1 Samuel 18:4

“Jonatani sì bọ́ aṣọ ìgúnwà, ó sì fi fun Dafidi pẹ̀lú aṣọ àwọ̀tẹ́lẹ̀ rẹ̀ àti pẹ̀lú idà rẹ̀, ọrun rẹ̀ àti àmùrè rẹ̀.”

1 Samuel 18:4 — Biblica® Open Yoruba Contemporary Bible

Verse 4 of 30 in 1 Samuel chapter 18 — Biblica® Open Yoruba Contemporary Bible. Read it in context below, with maps, timelines and thematic connections beside the text.

1 Samuel 18 — full chapter (Biblica® Open Yoruba Contemporary Bible)

Lẹ́yìn ìgbà tí ti parí ọ̀rọ̀ tí ó ń bá sọ, ọkàn di ọ̀kan pẹ̀lú ti , ó sì fẹ́ràn rẹ̀ gẹ́gẹ́ bí ara rẹ̀. Láti ọjọ́ náà pa mọ́ sí ọ̀dọ̀ rẹ̀ kò sì jẹ́ kí ó padà sí ilé baba rẹ̀ mọ́. Jonatani bá dá májẹ̀mú nítorí tí ó fẹ́ràn rẹ̀ gẹ́gẹ́ bí ara rẹ̀. Jonatani sì bọ́ aṣọ ìgúnwà, ó sì fi fun pẹ̀lú aṣọ àwọ̀tẹ́lẹ̀ rẹ̀ àti pẹ̀lú idà rẹ̀, ọrun rẹ̀ àti àmùrè rẹ̀. Ohunkóhun tí bá rán an láti ṣe, Dafidi máa ṣe ní àṣeyọrí, Saulu náà sì fun un ní ipò tí ó ga jù láàrín àwọn ológun. Eléyìí sì tẹ́ gbogbo ènìyàn lọ́rùn, àti pẹ̀lú ó sì tẹ́ àwọn ìjòyè lọ́rùn pẹ̀lú. Nígbà tí àwọn ènìyàn padà sí ilé lẹ́yìn ìgbà tí ti pa , gbogbo àwọn obìnrin tú jáde láti inú ìlú ẹli wá láti pàdé ọba pẹ̀lú orin àti ijó, pẹ̀lú orin ayọ̀ àti tambori àti ohun èlò orin olókùn. Bí wọ́n ṣe ń jó, bẹ́ẹ̀ ni wọ́n ń kọrin pé, “Saulu pa ẹgbẹ̀rún tirẹ̀ sì pa ẹgbẹẹgbàárún ní tirẹ̀.” Saulu sì bínú gidigidi, ọ̀rọ̀ náà sì korò létí rẹ̀ pé, “Wọ́n ti gbé ògo fún pẹ̀lú ẹgbẹẹgbàárún,” ó sì wí pé, “ṣùgbọ́n èmi pẹ̀lú ẹgbẹ̀rún kan. Kí ni ó kù kí ó gbà bí kò ṣe ìjọba?” Láti ìgbà náà lọ ni ti bẹ̀rẹ̀ sí ní fi ojú ìlara wo . Ní ọjọ́ kejì ẹ̀mí búburú láti ọ̀dọ̀ Ọlọ́run wá pẹ̀lú agbára sórí , ó sì sọ àsọtẹ́lẹ̀ ní ilé rẹ̀ nígbà tí sì ń fọn ohun èlò orin olókùn, gẹ́gẹ́ bí ó ti máa ń ṣe láti ẹ̀yìn wá, Saulu sì ní ọ̀kọ̀ kan ní ọwọ́ rẹ̀. Ó sì gbé e sókè, ó sì wí fún ara rẹ̀ pé, “Èmi yóò gún pọ̀ mọ́ ògiri.” Ṣùgbọ́n, Dafidi yẹ̀ fún un lẹ́ẹ̀méjì. Saulu sì ń bẹ̀rù nítorí pé Olúwa wà pẹ̀lú , ṣùgbọ́n ó ti fi sílẹ̀. Ó sì lé jáde ní ọ̀dọ̀ rẹ̀, ó sì fi jẹ olórí ogun ẹgbẹ̀rún kan (1,000), Dafidi ń kó wọn lọ, ó ń kó wọn bọ̀ nínú ìgbòkègbodò ogun. Dafidi sì ṣe ọlọ́gbọ́n ní gbogbo ìṣe rẹ̀, nítorí tí Olúwa wà pẹ̀lú rẹ̀. Nígbà tí rí bi àṣeyọrí rẹ̀ ti tó, ó sì bẹ̀rù rẹ̀. Ṣùgbọ́n gbogbo ẹli àti ni wọ́n fẹ́ràn , nítorí ó