2 Chronicles 16:11

“Àwọn iṣẹ́ ìjọba Asa, láti ìbẹ̀rẹ̀ títí dé òpin, ni akọ sínú ìwé ọba Juda àti Israẹli.”

2 Chronicles 16:11 — Biblica® Open Yoruba Contemporary Bible

Verse 11 of 14 in 2 Chronicles chapter 16 — Biblica® Open Yoruba Contemporary Bible. Read it in context below, with maps, timelines and thematic connections beside the text.

2 Chronicles 16 — full chapter (Biblica® Open Yoruba Contemporary Bible)

Ní ọdún kẹrìndínlógójì ìjọba , Baaṣa ọba ẹli gòkè wá sí ó sì kọlu , láti ma bá a jẹ́ kí ẹnikẹ́ni lè jáde tàbí wọlé tọ ọba lọ. Nígbà náà ni mú wúrà àti fàdákà jáde nínú ilé ìṣúra ilé Olúwa àti ààfin ọba ó sì ránṣẹ́ sí - ọba , ẹni tí ń gbé ní , ó wí pé, “Májẹ̀mú kan wà láàrín èmi àti ìrẹ, bí ó ti wà láàrín baba mi àti baba rẹ. Ẹ wò ó, mo fi wúrà àti fàdákà ránṣẹ́ sí ọ; lọ, ba májẹ̀mú tí o bá ṣa ọba ẹli dá jẹ́, kí ó lè lọ kúrò ní ọ̀dọ̀ mi.” Beni- sì gbọ́ ti ọba, ó sì rán àwọn olórí ogun rẹ̀ lọ sí àwọn ìlú ẹli, wọ́n sì kọlu , Dani, Abeli-, àti gbogbo ìlú ìṣúra . Nígbà tí ṣa gbọ́ èyí, ó sì dá kíkọ́ dúró, ó sì dá iṣẹ́ rẹ̀ dúró. Nígbà náà ní ọba kó gbogbo àwọn ènìyàn jọ, wọ́n sì kó òkúta àti igi lọ èyí ti ṣa ń fi kọ́lé; ó sì fi kọ́ àti . Ní àkókò náà wòlíì wá sí ọ̀dọ̀ ọba , ó sì wí fún un pé, “Nítorí tí ìwọ gbẹ́kẹ̀lé ọba , ìwọ kò sì gbẹ́kẹ̀lé Olúwa Ọlọ́run rẹ, nítorí náà ni ogún ọba ṣe bọ́ kúrò lọ́wọ́ rẹ. Àwa kì í ṣe ará àti àwọn ará àwọn alágbára ogun pẹ̀lú ọ̀pọ̀lọpọ̀ kẹ̀kẹ́ àti àwọn ẹlẹ́ṣin? Síbẹ̀ nígbà tí ìwọ bá gbẹ́kẹ̀lé Olúwa yóò sì fi wọ́n lé ọwọ́ rẹ. Nítorí ojú Olúwa yí gbogbo ayé ká láti fi agbára fún àwọn ẹni tí ó ní ọkàn pípé sí i. Ìwọ ti ṣe ohun aṣiwèrè, láti ìsinsin yìí lọ, ìwọ yóò wà lójú ogun.” sì bínú pẹ̀lú sí wòlíì nítorí èyí, ó sì mú un bínú gidigidi tí ó sì fi mú un sínú túbú. Ní àkókò náà sì ni díẹ̀ nínú àwọn ènìyàn náà lára. Àwọn iṣẹ́ ìjọba , láti ìbẹ̀rẹ̀ títí dé òpin, ni akọ sínú ìwé ọba àti ẹli. Ní ọdún kọkàndínlógójì ìjọba rẹ̀, sì ṣe àìsàn pẹ̀lú ààrùn nínú ẹsẹ̀ rẹ̀. Bi ó tilẹ̀ jẹ pé ààrùn rẹ̀ lágbára, síbẹ̀ kódà nínú àìsàn rẹ̀ kò wá ìrànlọ́wọ́ láti ọ̀dọ̀ Olúwa, ṣùgbọ́n lọ́dọ̀ àwọn íṣègùn nìkan. Nígbà náà tí ó pé ọdún kọ́kànlélógójì rẹ̀, kú, ó sì sùn pẹ̀lú àwọn ìjọba baba rẹ̀, wọ́n sì sin ín sínú isà òkú tí ó ti gbẹ́ jáde fún ara rẹ̀ ní ìlú . Wọ́n sì tẹ sí orí àkéte tí ó fi òórùn dídùn kún, àti írúú tùràrí tí a fi ọgbọ́n pèsè, wọ́n sì da iná ńlá nítorí rẹ̀.

Every verse in 2 Chronicles 16

Chapter navigation

Biblica® ní oore ọ̀fẹ́ láti lo Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní™ / Biblica® Open Yoruba Contemporary Bible™ Copyright © 2009, 2017 by Biblica, Inc. “Biblica” is a trademark registered in the United States Patent and Trademark Office by Biblica, Inc. Used with permission. Licensed under CC BY-SA 4.0.

0:000:00