2 Chronicles 17:2

“Ó sì fi ogun sínú gbogbo ìlú olódi Juda ó sì kó ẹgbẹ́ ológun ní Juda àti nínú ìlú Efraimu tí Asa baba rẹ̀ ti gbà.”

2 Chronicles 17:2 — Biblica® Open Yoruba Contemporary Bible

Verse 2 of 19 in 2 Chronicles chapter 17 — Biblica® Open Yoruba Contemporary Bible. Read it in context below, with maps, timelines and thematic connections beside the text.

2 Chronicles 17 — full chapter (Biblica® Open Yoruba Contemporary Bible)

Jehoṣafati ọmọ rẹ̀ sì jẹ ọba ní ipò rẹ̀ ó sì mú ara rẹ̀ lágbára sí lórí ẹli. Ó sì fi ogun sínú gbogbo ìlú olódi ó sì kó ẹgbẹ́ ológun ní àti nínú ìlú tí baba rẹ̀ ti gbà. Olúwa sì wà pẹ̀lú ṣafati nítorí, ní ọdún àkọ́kọ́ rẹ̀, ó rìn ní ọ̀nà ti baba rẹ̀ ti rìn, kò sì fi ọ̀ràn lọ . Ṣùgbọ́n ó wá Ọlọ́run baba rẹ̀ kiri ó sì tẹ̀lé àṣẹ rẹ̀ ju iṣẹ́ ẹli. Olúwa sì fi ìjọba rẹ̀ múlẹ̀ lábẹ́ àkóso rẹ̀, gbogbo sì mú ẹ̀bùn wá fún ṣafati, bẹ́ẹ̀ ni ó sì ní ọrọ̀ àti ọlá lọ́pọ̀lọ́pọ̀. Ọkàn rẹ̀ sì gbé sókè si ọ̀nà Olúwa, pẹ̀lúpẹ̀lú, ó sì mú ibi gíga wọn àti ère òrìṣà Aṣerah kúrò ní . Ní ọdún kẹta ìjọba rẹ̀, ó rán àwọn ìjòyè rẹ̀ -, , Sekariah, Netaneli, Mikaiah láti máa kọ́ ni nínú ìlú . Wọ́n sì ní díẹ̀ lára àwọn ọmọ , àní Ṣemaiah, Netaniah, Sebadiah, Asaheli, Ṣemiramotu, Jehonatani, , Tobijah àti - àti àwọn àlùfáà ṣama àti . Wọ́n ń kọ́ ni ní agbègbè , wọ́n mú ìwé òfin Olúwa wọ́n sì rìn yíká gbogbo àwọn ìlú wọ́n sì ń kọ́ àwọn ènìyàn. Ìbẹ̀rù Olúwa bà lórí gbogbo ìjọba ilẹ̀ tí ó yí ká, dé bi pé wọn kò bá ṣafati jagun. Lára àwọn ará , mú ẹ̀bùn fàdákà gẹ́gẹ́ bí owó ọba wá fún ṣafati, àwọn ará sì mú ọ̀wọ́ ẹran wá fún un, ẹgbàarindín ní ọ̀ọ́dúnrún (7,700) àgbò àti ẹgbàarindín ní ọ̀ọ́dúnrún (7,700) òbúkọ. Jehoṣafati sì ń di alágbára nínú agbára sí i, ó sì kọ́ ilé olódi àti ilé ìṣúra púpọ̀ ní Ó sì ní ìṣúra ní ìlú . Ó sì tún ní àwọn alágbára jagunjagun akọni ọkùnrin ní ẹmu. Iye wọn gẹ́gẹ́ bí ilé baba wọn nìwọ̀nyí. Láti , àwọn olórí ìpín kan ti ẹgbẹ̀rún (1,000): Adina olórí, pẹ̀lú ọ̀kẹ́ mẹ́ẹ̀ẹ́dógún (300,000) alágbára akọni ọkùnrin. Èkejì, Jehohanani olórí, pẹ̀lú ọ̀kẹ́ mẹ́rìnlá (280,000) ọkùnrin; àtẹ̀lé ọmọ , ẹni tí ó fi ara rẹ̀ fún iṣẹ́ Olúwa pẹ̀lú ọ̀kẹ́ mẹ́wàá (200,000). Láti ọ̀dọ̀ : Eliada, alágbára akọni ọkùnrin pẹ̀lú ọ̀kẹ́ mẹ́wàá (200,000) àwọn jagunjagun ọkùnrin pẹ̀lú ọrun àti àpáta ìhámọ́ra; àtẹ̀lé , pẹ̀lú ọ̀kẹ́ mẹ́sàn-án (180,000) jagunjagun ọkùnrin múra sílẹ̀ fún ogun. Wọ̀nyí ni àwọn ọkùnrin tí ń dúró níwájú ọba, ní àyíká àwọn ẹni tí ó fi sínú ìlú olódi ní àyíká gbogbo .

Every verse in 2 Chronicles 17

Chapter navigation

Biblica® ní oore ọ̀fẹ́ láti lo Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní™ / Biblica® Open Yoruba Contemporary Bible™ Copyright © 2009, 2017 by Biblica, Inc. “Biblica” is a trademark registered in the United States Patent and Trademark Office by Biblica, Inc. Used with permission. Licensed under CC BY-SA 4.0.

0:000:00