darí wọn lọ ní ìgbòkègbodò ogun wọn. Saulu wí fún pé, “Èyí ni àgbà nínú àwọn ọmọbìnrin mi . Èmi yóò fi òun fún ọ ní aya. Kí ìwọ sìn mí bí akọni, kí o sì máa ja ogun Olúwa.” Nítorí tí wí fún ara rẹ̀ pé, “Èmi kì yóò gbé ọwọ́ mi sókè sí i. Jẹ́ kí àwọn ṣe èyí.” Ṣùgbọ́n wí fún pé, “Ta ni mí, kí sì ni ìdílé mi tàbí ìdílé baba mi ní ẹli, tí èmi yóò di àna ọba?” Nígbà tí àkókò tó fún , ọmọbìnrin , láti fi fún , ni a sì fi fún ará ní aya. Nísinsin yìí ọmọbìnrin sì fẹ́ràn , nígbà tí wọ́n sọ fún nípa rẹ̀, ó sì dùn mọ́ ọn. Ó sọ nínú ara rẹ̀ pé, “Èmi yóò fi fún un kí òun ba à le jẹ́ ìkẹ́kùn fún un, kí ọwọ́ àwọn ará lè wà lára rẹ̀.” Nígbà náà ni wí fún pé, “Nísinsin yìí ìwọ ní àǹfààní eléyìí láti jẹ́ àna án mi.” Saulu pàṣẹ fún àwọn ìránṣẹ́ rẹ̀ pé, “Ẹ sọ fún ní ìkọ̀kọ̀, kí ẹ sì wí pé, ‘Wò ó, inú ọba dùn sí ọ, gbogbo àwọn ìránṣẹ́ rẹ̀ ni ó fẹ́ràn rẹ, nísinsin yìí jẹ́ àna ọba.’ ” Wọ́n tún ọ̀rọ̀ náà sọ fún . Ṣùgbọ́n wí pé, “Ṣé ẹ rò pé ohun kékeré ni láti jẹ́ àna ọba? Mo jẹ́ tálákà ènìyàn àti ímọ̀ kékeré.” Nígbà tí àwọn ìránṣẹ́ sọ fún un ohun tí sọ, Saulu dáhùn pé, “Sọ fún pé, ‘Ọba kò fẹ́ owó orí láti ọ̀dọ̀ àna rẹ̀ ju awọ iwájú orí ọgọ́rùn-ún lọ láti fi gba ẹ̀san lórí àwọn ọ̀tá rẹ̀.’ ” Èrò ni wí pé kí ṣubú sí ọwọ́ àwọn ará . Nígbà tí àwọn ìránṣẹ́ sọ àwọn nǹkan yìí fún , inú rẹ̀ dùn láti di àna ọba kí àkókò tí ó dá tó kọjá, Dafidi àti àwọn arákùnrin rẹ̀ jáde lọ wọ́n sì pa igba lára àwọn . Ó kó awọ iwájú orí wọn wá, ó sì pé iye tí ọba fẹ́ kí ó ba à lè jẹ́ àna ọba. Saulu sì fi ọmọ obìnrin fún un ní aya. Nígbà tí sì wá mọ̀ pé Olúwa wà pẹ̀lú tí ọmọbìnrin rẹ̀ sì fẹ́ràn , Saulu sì tún wá bẹ̀rù síwájú àti síwájú, Saulu sì wá di ọ̀tá fún gbogbo ọjọ́ rẹ̀ tókù. Àwọn ọmọ-aládé tún tẹ̀síwájú láti lọ sí ogun, ó sì ṣe lẹ́yìn ìgbà tí wọ́n lọ, Dafidi ṣe àṣeyọrí ju gbogbo àwọn ìránṣẹ́ lọ, orúkọ rẹ̀ sì gbilẹ̀.

Every verse in 1 Samuel 18

Chapter navigation

Biblica® ní oore ọ̀fẹ́ láti lo Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní™ / Biblica® Open Yoruba Contemporary Bible™ Copyright © 2009, 2017 by Biblica, Inc. “Biblica” is a trademark registered in the United States Patent and Trademark Office by Biblica, Inc. Used with permission. Licensed under CC BY-SA 4.0.

0:000:00