1 Samuel 14:23
“Bẹ́ẹ̀ ni Olúwa sì gba Israẹli ní ọjọ́ náà, ìjà náà sì rékọjá sí Beti-Afeni.”
1 Samuel 14:23 — Biblica® Open Yoruba Contemporary Bible
Verse 23 of 52 in 1 Samuel chapter 14 — Biblica® Open Yoruba Contemporary Bible. Read it in context below, with maps, timelines and thematic connections beside the text.
1 Samuel 14 — full chapter (Biblica® Open Yoruba Contemporary Bible)
Ní ọjọ́ kan, Jonatani ọmọ wí fún ọ̀dọ́mọkùnrin tí ó ń ru ìhámọ́ra rẹ̀ pé, “Wá, jẹ́ kí a rékọjá lọ sí ìlú olódi àwọn tí ó wà ní ìhà kejì.” Ṣùgbọ́n kò sọ fún baba rẹ̀. Saulu sì dúró ní ìhà etí ìpínlẹ̀ lábẹ́ igi pomegiranate èyí tí ó wà ní . Àwọn ẹgbẹ̀ta (600) ọkùnrin sì wà pẹ̀lú rẹ̀, lára wọn ni , tí ó wọ efodu. Òun ni ọmọ arákùnrin , ọmọ , ọmọ , àlùfáà Olúwa ní Ṣilo kò sí ẹni tí ó mọ̀ pé ti lọ. Ní ọ̀nà tí ti ń fẹ́ láti kọjá dé ìlú olódi àwọn , ní bèbè òkúta mímú kan wá, orúkọ èkínní sì ń jẹ́ , orúkọ èkejì sì ń jẹ́ . Bèbè òkúta kan dúró sí àríwá ní ìhà , èkejì sì wà ní gúúsù ní ìhà . Jonatani sì wí fún ọ̀dọ́mọkùnrin tí ó ń ru ìhámọ́ra rẹ̀ pé, “Wá, jẹ́ kí a lọ sí ìlú olódi àwọn aláìkọlà yìí. Bóyá Olúwa yóò jà fún wa, kò sí ohun tó lè di Olúwa lọ́wọ́ láti gbàlà, yálà nípasẹ̀ púpọ̀ tàbí nípasẹ̀ díẹ̀.” Ẹni tí ó ru ìhámọ́ra rẹ̀ sì wí pé, “Ṣe gbogbo ohun tí ó wà ní ọkàn rẹ, tẹ̀síwájú, Èmi wà pẹ̀lú ọkàn àti ẹ̀mí rẹ.” Jonatani sì wí pé, “Wá nígbà náà, àwa yóò rékọjá sí ọ̀dọ̀ ọkùnrin wọ̀nyí, kí a sì jẹ́ kí wọ́n rí wa. Bí wọ́n bá sọ fún wa pé, ‘Ẹ dúró títí àwa yóò fi tọ̀ yín wá,’ àwa yóò dúró sí ibi tí a wà, àwa kì yóò sì gòkè tọ̀ wọ́n lọ. Ṣùgbọ́n bí wọ́n bá wí pé, ‘Ẹ gòkè tọ̀ wá wá,’ àwa yóò gòkè lọ, nítorí èyí ni yóò jẹ́ àmì fún wa pé Olúwa ti fi wọ́n lé wa lọ́wọ́.” Báyìí ní àwọn méjèèjì sì fi ara wọn hàn fún ìlú olódi . Àwọn sì wí pé, “Wò ó! Àwọn ń yọ jáde wá láti inú ihò tí wọ́n fi ara wọn pamọ́ sí.” Àwọn ọkùnrin ìlú olódi náà sì kígbe sí àti ẹni tí ó ru ìhámọ́ra rẹ̀ pé, “Ẹ gòkè tọ̀ wá wá àwa yóò sì kọ́ ọ yín ní ẹ̀kọ́.” sì wí fún ẹni