1 Samuel 19:24
“Ó sì bọ́ aṣọ rẹ̀, òun pẹ̀lú sì ń sọtẹ́lẹ̀ níwájú Samuẹli. Ó sì dùbúlẹ̀ bẹ́ẹ̀ ní gbogbo ọjọ́ náà àti ní òru. Ìdí nìyìí tí àwọn ènìyàn fi wí pé, “Ṣé Saulu náà wà lára àwọn wòlíì ni?””
1 Samuel 19:24 — Biblica® Open Yoruba Contemporary Bible
Verse 24 of 24 in 1 Samuel chapter 19 — Biblica® Open Yoruba Contemporary Bible. Read it in context below, with maps, timelines and thematic connections beside the text.
1 Samuel 19 — full chapter (Biblica® Open Yoruba Contemporary Bible)
Saulu sọ fún ọmọ rẹ̀ àti gbogbo àwọn ìránṣẹ́ rẹ̀ pé kí wọ́n pa . Ṣùgbọ́n fẹ́ràn púpọ̀ Jonatani sì kìlọ̀ fún pé, “Baba mi wá ọ̀nà láti pa ọ́, kíyèsi ara rẹ di òwúrọ̀ ọ̀la; lọ sí ibi ìkọ̀kọ̀, kí o sì sá pamọ́ sí ibẹ̀. Èmi yóò jáde lọ láti dúró ní ọ̀dọ̀ baba mi ní orí pápá níbi tí ó wà. Èmi yóò sọ̀rọ̀ fún un nípa à rẹ, èmi yóò sì sọ ohun tí òun bá wí fún ọ.” Jonatani sọ̀rọ̀ rere nípa fún baba rẹ̀, ó sì wí fún un pé, “Má ṣe jẹ́ kí ọba kí ó ṣe ohun tí kò dára fún ìránṣẹ́ rẹ̀; nítorí tí kò ṣẹ̀ ọ́, ohun tí ó sì ṣe pé ọ púpọ̀. Ó fi ẹ̀mí rẹ̀ wéwu nígbà tí ó pa . Olúwa ṣẹ́ ogun ńlá fún gbogbo ẹli, ìwọ rí i inú rẹ dùn. Ǹjẹ́ nítorí kí ni ìwọ yóò ṣe dẹ́ṣẹ̀ sí aláìṣẹ̀, tí ìwọ yóò fi pa á láìnídìí?” Saulu fetísí , ó sì búra báyìí, “Níwọ́n ìgbà tí Olúwa bá ti ń bẹ láààyè, a kì yóò pa .” Nítorí náà pe , ó sì sọ gbogbo àjọsọ wọn fún un. Ó sì mú un wá fún , Dafidi sì wà lọ́dọ̀ gẹ́gẹ́ bí i ti tẹ́lẹ̀. Lẹ́ẹ̀kan an sí i ogun tún wá, Dafidi sì jáde lọ, ó sì bá àwọn ara jà. Ó sì pa wọn pẹ̀lú agbára, wọ́n sì sálọ níwájú u rẹ̀. Ṣùgbọ́n ẹ̀mí búburú láti ọ̀dọ̀ Olúwa wá sí orí bí ó ti jókòó ní ilé e rẹ̀ pẹ̀lú ọ̀kọ̀ rẹ̀ ní ọwọ́ rẹ̀. Bí sì ti fọn ohun èlò orin olókùn, Saulu sì wá ọ̀nà láti gún un mọ́ ògiri pẹ̀lú ọ̀kọ̀ rẹ̀, ṣùgbọ́n yẹ̀ ẹ́ sílẹ̀ gẹ́gẹ́ bí ti ju ọ̀kọ̀ náà mọ́ ara ògiri. Ní alẹ́ ọjọ́ náà sì fi ara pamọ́ dáradára. Saulu rán ènìyàn sí ilé láti ṣọ́ ọ kí wọ́n sì pa á ní òwúrọ̀. Ṣùgbọ́n , ìyàwó kìlọ̀ fún un pé, “Tí o kò bá sá