àti ogbúgbu, àti ẹyẹ tí ó sanra. Nítorí òun ni ó ṣàkóso lórí gbogbo agbègbè ní ìhà ìwọ̀-oòrùn odò , láti títí dé , lórí gbogbo àwọn ọba ní ìhà ìhín odò, ó sì ní àlàáfíà ní gbogbo ìlú tí ó yí i káàkiri. Nígbà ayé , Juda àti ẹli, láti títí dé ṣeba, wọ́n ń gbé ní àlàáfíà, olúkúlùkù lábẹ́ àjàrà rẹ̀ àti lábẹ́ igi ọ̀pọ̀tọ́ rẹ̀. Solomoni sì ní ẹgbàajì (4,000) ilé ẹṣin fún kẹ̀kẹ́ rẹ̀, àti ẹgbàá mẹ́fà (12,000) ẹlẹ́ṣin. Àwọn ìjòyè agbègbè, olúkúlùkù ní oṣù rẹ̀, ń pèsè oúnjẹ fún ọba àti gbogbo àwọn tí ń wá sí ibi tábìlì ọba, wọ́n sì rí i pé ohun kankan kò ṣẹ́kù. Wọ́n tún máa ń mú ọkà barle àti koríko fún ẹṣin àti fún ẹṣin sísáré wá pẹ̀lú sí ibi tí ó yẹ, olúkúlùkù gẹ́gẹ́ bí ìlànà tirẹ̀. Ọlọ́run sì fún ní ọgbọ́n, àti òye ní ọ̀pọ̀lọpọ̀, àti ìmọ̀ gbígbòòrò òye tí a kò le è fiwé iyanrìn tí ó wà létí Òkun. Ọgbọ́n sì pọ̀ ju ọgbọ́n ọkùnrin ìlà-oòrùn lọ, ó sì pọ̀ ju gbogbo ọgbọ́n lọ. Ó sì ní òye ju gbogbo ènìyàn lọ, ju , ará , àti àti , àti àwọn ọmọ lọ. Òkìkí rẹ̀ sì kàn ní gbogbo orílẹ̀-èdè yíká. Ó sì pa ẹgbẹ̀rún mẹ́ta (3,000) òwe, àwọn orin rẹ̀ sì jẹ́ ẹgbẹ̀rún ó lé márùn-ún (1,005). Ó sì sọ̀rọ̀ ti igi, láti kedari tí ń bẹ ní dé Hísópù tí ń dàgbà lára ògiri. Ó sì tún sọ ti àwọn ẹranko àti ti àwọn ẹyẹ, àti ohun tí ń rákò àti ti ẹja. Àwọn ènìyàn sì ń wá láti gbogbo orílẹ̀-èdè láti gbọ́ ọgbọ́n , láti ọ̀dọ̀ àwọn ọba ayé láti wá gbọ́ nípa ọgbọ́n rẹ̀.
Every verse in 1 Kings 4
Chapter navigation
Biblica® ní oore ọ̀fẹ́ láti lo Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní™ / Biblica® Open Yoruba Contemporary Bible™ Copyright © 2009, 2017 by Biblica, Inc. “Biblica” is a trademark registered in the United States Patent and Trademark Office by Biblica, Inc. Used with permission. Licensed under CC BY-SA 4.0.