tí ó ru ìhámọ́ra rẹ̀ pé, “Gòkè tọ̀ mí lẹ́yìn; Olúwa ti fi wọ́n lé ẹli lọ́wọ́.” Jonatani lo ọwọ́ àti ẹsẹ̀ rẹ̀ láti fà gòkè pẹ̀lú ẹni tí ó ru ìhámọ́ra rẹ̀ ní ọwọ́ ọ̀tún ní ẹ̀gbẹ́ rẹ̀. Àwọn sì ṣubú níwájú ẹni tí ó ru ìhámọ́ra rẹ̀ sì tẹ̀lé e, ó sì ń pa lẹ́gbẹ̀ẹ́ rẹ̀. Ní ìkọlù èkínní yìí, Jonatani àti ẹni tí ó ru ìhámọ́ra rẹ̀ sì pa ogún ọkùnrin ní agbègbè tó tó ìwọ̀n ààbọ̀ sáré ilẹ̀. Nígbà náà ni ìbẹ̀rùbojo bá àwọn ọmọ-ogun; àwọn tí ó wà ní ibùdó àti ní pápá, àti àwọn tí ó wà ní ilé ìlú olódi àti àwọn tí ń kó ìkógun, ilẹ̀ sì mì. Ó jẹ́ ìbẹ̀rù tí ó ti ọ̀dọ̀ Ọlọ́run wá. Àwọn tí ó ń ṣọ́nà fún ní ti sì rí àwọn ọmọ-ogun ń túká ní gbogbo ọ̀nà. Nígbà náà ni wí fún àwọn ènìyàn tí ó wà pẹ̀lú rẹ̀ pé, “Ẹ ka àwọn ènìyàn kí ẹ sì mọ ẹni tí ó jáde kúrò nínú wa.” Nígbà tí wọ́n sì ṣe bẹ́ẹ̀, sì wò ó, Jonatani àti ẹni tí ó ru ìhámọ́ra rẹ̀ ni kò sì sí níbẹ̀. Saulu sì wí fún pé, “Gbé àpótí Ọlọ́run wá.” Àpótí Ọlọ́run wà pẹ̀lú àwọn ọmọ ẹli ní ìgbà náà. Nígbà tí sì ń bá àlùfáà sọ̀rọ̀, ariwo ní ibùdó àwọn sì ń pọ̀ síwájú sí. Saulu sì wí fún àlùfáà pé, “Dá ọwọ́ rẹ dúró.” Saulu àti gbogbo àwọn ènìyàn rẹ̀ sì péjọ, wọ́n sì lọ sí ojú ìjà. Wọ́n sì bá gbogbo àwọn ní ìdàrúdàpọ̀ ńlá, idà olúkúlùkù sì wà lára ọmọ ẹnìkejì rẹ̀. Àwọn tí ó ti wà lọ́dọ̀ àwọn tẹ́lẹ̀, tí wọ́n sì ti gòkè tẹ̀lé wọn lọ sí àgọ́ wọn wá sọ́dọ̀ àwọn ọmọ ẹli tí wọ́n ti wà pẹ̀lú àti . Nígbà tí gbogbo àwọn ẹli tí ó ti pa ara wọn mọ́ nínú òkè ńlá gbọ́ pé àwọn sá, wọ́n darapọ̀ mọ́ ìjà náà ní ìlépa gbígbóná. Bẹ́ẹ̀ ni Olúwa sì gba ẹli ní ọjọ́ náà, ìjà náà sì rékọjá sí -. Gbogbo ọkùnrin ẹli sì wà ní ìpọ́njú ńlá ní ọjọ́ náà, nítorí pé ti fi àwọn ènìyàn gégùn ún wí pé, “Ègbé ni fún ẹni tí ó jẹ oúnjẹ títí di alẹ́, títí èmi yóò fi gbẹ̀san mi lára àwọn ọ̀tá mi!” Bẹ́ẹ̀ ni kò sí ẹnìkankan nínú ọ̀wọ́ ogun náà tí ó fi ẹnu kan oúnjẹ. Gbogbo àwọn ènìyàn sì wọ inú igbó, oyin sì wà lórí ilẹ̀ náà. Nígbà tí wọ́n dé inú igbó náà, wọ́n sì rí oyin ń sun jáde, kò sí ẹni tí ó fi ọwọ́ rẹ̀ kan ẹnu rẹ̀ síbẹ̀, nítorí pé wọ́n bẹ̀rù ìfiré. Ṣùgbọ́n kò gbọ́ pé baba rẹ̀ ti fi ìfibú kìlọ̀ fún àwọn ènìyàn náà, bẹ́ẹ̀ ni ó sì tẹ orí ọ̀pá tí ń bẹ ní ọwọ́ rẹ̀ bọ afárá oyin náà, ó sì fi sí ẹnu rẹ̀, ojú rẹ̀ sì dán. Nígbà náà ni ọ̀kan nínú àwọn ọmọ-ogun sọ fún un pé, “Baba rẹ fi ìfibú kìlọ̀ fún àwọn ọmọ-ogun wí pé, ‘Ègbé ni fún ẹni tí ó jẹ oúnjẹ ní òní!’ Ìdí nìyìí tí àárẹ̀ fi mú àwọn ènìyàn.” Jonatani sì wí pé, “Baba mi ti mú ìdààmú bá ìlú, wò ó bí ojú mi ti dán nígbà tí mo fi ẹnu kan oyin yìí. Báwo ni kò bá ti dára tó bí àwọn ènìyàn bá ti jẹ nínú ìkógun àwọn ọ̀tá wọn lónìí, pípa àwọn ìbá ti pọ̀ tó?” Ní ọjọ́ náà, lẹ́yìn ìgbà tí àwọn ọmọ ẹli ti pa nínú àwọn láti dé , ó sì rẹ àwọn ènìyàn náà. Wọ́n sáré sí ìkógun náà, wọ́n sì mú àgùntàn. Màlúù àti ọmọ màlúù, wọ́n pa wọ́n sórí ilẹ̀, wọ́n sì jẹ wọ́n papọ̀ tẹ̀jẹ́tẹ̀jẹ̀. Nígbà náà ni ẹnìkan sì wí fún pé, “Wò ó, àwọn ènìyàn tí ń dẹ́ṣẹ̀ sí Olúwa nípa jíjẹ ẹran tí ó ní ẹ̀jẹ̀ lára.” Ó sì wí pé, “Ẹ̀ṣẹ̀ yín ti pọ̀jù, yí òkúta ńlá sí ibi nísinsin yìí.” Nígbà náà ni ó wí pé, “Ẹ jáde lọ sáàrín àwọn ènìyàn náà kí ẹ sì wí fún wọn pé, ‘Kí olúkúlùkù wọn mú màlúù àti àgùntàn tirẹ̀ tọ̀ mí wá, kí wọ́n sì pa wọ́n níhìn-ín, kí wọ́n sì jẹ́. Ẹ má ṣe ṣẹ̀ sí Olúwa, kí ẹ má ṣe jẹ ẹran tòun-tẹ̀jẹ̀.’ ” Bẹ́ẹ̀ ní olúkúlùkù mú màlúù tirẹ̀ wá ní alẹ́ ọjọ́ náà, wọ́n sì pa wọ́n níbẹ̀. Nígbà náà kọ́ pẹpẹ kan fún Olúwa; èyí sì jẹ́ ìgbà àkọ́kọ́ tí ó kọ́kọ́ ṣe èyí. Saulu sì wí pé, “Ẹ jẹ́ kí a sọ̀kalẹ̀ tọ lọ ní òru, kí a bá wọn jà títí di ìmọ́lẹ̀ òwúrọ̀, kí a má ṣì ṣe dá ẹnìkankan sí nínú wọn.” Wọ́n sì wí pé, “Ṣe ohun tí ó bá dára ní ojú rẹ̀.” Ṣùgbọ́n àlùfáà wí pé, “Ẹ jẹ́ kí a ṣe ìwádìí lọ́wọ́ Ọlọ́run níhìn-ín.” Nígbà náà ni béèrè lọ́dọ̀ Ọlọ́run pé, “Ṣé kí n sọ̀kalẹ̀ tọ àwọn lọ bí? Ǹjẹ́ ìwọ yóò fi wọ́n lé ẹli lọ́wọ́ bí?” Ṣùgbọ́n Ọlọ́run kò dá a lóhùn ní ọjọ́ náà. Saulu sì wí pé, “Ẹ wá síyìn-ín ín, gbogbo ẹ̀yin tí ẹ jẹ́ olórí ogun, kí a ṣe ìwádìí irú ẹ̀ṣẹ̀ tí ẹ ti ṣẹ̀ lónìí. Bí Olúwa tí ó gba ẹli là ti wà, bí ó bá ṣe pé