1 Samuel 7:3

“Samuẹli sọ fún gbogbo ilé Israẹli pé, “Tí ẹ bá ń padà sí ọ̀dọ̀ Olúwa pẹ̀lú gbogbo ọkàn yín, ẹ yẹra kúrò lọ́dọ̀ ọlọ́run àjèjì àti Aṣtoreti kí ẹ sì fi ara yín jì fún Olúwa kí ẹ sì sin òun nìkan ṣoṣo, òun yóò sì gbà yín kúrò lọ́wọ́ àwọn ará Filistini.””

1 Samuel 7:3 — Biblica® Open Yoruba Contemporary Bible

Verse 3 of 17 in 1 Samuel chapter 7 — Biblica® Open Yoruba Contemporary Bible. Read it in context below, with maps, timelines and thematic connections beside the text.

1 Samuel 7 — full chapter (Biblica® Open Yoruba Contemporary Bible)

Nígbà náà àwọn ará - wá, wọ́n sì gbé àpótí ẹ̀rí Olúwa. Wọ́n gbé e lọ sí ilé lórí òkè, wọ́n sì ya ọmọ rẹ̀ sí mímọ́ láti ṣọ́ àpótí ẹ̀rí Olúwa. Ó sì jẹ́ ní ìgbà pípẹ́, ogún ọdún ni àpótí ẹ̀rí Olúwa fi wà ní -. Gbogbo ilé ẹli ṣọ̀fọ̀ wọ́n sì pohùnréré ẹkún sí Olúwa. Samuẹli sọ fún gbogbo ilé ẹli pé, “Tí ẹ bá ń padà sí ọ̀dọ̀ Olúwa pẹ̀lú gbogbo ọkàn yín, ẹ yẹra kúrò lọ́dọ̀ ọlọ́run àjèjì àti Aṣtoreti kí ẹ sì fi ara yín jì fún Olúwa kí ẹ sì sin òun nìkan ṣoṣo, òun yóò sì gbà yín kúrò lọ́wọ́ àwọn ará .” Nígbà náà ni àwọn ọmọ ẹli yẹra fún àti Aṣtoreti, wọ́n sì sin Olúwa nìkan ṣoṣo. Nígbà náà ni, Samuẹli wí pé, “Ẹ kó gbogbo àwọn ọmọ ẹli jọ sí , èmi yóò bẹ̀bẹ̀ fún un yín lọ́dọ̀ Olúwa.” Nígbà tí wọ́n sì ti péjọpọ̀ ní , wọ́n pọn omi, wọ́n sì dà á sílẹ̀ níwájú Olúwa. Ní ọjọ́ náà, wọ́n gbààwẹ̀, wọ́n sì jẹ́wọ́ pé, “Àwa ti ṣẹ̀ sí Olúwa.” ẹli sì jẹ́ olórí àwọn ọmọ ẹli ní . Nígbà tí àwọn gbọ́ pé àwọn ẹli ti péjọ ní , àwọn aláṣẹ gòkè wá láti kọlù wọ́n. Nígbà tí àwọn ọmọ ẹli gbọ́ èyí, ẹ̀rù bà wọ́n nítorí àwọn . Wọ́n sọ fún ẹli pé, “Má ṣe dákẹ́ kíké pe Olúwa Ọlọ́run wa fún wa, ké pè é kí ó lè gbà wá kúrò lọ́wọ́ àwọn .” Nígbà náà ni ẹli mú ọ̀dọ́-àgùntàn tí ó jẹ́ ọmọ ọmú, ó sì fi rú ẹbọ sísun sí Olúwa. Ó sí ké pe Olúwa nítorí ilé ẹli, Olúwa sì dá a lóhùn. Nígbà tí ẹli ń ṣe ìrúbọ ẹbọ sísun, àwọn súnmọ́ tòsí láti bá ẹli ja ogun. Ṣùgbọ́n ní ọjọ́ náà, Olúwa sán àrá ńlá lu àwọn , ó sì mú jìnnìjìnnì bá wọn, a sì lé wọn níwájú àwọn ọmọ ẹli. Àwọn ọkùnrin ẹli tú jáde láti . Wọ́n sì ń lépa àwọn , wọ́n sì pa wọ́n ní àpá rìn títí dé abẹ́ -. Samuẹli mú òkúta kan ó sì fi lélẹ̀ láàrín àti Ṣeni, ó sì pe orúkọ rẹ̀ ní , wí pé, “Ibí ni Olúwa ràn wá lọ́wọ́ dé.” Bẹ́ẹ̀ ni wọ́n ṣẹ́gun , wọn kò sì wá sí agbègbè àwọn ọmọ ẹli mọ́. Ní gbogbo ìgbésí ayé ẹli, ọwọ́ Olúwa lòdì sí àwọn . Àwọn ìlú láti dé tí àwọn ti gbà lọ́wọ́ ẹli ni ó ti gbà padà fún ẹli, ó sì gba gbogbo ilẹ̀ agbègbè rẹ̀ kúrò lọ́wọ́ ìṣàkóso àwọn . Ìrẹ́pọ̀ sì wà láàrín ẹli àti àwọn . Samuẹli tẹ̀síwájú gẹ́gẹ́ bí adájọ́ lórí ẹli. Ní ọjọ́ ayé e rẹ̀. Láti ọdún dé ọdún, ó lọ yíká láti dé dé , ó sì ń ṣe ìdájọ́ ẹli ní gbogbo ibi wọ̀nyí. Ṣùgbọ́n ó máa ń padà sí ilé rẹ̀ ní , níbí tí ilé rẹ̀ wà, ó sì túnṣe ìdájọ́ ẹli níbẹ̀, ó sì kọ́ pẹpẹ kan síbẹ̀ fún Olúwa.

Every verse in 1 Samuel 7

Chapter navigation

Biblica® ní oore ọ̀fẹ́ láti lo Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní™ / Biblica® Open Yoruba Contemporary Bible™ Copyright © 2009, 2017 by Biblica, Inc. “Biblica” is a trademark registered in the United States Patent and Trademark Office by Biblica, Inc. Used with permission. Licensed under CC BY-SA 4.0.

0:000:00