2 Chronicles 11:13

“Àwọn àlùfáà àti àwọn ará Lefi, láti gbogbo ẹ̀yà wọn jákèjádò Israẹli wà ní ẹ̀bá rẹ̀.”

2 Chronicles 11:13 — Biblica® Open Yoruba Contemporary Bible

Verse 13 of 23 in 2 Chronicles chapter 11 — Biblica® Open Yoruba Contemporary Bible. Read it in context below, with maps, timelines and thematic connections beside the text.

2 Chronicles 11 — full chapter (Biblica® Open Yoruba Contemporary Bible)

Nígbà tí dé ẹmu, ó kó ilé àti jọ, ọ̀kẹ́ mẹ́sàn-án (180,000) ènìyàn tí a yàn, tí wọ́n jẹ́ ológun, láti bá ẹli jà kí ó lè mú ìjọba náà padà bọ̀ sọ́dọ̀ rẹ̀. Ṣùgbọ́n ọ̀rọ̀ Olúwa tọ Ṣemaiah ènìyàn Ọlọ́run wá wí pé, “Wí fún ọmọ ọba , sí gbogbo àwọn ọmọ ẹli ní àti , ‘Èyí ní ohun tí Olúwa wí. Ẹ má ṣe gòkè lọ láti lọ jà pẹ̀lú arákùnrin yín, ẹ lọ sílé, gbogbo yín, nítorí ti ìṣe mi nìyí.’ ” Bẹ́ẹ̀ ni wọ́n tẹ̀lé ọ̀rọ̀ Ọlọ́run, wọ́n sì padà sẹ́yìn láti yan lọ dojúkọ . Rehoboamu ń gbe ní ẹmu ó sì kọ́ àwọn ìlú fún olódi ní . Bẹtilẹhẹmu, Etamu, , Beti-, Soko, Adullamu, Gati, Meraṣa , Adoraimu, Lakiṣi, Aseka Sora, Aijaloni, àti . Wọ̀nyí ni àwọn ìlú ìdáàbòbò ní àti . Ó sì mú àwọn ìlú olódi lágbára, ó sì fi àwọn balógun sínú wọn àti àkójọ oúnjẹ, àti òróró àti ọtí wáìnì. Àti ní olúkúlùkù ìlú ni ó fi asà àti ọ̀kọ̀ sí, ó sì mú wọn lágbára gidigidi, ó sì ní àti lábẹ́ rẹ̀. Àwọn àlùfáà àti àwọn ará , láti gbogbo ẹ̀yà wọn jákèjádò ẹli wà ní ẹ̀bá rẹ̀. Àwọn ará fi ìgbèríko sílẹ̀, wọ́n sì wá sí àti ẹmu nítorí àti àwọn ọmọ rẹ̀, ti kọ̀ wọ́n sílẹ̀ gẹ́gẹ́ bí àwọn àlùfáà Olúwa. Ó sì yan àwọn àlùfáà tirẹ̀ fún àwọn ibi gíga wọ̀n-ọn-nì, àti fún àwọn ère òbúkọ, àti fún ẹgbọrọ màlúù tí ó ṣe. Àwọn tó wá láti gbogbo ẹ̀yà ẹli tí wọ́n fi ọkàn wọn fún wíwá Olúwa, Ọlọ́run ẹli, tẹ̀lé àwọn ará lọ sí ẹmu láti lọ rú ẹbọ sí Olúwa Ọlọ́run baba a wọn. Ó fún ìjọba ní agbára, ó sì ti ọmọ lẹ́yìn fún ọdún mẹ́ta nítorí ọdún mẹ́ta ni wọ́n fi rìn ní ọ̀nà ti àti ní àkókò yí. Rehoboamu fẹ́ tí ó jẹ́ ọmọbìnrin ti ọmọkùnrin bi àti ti , ọmọbìnrin ti ọmọkùnrin bí. Ó bí àwọn ọmọ fún un: Jeuṣi, Ṣemariah àti . Nígbà náà, ó fẹ́ ọmọbìnrin , tí ó bí fún , Sisa àti Ṣelomiti. Rehoboamu fẹ́ràn ọmọbìnrin ju èyíkéyìí nínú àwọn ìyàwó rẹ̀ àti àwọn àlè rẹ̀ lọ. Ní gbogbo rẹ̀, ó ní ìyàwó méjìdínlógún àti ọgọ́ta àlè ọmọkùnrin méjìdínlọ́gbọ̀n àti ọgọ́ta ọmọbìnrin. Rehoboamu yan ọmọ láti jẹ́ olóyè ọmọ-aládé láàrín àwọn arákùnrin rẹ̀, kí ó ba à lè ṣe é ní ọba. Ó hùwà ọlọ́gbọ́n, nípa fí fọ́n díẹ̀ nínú àwọn ọmọ rẹ̀ jákèjádò ká àwọn agbègbè àti àti sí gbogbo àwọn ìlú ńlá olódi. Ó fún wọn ní ọ̀pọ̀ ohun tí wọ́n fẹ́, ó sì fẹ́ ọ̀pọ̀ ìyàwó fún wọn.

Every verse in 2 Chronicles 11

Chapter navigation

Biblica® ní oore ọ̀fẹ́ láti lo Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní™ / Biblica® Open Yoruba Contemporary Bible™ Copyright © 2009, 2017 by Biblica, Inc. “Biblica” is a trademark registered in the United States Patent and Trademark Office by Biblica, Inc. Used with permission. Licensed under CC BY-SA 4.0.

0:000:00