a rí í lára ọmọ mi, ó ní láti kú.” Ṣùgbọ́n ẹnìkankan nínú wọn kò sọ ọ̀rọ̀ kan. Nígbà náà ni wí fún gbogbo àwọn ọmọ ẹli pé, “Ẹ lọ sí apá kan; èmi àti ọmọ mi yóò lọ sí apá kan.” àwọn ènìyàn sì dáhùn pé, “Ṣe èyí tí ó tọ́ ní ojú rẹ.” Nígbà náà ni gbàdúrà sí Olúwa Ọlọ́run ẹli pé, “Fún mi ní ìdáhùn tí ó tọ́.” A sì mú àti nípa ìbò dídì, àwọn ènìyàn náà sì yege. Saulu sì wí pé, “Ẹ dìbò láàrín èmi àti ọmọ mi.” Ìbò náà sì mú . Saulu sì wí fún pé, “Sọ nǹkan tí ìwọ ṣe fún mi.” sì sọ fún un pé, “Mo kàn fi orí ọ̀pá mi tọ́ oyin díẹ̀ wò. Nísinsin yìí ṣé mo ní láti kú?” Saulu sì wí pé, “Kí Ọlọ́run kí ó ṣe bẹ́ẹ̀ àti jù bẹ́ẹ̀ lọ sí mi, nítorí pé ìwọ yóò sá à kú dandan.” Ṣùgbọ́n àwọn ènìyàn wí fún pé, “Ǹjẹ́ ó yẹ kí kú, ẹni tí ó ti mú ìgbàlà ńlá yìí wá fún ẹli? Kí a má rí í! Bí Olúwa ti wà, ọ̀kan nínú irun orí rẹ̀ kì yóò bọ́ sílẹ̀, nítorí tí ó ṣe èyí pẹ̀lú ìrànlọ́wọ́.” Báyìí ni àwọn ènìyàn gba sílẹ̀, kò sì kú. Nígbà náà ni sì dẹ́kun lílépa àwọn , àwọn sì padà sí ìlú wọn. Lẹ́yìn ìgbà tí ti jẹ ọba lórí ẹli, ó sì bá gbogbo ọ̀tá wọn jà yíká: Moabu àti àwọn ọmọ ; Edomu, àti àwọn ọba , àti àwọn . Ibikíbi tí ó bá kọjú sí, ó máa ń fi ìyà jẹ wọ́n. Ó sì jà tagbára tagbára, ó ṣẹ́gun àwọn , ó sì ń gba ẹli sílẹ̀ lọ́wọ́ àwọn tí ó ń kọlù wọ́n. Àwọn ọmọ sì ni , Iṣifi àti ṣua. Orúkọ ọmọbìnrin rẹ̀ àgbà sì ni àti orúkọ ọmọbìnrin rẹ̀ kékeré ni . Orúkọ ìyàwó rẹ̀ ní ọmọbìnrin . Orúkọ olórí ogun rẹ̀ ni ọmọ arákùnrin baba . Kiṣi baba àti baba wọ́n sì jẹ́ ọmọ . Ní gbogbo ọjọ́ , ogun náà sì gbóná sí àwọn , níbikíbi tí bá sì ti rí alágbára tàbí akíkanjú ọkùnrin, a sì mú u láti máa bá a ṣiṣẹ́.
Every verse in 1 Samuel 14
Chapter navigation
Biblica® ní oore ọ̀fẹ́ láti lo Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní™ / Biblica® Open Yoruba Contemporary Bible™ Copyright © 2009, 2017 by Biblica, Inc. “Biblica” is a trademark registered in the United States Patent and Trademark Office by Biblica, Inc. Used with permission. Licensed under CC BY-SA 4.0.