1 Samuel 13:12

“mo rò pé, ‘Àwọn Filistini yóò sọ̀kalẹ̀ tọ̀ mí wá ní Gilgali nísinsin yìí, bẹ́ẹ̀ ni èmi kò ì tí ì wá ojúrere Olúwa.’ Báyìí ni mo mú ara mi ní ipá láti rú ẹbọ sísun náà.””

1 Samuel 13:12 — Biblica® Open Yoruba Contemporary Bible

Verse 12 of 23 in 1 Samuel chapter 13 — Biblica® Open Yoruba Contemporary Bible. Read it in context below, with maps, timelines and thematic connections beside the text.

1 Samuel 13 — full chapter (Biblica® Open Yoruba Contemporary Bible)

Saulu sì jẹ́ ọmọ ọgbọ̀n ọdún nígbà tí ó jẹ ọba, ó sì jẹ ọba lórí ẹli ní ọdún méjìlélógójì. Saulu yan ẹgbẹ̀rún mẹ́ta (3,000) ọkùnrin ní ẹli, ẹgbẹ̀rún méjì (2,000) sì wà lọ́dọ̀ rẹ̀ ní àti ní ìlú òkè ẹgbẹ̀rún kan (1,000) sì wà lọ́dọ̀ ní ti . Àwọn ọkùnrin tókù ni ó rán padà sí ilé e wọn. Jonatani sì kọlu ẹgbẹ́ ogun àwọn ní , Filistini sì gbọ́ èyí. Nígbà náà ni fọn ìpè yí gbogbo ilẹ̀ náà ká, ó sì wí pé, “Jẹ́ kí àwọn gbọ́!” Bẹ́ẹ̀ ni gbogbo ẹli sì gbọ́ ìròyìn pé, “Saulu ti kọlu ẹgbẹ́ ogun àwọn , Israẹli sì di òórùn búburú fún àwọn .” Àwọn ènìyàn náà sì péjọ láti darapọ̀ mọ́ ní . Àwọn kó ara wọn jọ pọ̀ láti bá ẹli jà, pẹ̀lú ẹgbẹ̀rún mẹ́ta (3,000) kẹ̀kẹ́, ẹgbẹ̀rún mẹ́fà (6,000) ọkùnrin ẹlẹ́ṣin, àwọn ológun sì pọ̀ bí yanrìn etí Òkun. Wọ́n sì gòkè lọ, wọ́n dó ní ní ìhà ilẹ̀ oòrùn -. Nígbà tí àwọn ọkùnrin ẹli sì rí i pé àwọn wà nínú ìpọ́njú àti pé àwọn ológun wọn wà nínú ìhámọ́, wọ́n fi ara pamọ́ nínú ihò àti nínú igbó láàrín àpáta, nínú ọ̀fìn, àti nínú kànga gbígbẹ. Àwọn mìíràn tilẹ̀ kọjá a sí ilẹ̀ àti . Saulu wà ní síbẹ̀, gbogbo àwọn ọ̀wọ́ ogun tí ó wà pẹ̀lú rẹ̀ sì ń wárìrì fún ìbẹ̀rù. Ó sì dúró di ọjọ́ méje, àkókò tí ẹli dá; ṣùgbọ́n ẹli kò wá sí , àwọn ènìyàn sì bẹ̀rẹ̀ sí ní túká. Saulu sì wí pé, “Ẹ mú ẹbọ sísun àti ẹbọ ìrẹ́pọ̀ wá fún mi.” sì rú ẹbọ sísun náà. Bí ó sì ti ń parí rírú ẹbọ sísun náà, Samuẹli sì dé, Saulu sì jáde láti lọ kí i. Samuẹli sì wí pé, “Kí ni ìwọ ṣe yìí.” sì dáhùn pé, “Nígbà tí mo rí pé àwọn ènìyàn náà ń túká, àti tí ìwọ kò sì wá ní àkókò ọjọ́ tí ìwọ dá, tí àwọn sì kó ara wọ́n jọ ní , mo rò pé, ‘Àwọn yóò sọ̀kalẹ̀ tọ̀ mí wá ní nísinsin yìí, bẹ́ẹ̀ ni èmi kò ì tí ì wá ojúrere Olúwa.’ Báyìí ni mo mú ara mi ní ipá láti rú ẹbọ sísun náà.” Samuẹli sì wí fún un pé, “Ìwọ hu ìwà aṣiwèrè, ìwọ kò sì pa òfin tí Olúwa Ọlọ́run rẹ fi fún ọ mọ́; bí o kò bá ṣe bẹ́ẹ̀, òun ìbá fi ìdí ìjọba rẹ kalẹ̀ lórí ẹli láéláé. Ṣùgbọ́n nísinsin yìí ìjọba rẹ kì yóò dúró pẹ́, Olúwa ti wá ọkùnrin tí ó wù ú ní ọkàn rẹ̀ fún ara rẹ̀, ó sì ti yàn án láti ṣe olórí fún àwọn ènìyàn rẹ̀, nítorí pé ìwọ kò pa òfin Olúwa mọ́.” Nígbà náà ni ẹli kúrò ní , ó sì gòkè lọ sí ti , Saulu sì ka àwọn ènìyàn tí ó wà lọ́dọ̀ rẹ̀, wọ́n sì jẹ́ ẹgbẹ̀ta (600). Saulu àti ọmọ rẹ̀ àti àwọn ènìyàn tí ó wà pẹ̀lú wọn dúró ní ti , nígbà tí àwọn dó ní . Ẹgbẹ́ àwọn ísùmọ̀mí mẹ́ta jáde lọ ní àgọ́ àwọn ní ọnà ọ̀tọ̀ọ̀tọ̀. Ẹgbẹ́ kan gba ọ̀nà ti ní agbègbè ìlú Ṣuali, òmíràn gba ọ̀nà -, ẹ̀kẹta sí ìhà ibodè tí ó kọjú sí àfonífojì tí ó kọjú sí ijù. A kò sì rí alágbẹ̀dẹ kan ní gbogbo ilẹ̀ ẹli, nítorí tí àwọn wí pé, “Bí kò ṣe bẹ́ẹ̀ àwọn yóò rọ idà tàbí ọ̀kọ̀!” Bẹ́ẹ̀ ni gbogbo ẹli tọ àwọn lọ láti pọ́n dòjé wọn, ọ̀kọ̀, àáké àti ọ̀ṣọ́ wọn. Iye tí wọ́n fi pọ́n dòjé àti ọ̀kọ̀ jẹ́ ọwọ́ méjì nínú ìdámẹ́ta ṣékélì, àti ìdámẹ́ta ṣékélì fún pípọ́n òòyà-irin tí ilẹ̀, àáké àti irin ọ̀pá olùṣọ́ màlúù. Bẹ́ẹ̀ ni ọjọ́ ìjà ẹnìkankan nínú àwọn ọmọ-ogun tí ó wà pẹ̀lú àti kò sì ní idà, tàbí ọ̀kọ̀ ní ọwọ́; àfi àti ọmọ rẹ̀ ni wọ́n ni wọ́n. Àwọn ẹgbẹ́ ogun sì ti jáde lọ sí ìkọjá .

Every verse in 1 Samuel 13

Chapter navigation

Biblica® ní oore ọ̀fẹ́ láti lo Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní™ / Biblica® Open Yoruba Contemporary Bible™ Copyright © 2009, 2017 by Biblica, Inc. “Biblica” is a trademark registered in the United States Patent and Trademark Office by Biblica, Inc. Used with permission. Licensed under CC BY-SA 4.0.

0:000:00