1 Samuel 23:12

“Dafidi sì wí pé, “Àwọn àgbà ìlú Keila yóò fi èmi àti àwọn ọmọkùnrin mi lé Saulu lọ́wọ́ bí?” Olúwa sì wí pé, “Wọn ó fi ọ́ lé wọn lọ́wọ́.””

1 Samuel 23:12 — Biblica® Open Yoruba Contemporary Bible

Verse 12 of 29 in 1 Samuel chapter 23 — Biblica® Open Yoruba Contemporary Bible. Read it in context below, with maps, timelines and thematic connections beside the text.

1 Samuel 23 — full chapter (Biblica® Open Yoruba Contemporary Bible)

Wọ́n sì wí fún pé, “Sá wò ó, àwọn ará ń bá ará jagun, wọ́n sì ja àwọn ilẹ̀ ìpakà lólè.” Dafidi sì béèrè lọ́dọ̀ Olúwa pé, “Ṣé kí èmi ó lọ kọlu àwọn ará wọ̀nyí bí?” Olúwa sì wí fún pé, “Lọ kí o sì kọlu àwọn ará kí o sì gba sílẹ̀.” Àwọn ọmọkùnrin tí ó wà lọ́dọ̀ sì wí fún un pé, “Wò ó, àwa ń bẹ̀rù níhìn-ín yìí ní ; ǹjẹ́ yóò ti rí nígbà ti àwa bá dé láti fi ojú ko ogun àwọn ara ?” Dafidi sì tún béèrè lọ́dọ̀ Olúwa. Olúwa sì dá a lóhùn, ó sì wí pé, “Dìde, kí o sọ̀kalẹ̀ lọ sí , nítorí pé èmi ó fi àwọn ará náà lé ọ lọ́wọ́.” Dafidi àti àwọn ọmọkùnrin rẹ̀ sì lọ sí , wọ́n sì bá àwọn ará jà, wọ́n sì kó ohun ọ̀sìn wọn, wọ́n sì fi ìparun ńlá pa wọ́n. Dafidi sì gba àwọn ará sílẹ̀. Ó sì ṣe, nígbà tí ọmọ fi sá tọ lọ ní , ó sọ̀kalẹ̀ òun pẹ̀lú efodu kan lọ́wọ́ rẹ̀. A sì sọ fún pé wá sí . Saulu sì wí pé, “Ọlọ́run ti fi í lé mi lọ́wọ́; nítorí tí ó ti sé ara rẹ̀ mọ́ ní ti wíwá tí ó wá sí ìlú tí ó ní ìlẹ̀kùn àti kẹrẹ.” Saulu sì pe gbogbo àwọn ènìyàn náà jọ sí ogun, láti sọ̀kalẹ̀ lọ sí , láti ká mọ́ àti àwọn ọmọkùnrin rẹ̀. Dafidi sì mọ̀ pé ti gbèrò búburú sí òun; ó sì wí fún àlùfáà náà pé, “Mú efodu náà wá níhìn-ín yìí!” Dafidi sì wí pé, “Olúwa Ọlọ́run ẹli, lóòótọ́ ni ìránṣẹ́ rẹ ti gbọ́ pé ń wá ọ̀nà láti wá sí , láti wá fọ́ ìlú náà nítorí mi. Àwọn àgbà ìlú yóò fi mí lé e lọ́wọ́ bí? Saulu yóò ha sọ̀kalẹ̀, gẹ́gẹ́ bí ìránṣẹ́ rẹ ti gbọ́ bí?” Olúwa Ọlọ́run ẹli, èmi bẹ̀ ọ́, wí fún ìránṣẹ́ rẹ. Olúwa sì wí pé, “Yóò sọ̀kalẹ̀ wá.” Dafidi sì wí pé, “Àwọn àgbà ìlú yóò fi èmi àti àwọn ọmọkùnrin mi lé lọ́wọ́ bí?” Olúwa sì wí pé, “Wọn ó fi ọ́ lé wọn lọ́wọ́.” Dafidi àti àwọn ọmọkùnrin rẹ̀ tí wọ́n tó ẹgbẹ̀ta (600) ènìyàn sì dìde, wọ́n lọ kúrò ní , wọ́n sì lọ sí ibikíbi tí wọ́n lè rìn lọ. A sì wí fún pé, “Dafidi ti sá kúrò ní ; kò sì lọ sí mọ́.” Dafidi sì ń gbé ní aginjù, níbi tí ó ti sá pamọ́ sí, ó sì ń gbé níbi òkè ńlá kan ní aginjù . Saulu sì ń wá a lójoojúmọ́, ṣùgbọ́n Ọlọ́run kò