fún ẹ̀mí rẹ ní alẹ́ yìí, ní ọ̀la ni a yóò pa ọ́.” Nígbà náà sì gbé sọ̀kalẹ̀ ó sì fi aṣọ bò ó. Mikali gbé ère ó sì tẹ́ e lórí ibùsùn, ó sì fi irun ewúrẹ́ sí ibi orí rẹ̀. Nígbà ti rán ènìyàn láti lọ fi agbára mú , Mikali wí pé, “Ó rẹ̀ ẹ́.” Nígbà náà ni rán ọkùnrin náà padà láti lọ wo ó sì sọ fún wọn pé, “Mú wa fún mi láti orí ibùsùn rẹ̀ kí èmi kí ó le pa á.” Ṣùgbọ́n nígbà tí ọkùnrin náà wọlé, ère ni ó bá lórí ibùsùn àti irun ewúrẹ́ ní orí ère náà. Saulu wí fún pé, “Èéṣe tí ìwọ fi tàn mí báyìí tí o sì jẹ́ kí ọ̀tá mi sálọ tí ó sì bọ́?” sọ fún un pé, “Ó wí fún mi, ‘Jẹ́ kí èmi ó lọ. Èéṣe tí èmi yóò fi pa ọ́?’ ” Nígbà tí ti sálọ tí ó sì ti bọ́, ó sì lọ sọ́dọ̀ ẹli ní ó sì sọ gbogbo ohun tí ti ṣe fún un. Òun àti ẹli lọ sí láti dúró níbẹ̀. Ọ̀rọ̀ sì tọ wá pé, “Dafidi wà ní ní ,” Saulu sì rán àwọn ènìyàn láti fi agbára mú wá ṣùgbọ́n nígbà tí wọ́n rí ọ̀pọ̀ àwọn wòlíì tí ń sọtẹ́lẹ̀, pẹ̀lú ẹli dúró níbẹ̀ gẹ́gẹ́ bí olórí, Ẹ̀mí Ọlọ́run sì wá sórí àwọn arákùnrin àwọn náà sì ń sọtẹ́lẹ̀. Wọ́n sì sọ fún nípa rẹ̀, ó sì rán ọ̀pọ̀ àwọn ènìyàn mìíràn lọ àwọn náà sì ń sọtẹ́lẹ̀. Saulu tún rán íṣẹ́ lọ ní ìgbà kẹta, àwọn náà bẹ̀rẹ̀ sí ní sọtẹ́lẹ̀. Nígbẹ̀yìn, òun fúnra rẹ̀ sì lọ sí ó sì dé ibi àmù ńlá kan ní . Ó sì béèrè, “Níbo ni ẹli àti wà?” Wọ́n wí pé, “Wọ́n wà ní ìrékọjá ní ní .” Saulu sì lọ sí ni . Ṣùgbọ́n, Ẹ̀mí Ọlọ́run bà lé e lórí ó sì ń lọ lọ́nà, ó sì ń sọtẹ́lẹ̀ títí tí ó fi dé . Ó sì bọ́ aṣọ rẹ̀, òun pẹ̀lú sì ń sọtẹ́lẹ̀ níwájú ẹli. Ó sì dùbúlẹ̀ bẹ́ẹ̀ ní gbogbo ọjọ́ náà àti ní òru. Ìdí nìyìí tí àwọn ènìyàn fi wí pé, “Ṣé náà wà lára àwọn wòlíì ni?”
Every verse in 1 Samuel 19
Chapter navigation
Biblica® ní oore ọ̀fẹ́ láti lo Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní™ / Biblica® Open Yoruba Contemporary Bible™ Copyright © 2009, 2017 by Biblica, Inc. “Biblica” is a trademark registered in the United States Patent and Trademark Office by Biblica, Inc. Used with permission. Licensed under CC BY-SA 4.0.