2 Chronicles 22:1

“Àwọn ènìyàn Jerusalẹmu mú Ahasiah, ọmọ Jehoramu tí ó kéré jùlọ, jẹ ọba ní ipò rẹ̀, láti ìgbà tí àwọn onísùnmọ̀mí, tí ó wá pẹ̀lú àwọn ará Arabia sínú ibùdó, tí wọn sì ti pa àwọn ọmọkùnrin àgbà. Bẹ́ẹ̀ ni Ahasiah ọmọ Jehoramu ọba Juda bẹ̀rẹ̀ sí ní jẹ ọba.”

2 Chronicles 22:1 — Biblica® Open Yoruba Contemporary Bible

Verse 1 of 12 in 2 Chronicles chapter 22 — Biblica® Open Yoruba Contemporary Bible. Read it in context below, with maps, timelines and thematic connections beside the text.

2 Chronicles 22 — full chapter (Biblica® Open Yoruba Contemporary Bible)

Àwọn ènìyàn ẹmu mú , ọmọ tí ó kéré jùlọ, jẹ ọba ní ipò rẹ̀, láti ìgbà tí àwọn ísùnmọ̀mí, tí ó wá pẹ̀lú àwọn ará sínú ibùdó, tí wọn sì ti pa àwọn ọmọkùnrin àgbà. Bẹ́ẹ̀ ni ọmọ ọba bẹ̀rẹ̀ sí ní jẹ ọba. Ahasiah jẹ́ ẹni ọdún méjìlélógún nígbà tí ó di ọba. Ó sì jẹ ọba ní ẹmu fún ọdún kan. Orúkọ ìyá rẹ̀ a máa jẹ́ , ọmọ ọmọbìnrin . Ó mú ìrìn ní ọ̀nà ilé . Nítorí tí ìyá rẹ̀ kì í láyà nínú ṣíṣe búburú. Ó ṣe búburú ní ojú Olúwa, gẹ́gẹ́ bí ilé ti ṣe, nítorí lẹ́yìn ikú baba a rẹ̀, wọ́n di olùgbani nímọ̀ràn rẹ̀ sí ṣíṣe rẹ̀. Ó tẹ̀lé ìgbìmọ̀ wọn nígbà tí ó lọ pẹ̀lú ọmọ ọba ẹli láti gbógun ti ọba ní . Àwọn ará ṣá ní ọgbẹ́; bẹ́ẹ̀ ni ó padà sí láti wo ọgbẹ́ rẹ̀ sàn tí wọ́n ti dá sí i lára ní ní ojú ogun rẹ̀ pẹ̀lú ọba . Nígbà náà, Ahasiah, ọmọ ọba lọ sí láti lọ rí ọmọ nítorí a ti ṣá a lọ́gbẹ́. Ní gbogbo ìgbà ìbẹ̀wò sí , Ọlọ́run mú ìṣubú wá. Nígbà tí dé, ó jáde lọ pẹ̀lú láti lọ bá ọmọ ṣi, ẹni tí Olúwa ti fi àmì òróró yàn láti pa ìdílé run. Nígbà tí ń ṣe ìdájọ́ lórí ilé , ó rí àwọn ọmọbìnrin ọba ti àti àwọn ọmọkùnrin ìbátan , tí ó ń tọ́jú , ó sì pa wọ́n. Ó lọ láti wá , àti àwọn ọkùnrin rẹ̀. Àwọn arákùnrin rẹ̀ ṣẹ́gun rẹ̀ nígbà tí ó sá pamọ́ ní . A gbé e wá sí ọ̀dọ̀ , a sì pa á. Wọ́n sin ín nítorí wọ́n wí pé, “Ọmọkùnrin ṣafati ni, ẹni tí ó wá Olúwa pẹ̀lú gbogbo ọkàn rẹ̀.” Bẹ́ẹ̀ ni kò sí ẹnìkan ní ilé tí ó lágbára láti gbé ìjọba náà dúró. Nígbà tí ìyá rí i wí pé ọmọkùnrin rẹ̀ ti kú, ó tẹ̀síwájú láti pa gbogbo ìdílé ọba ti ilẹ̀ run. Ṣùgbọ́n ṣeba ọmọbìnrin ọba mú ṣi, ọmọkùnrin ó sì jí gbé lọ kúrò láàrín àwọn ọmọbìnrin ọba, àwọn tí ó kù díẹ̀ kí wọn pa. Wọn gbé òun àti olùtọ́jú rẹ̀ sínú ìyẹ̀wù. Nítorí ṣeba ọmọbìnrin ọba àti ìyàwó àlùfáà jẹ́ arábìnrin . Ó fi ọmọ náà pamọ́ kúrò fún , kí ó má ba à pa á. Ó wà ní ìpamọ́ pẹ̀lú wọn ni ilé Ọlọ́run fún ọdún mẹ́fà nígbà tí ṣàkóso ilẹ̀ náà.

Every verse in 2 Chronicles 22

Chapter navigation

Biblica® ní oore ọ̀fẹ́ láti lo Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní™ / Biblica® Open Yoruba Contemporary Bible™ Copyright © 2009, 2017 by Biblica, Inc. “Biblica” is a trademark registered in the United States Patent and Trademark Office by Biblica, Inc. Used with permission. Licensed under CC BY-SA 4.0.

0:000:00