fi lé e lọ́wọ́. Nígbà tí wà ní ṣi ní aginjù , Dafidi sì rí i pé, Saulu ti jáde láti wá ẹ̀mí òun kiri. Jonatani ọmọ sì dìde, ó sì tọ lọ nínú igbó ṣi, ó sì gbà á ní ìyànjú nípa ti Ọlọ́run. Òun sì wí fún un pé, “Má ṣe bẹ̀rù, nítorí tí ọwọ́ baba mi kì yóò tẹ̀ ọ́. Ìwọ ni yóò jẹ ọba lórí ẹli, èmi ni yóò sì ṣe ibìkejì rẹ. Saulu baba mi mọ̀ bẹ́ẹ̀ pẹ̀lú.” Àwọn méjèèjì sì ṣe àdéhùn níwájú Olúwa; Dafidi sì jókòó nínú igbó ṣi. Jonatani sì lọ sí ilé rẹ̀. Àwọn ará sì gòkè tọ wá sí , wọ́n sì wí pé, “Ṣé ti fi ara rẹ̀ pamọ́ sọ́dọ̀ wa ní ibi gíga ìsápamọ́sí ní ṣi, ní òkè , tí ó wà níhà gúúsù ti Jeṣimoni. Ǹjẹ́ nísinsin yìí, ọba, sọ̀kalẹ̀ wá gẹ́gẹ́ bi gbogbo ìfẹ́ tí ó wà ní ọkàn rẹ láti sọ̀kalẹ̀: ipa tí àwa ní láti fi lé ọba lọ́wọ́.” Saulu sì wí pé, “Alábùkún fún ni ẹ̀yin nípa Olúwa; nítorí pé ẹ̀yin ti káàánú fún mi. Lọ, èmi bẹ̀ yín, ẹ tún múra, kí ẹ sì mọ̀ ki ẹ si rí ibi tí ẹsẹ̀ rẹ̀ gbé wà, àti ẹni tí ó rí níbẹ̀: nítorí tí a ti sọ fún mi pé, ọgbọ́n ni ó ń lò jọjọ. Ẹ sì wò, kí ẹ sì mọ ibi ìsápamọ́ tí ó máa ń sá pamọ́ sí, kí ẹ sì tún padà tọ̀ mí wá, kí èmi lè mọ̀ dájú; èmi ó sì bá yín lọ: yóò sì ṣe bí ó bá wà ní ilẹ̀ ẹli, èmi ó sì wá a ní àwárí nínú gbogbo ẹgbẹ̀rún !” Wọ́n sì dìde, wọ́n sì ṣáájú lọ sí , ṣùgbọ́n àti àwọn ọmọkùnrin rẹ̀ wà ní aginjù , ní pẹ̀tẹ́lẹ̀ níhà gúúsù ti Jeṣimoni. Saulu àti àwọn ọmọkùnrin rẹ̀ sì lọ ń wá a. Wọ́n sì sọ fún : ó sì sọ̀kalẹ̀ wá sí ibi òkúta kan, ó sì jókòó ní aginjù ti . Saulu sì gbọ́, ó sì lépa ní aginjù . Saulu sì ń rin apá kan òkè kan, Dafidi àti àwọn ọmọkùnrin rẹ̀ ní apá kejì òkè náà. Dafidi sì yára láti sá kúrò níwájú ; nítorí pé àti àwọn ọmọkùnrin rẹ̀ ti rọ̀gbà yí àti àwọn ọmọkùnrin rẹ̀ ká láti mú wọn. Ṣùgbọ́n íṣẹ́ kan sì tọ wá ó sì wí pé, “Ìwọ yára kí o sì wá, nítorí tí àwọn ti gbé ogun ti ilẹ̀ wa.” Saulu sì padà kúrò ní lílépa , ó sì lọ pàdé àwọn nítorí náà ni wọ́n sì ṣe ń pe ibẹ̀ náà ní (èyí tí ó túmọ̀ sí “Òkúta Ìpinyà”). Dafidi sì gòkè láti ibẹ̀ lọ, ó sì jókòó níbi tí ó sá pamọ́ sí ní En-.

Every verse in 1 Samuel 23

Chapter navigation

Biblica® ní oore ọ̀fẹ́ láti lo Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní™ / Biblica® Open Yoruba Contemporary Bible™ Copyright © 2009, 2017 by Biblica, Inc. “Biblica” is a trademark registered in the United States Patent and Trademark Office by Biblica, Inc. Used with permission. Licensed under CC BY-SA 4.0.

0:000:00